Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,148,968 members, 7,803,213 topics. Date: Saturday, 20 April 2024 at 11:29 AM

Asiri Ijinle Awon Woli Lailai - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai (39107 Views)

Ogun Eyonu Awon Agba Todaju / Asiri Agbara Lati Mu Ona Ola Si Kia Kia / Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(m): 12:07pm On Dec 03, 2016
Hallelujah +Hallelujah ++Hallelujah +++
Alafia fun yin ooo,oruko emi omo yin aburo yin ni SNR AP PROPHET S.A.NASE. Pataki oun ti o mu mi da ikanni yisile nipe,opo WOLI ode oni ti so agbara Olorun nu,ati papa julo,ASIRI awon woli igba lailai ti parun lo die die,ewe ati egbo nikan loku ti opo woli gbekanle loni,Emi Olorun wa mi simi lati gbe abala yi kale,kale ma fun arawa ni ASIRI imo ijinle nipa agbara mimo ati ASIRI ijinle awon woli igba lailai,enikeni ti o batije woli ododo lokunrin lobinrin,ni oledarapo mo ikanni yi,iwonba asiri la o ma fisibi,lori wathsapp ni ekunrere ASIRI wa number wathsapp na re,08075198871/08135072961. Awon woli nikan ni ikanni yi wulo fun o.Iwo ti o ba se ojise Olorun ti o si wa iranlowo woli okan le bami soro ni privet. Ao fe asa kasa ebu,tabi ija,tabi Fifi enu abuku kan eka ijo kankan tabi ojise Olorun kankan,Lori ikanni yi,beru Olorun Emi Awon woli ooo.Hallelujah
Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(m): 12:56pm On Dec 03, 2016
ETO ADURA LASIKO-INIRA TABI IDANWO AYE
JEHOVAH-SHARAKAH: Fi oruko mimo Olorun yi gbadura bi idanwo tabi inira aye bawa fun enia,pe oruko ni pelu idojubole ni igba meje,Ki o si se adura na fun ojo 7 tabi ojo 3,Akoko adura na ni agogo mejila oru,ati agogo marun aro saju kato ba enia soro,kia ni Iwo yio si bori idanwo ati isoro na logan.+++
smileyETO ADURA LASIKO-INIRA TABI IDANWO AYE
JEHOVAH-SHARAKAH: Fi oruko mimo Olorun yi gbadura bi idanwo tabi inira aye bawa fun enia,pe oruko ni pelu idojubole ni igba meje,Ki o si se adura na fun ojo 7 tabi ojo 3,Akoko adura na ni agogo mejila oru,ati agogo marun aro saju kato ba enia soro,kia ni Iwo yio si bori idanwo ati isoro na logan.+++

3 Likes

Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by banjicom(m): 1:10pm On Dec 03, 2016
ki oluwa o bukun fun yin, fun eto ikanni ti e dasi le yi sir. Eleyi yo wulo fun gbogbo woli ati omo olorun lapapo. Ki oluwa tu bo ma fun yin ni okun ati agbara lati ma gbe ogo ise re yo Amin.

1 Like

Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by scholes0(m): 1:45pm On Dec 03, 2016
Iru asiri wo ni o le wa ninu ise ojise Olorun ti ko si ninu bibeli?
Olorun so fun wa ninu iwe mimo-o re wipe ki a ke pe oluwa, oun yio si da wa l'ohun.
Abi be-e ko?

