Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,435 members, 7,808,556 topics. Date: Thursday, 25 April 2024 at 01:24 PM

Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. - Politics - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. (1234 Views)

Awọn Oludije Metadinlogun Ma Dije Ni Idibo Gomina Ni Ondo - INEC / Ile-ẹjọ Da Obaseki Duro Lati Dije Ipo Idibo Akọkọ Ti PDP / Awọn Dokita Olugbe Ni Naijiria Bẹrẹ Idasesile Ailopin (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (Reply) (Go Down)

Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(m): 1:04am On Jun 21, 2020
Iwulo ede abinibi ninu eto oselu.

1 Like 1 Share

Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(m): 1:05am On Jun 21, 2020
Bawo ni a se le fi ede abinibi tun ilu se?
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:05am On Jun 21, 2020
Ani lati tun korikuloomu wa ko

1 Like 1 Share

Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:05am On Jun 21, 2020
Oye ki awon asoju wa moju to oro yi
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(m): 1:07am On Jun 21, 2020
Fun apeere, ipa ti gbolohun "O to ge" ko ninu idibo abenu ti ipinle Kwara odun 2019

2 Likes

Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by AbakalikiPress: 1:08am On Jun 21, 2020
....
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Mastakija(m): 1:09am On Jun 21, 2020
ewo tun leleyi ni tori oloun

1 Like

Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:11am On Jun 21, 2020
Ose koko
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:12am On Jun 21, 2020
Oye ki a jeki awon omo ton bo mo nipa ede ati asa
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by YourNemesis: 1:12am On Jun 21, 2020
Ipade awon aderinposunu ree o grin
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(m): 1:13am On Jun 21, 2020
YourNemesis:
Ipade awon aderinposunu ree o grin

grin
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by AbakalikiPress: 1:14am On Jun 21, 2020
Ndi uchu niile!

2 Likes

Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:14am On Jun 21, 2020
E ku apero o
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Trutharenas: 1:15am On Jun 21, 2020
Oga o
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by ajailer(m): 1:17am On Jun 21, 2020
opon dandan ki awon omo wa mo npa ede wa... eje ki ama ba awon omo wa so ede wa nile, ko ki nse ede geesi nikan

1 Like

Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by scholes0(m): 1:17am On Jun 21, 2020
Fatalityyyy:
Ki lo fa sababi

Sababi koor, abebi nii. grin

2 Likes

Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:17am On Jun 21, 2020
Ose pataki
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Factshunter: 1:18am On Jun 21, 2020
Killo'nsele
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Factshunter: 1:18am On Jun 21, 2020
grin
Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:18am On Jun 21, 2020
Mo n gbadun ikanni yi bi eni n gbadun tea gbigbona

1 Like

Re: Eto Idibo Ni Guusu Iwo Oorun Naijiria. by Salewa97: 1:18am On Jun 21, 2020
Eyin omo iya mi

1 Like

(1) (2) (3) (Reply)

Governor Makinde Never Called Since Ajimobi illness till death- Ajimobi wife / Where Does Tinubu Get His Money? / Pdp Chieftain Arrested For The Gruesome Murder Of Mr Aborode In Igangan- Photo

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.