1 Like

Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(m): 2:22pm On Dec 03, 2016
eniti o bere pe ASIRI wo lobe ninu ise iranse ti o si ninu bibeli ,idahun mi re o ,ASIRI imo ijinle Olorun po lowo awon woli isaju ti won si pawon mo ti won o kowon sinu bibeli,tori komadi oun imulo fun taja teran ni,bibeli gan wipe ASIRI OLUWA wa pelu awon to beru re yio si fiwon mo majemure,Orin Dafidi 25:14, nibo ni JEHOVAH EL ADONAI, wa ninu Bibeli kideni won fi se bawo lawon woli se lo ti Olorun fi yara gbo tiwon,juti awon ti o Ku lo,Iwo na bere akara biti Elijah Ki eye Iwo gbe wa fun Iwo na,besini ASIRI yi siwa lowo awon woli mimo ti won fi irele sun mo Olorun biti Elijah, sugbon ejoreto sebi opo babalawo ti pe ara re ni woli loni ni o je kamo awon woli ododo mo,se o gbagbe pe bibeli wipe bi ogbon ba Ku fun enikeni Ki o bere lowo Olorun ni,ASIRI Olorun po,ti enikeni o mo o,sugbon ti Olorun si fi han awon woli re,tori agbara igbohun Irina imoaya,ala,ati bebelo siwa sibe ti Olorun fi fi asiri ohun ijinle han awon woli re o.Jesus is Lord. Hallelujah
Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by kenismusic: 3:31pm On Dec 20, 2016
Scholes....Ko eko...asiri nbe.... gba bi mo ti se so fun e
Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by omoolope2019(m): 1:29pm On Jul 30, 2017
ayokomi1010:
eniti o bere pe ASIRI wo lobe ninu ise iranse ti o si ninu bibeli ,idahun mi re o ,ASIRI imo ijinle Olorun po lowo awon woli isaju ti won si pawon mo ti won o kowon sinu bibeli,tori komadi oun imulo fun taja teran ni,bibeli gan wipe ASIRI OLUWA wa pelu awon to beru re yio si fiwon mo majemure,Orin Dafidi 25:14, nibo ni JEHOVAH EL ADONAI, wa ninu Bibeli kideni won fi se bawo lawon woli se lo ti Olorun fi yara gbo tiwon,juti awon ti o Ku lo,Iwo na bere akara biti Elijah Ki eye Iwo gbe wa fun Iwo na,besini ASIRI yi siwa lowo awon woli mimo ti won fi irele sun mo Olorun biti Elijah, sugbon ejoreto sebi opo babalawo ti pe ara re ni woli loni ni o je kamo awon woli ododo mo,se o gbagbe pe bibeli wipe bi ogbon ba Ku fun enikeni Ki o bere lowo Olorun ni,ASIRI Olorun po,ti enikeni o mo o,sugbon ti Olorun si fi han awon woli re,tori agbara igbohun Irina imoaya,ala,ati bebelo siwa sibe ti Olorun fi fi asiri ohun ijinle han awon woli re o.Jesus is Lord. Hallelujah
i like your explanation
Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by Hert777: 1:25am On Sep 02, 2017
Ororo ibukun. Ao wa patchment paper. Ao wa ya agbelebu 3 si oke paper yi lehin EYI ao wa ko samu 72 si iwe yi lati ibere de Opin. Lehin pepa yi ao wa ko oruko mimo yi. AKEMOKEHUJA. ZERO. ZEROYE. X3. Ao wa sun pepa yen ao lo ejijo re dasi inu.ororo olive. Ao ya si mimo PELU samu 21 PELU IMOLE funfun kan. Fifi para lowo wa ri iyanu Olorun.

2 Likes

Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by 08101646045atwp(m): 12:46pm On Sep 25, 2018
OGUN IFURA eja ojiji ao fi ikonde ha lenu pelu odindi atare kan ao Jo po ao sin gbenre yika orun ese mejeji

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon nkan lara egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS . Fun ti majemu, abi eyi ti atun npe Ni:- ALUMONNI AWON AKONI:- https:///8ahrCpBnxgS3qHb0L63Hp8
Fun ti ALUMONNI AWON AKONI.
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(m): 10:18am On Mar 24, 2023
E karo gbogbo Ile, alafia oluwa olorun awon Omo Ogun yio wa pelu wa
Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(m): 10:21am On Mar 24, 2023
EMI prophet Ayokomi, ti moje oludasile ikanni Yi ti de pada bayi, oluwa yio ranwa lowo, fun awa ti a Fe eto adura, tabi awon asoyepi kan Lori aiyere, boya o si Fe se eto adura kan loni imonipa boselese, ao ba e se Koda ao tun Fi ranse yala boya Nigeria tabi oke okun, number mi niyin oun na ni Whatsapp, 08135072961

(1) (Reply)

Ooni Of Ife, His Wife And High Chiefs Worship At A Church In Canada. Photos / Nigerian Doll Created By Taofik Okoya Now Outselling White Dolls Barbie / Hausa Hero And Warrior Queen Amina Of Zaria Full History,life And Legendary Work

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 23
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.