Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,158,883 members, 7,838,172 topics. Date: Thursday, 23 May 2024 at 04:40 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1831580 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (64) (65) (66) (67) (68) (69) (70) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by cancioamor: 9:17am On Mar 19, 2016 |
Bawo ni lilo ises yi? esheun dominicson: 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:27am On Mar 19, 2016 |
dominicson: OKARE OMO-ONIBABALAWO. BEE NI...BI IFA NA TI RI NU. AO GE IGBIN YEN NI MARUN-MERIN NI, TI GBOGBO E A JE MESAN SUGBON KIISE OBE(KNIFE) NI A FI MA N GE OO. FANRAN OPARUN(re re re) NI AO FI GE. OTUTU(re mi do)-OPON(re do) yen ni ileke ti awon babalawo ma n fi so ide(re do) ti won ma n so mo owo(hand). Kiise ileke-fun-fun oo, GREEN & REDISH brown ni. Ileke yen na ma je mesan! Sefunsefun yen ni a pe ni Sese-efun(mi mi re re). Ela-boru,Ela-boye,Ela-bosise. 4 Likes |
Re: .. by dominicson: 11:17am On Mar 19, 2016 |
@ Cancioamor, Obe/Aseje ni ise naa. @Lero70, Gbigbe ni asin ati Oga naa, sugbon asin ti won la ni aya(chest) ni o. Orangun meji naa ni an pe ni ofu meji, odu yii ni alakoso awon iya mi eleye before osa meji took its position, that's a story for another day. Two-one-two-one at both sides . . . . . . . . . . . . And for pronunciation of those words, you can call or whatsapp me, so I can record and send. @Wale259, Gbigbe ni asin ati oga naa o. Ati wipe ale patapata ni a lo imule yii. 3 Likes |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:27am On Mar 19, 2016 |
Ifa ni; A kii s'omo babalawo ka binu A kii s'omo onisegun ka saigboran A kii s'omo baale ka ba ilu je Dia fun Adekambi ti s'omo okaransode Mo gbo wipe won so ide mo ba won so. Emi o ma ma mo oun won n fi se Mo gbo pe won n s'ode mo ba won so. Aboru, Aboye! 4 Likes |
Re: .. by dominicson: 11:32am On Mar 19, 2016 |
I intended posting ten confirmed Imule, but now I'm afraid the next eight could make the female ones among us 'fly'. So helpless I am to help those I know they really need these imule here! |
Re: .. by akingbemi(m): 11:35am On Mar 19, 2016 |
KEHINDE633:Se Ao Da Ose Dudu Yen Si Inu Ikoko Ti Ati Fe Jo Ogun Yen Ni 1 Like |
Re: .. by Nobody: 11:43am On Mar 19, 2016 |
dominicson: Ok. Kindly oblige me the rest via whatsApp +2348034039830. Will be very grateful if you can do that asap. God bless you. |
Re: .. by Lero70: 12:05pm On Mar 19, 2016 |
dominicson:pls Sir, post d remaining 8 wt d strong warning for females folk. Pls pple like myself r in crucial need of it. Or u can help me by sending it to my e-mail ( tailadoriginal@gmail.com) Thanks. Agbaoniitanlorile o ojo yin adale eepefunwa o. For that pronunciation issue, am so sorry to inform you that my phone can not accept whatsapp application. |
Re: .. by cancioamor: 12:54pm On Mar 19, 2016 |
Beni emi o ri nkan tiko da rara ninu tita iwe ogun, ofe ko ni won print e sita fun anfani awa omo yoruba amo ere ajeju nio da rara, Ki awon agba mejiji yi dakun kiwon jebure bi awon agba tin wi, epari ija ti owa larin ara yin, alagba ifankaleluya mo mo wipe agba awo ni yin. kin ma paro fun yin ona po pupo ti ele fi ran ikanni yii lowo. ema se binu. siso oro, gbigbo oro, titumo oro.. oun to lagbara ni. emase binu rara. baba healthfirst mo fi olohun oba be eyin na emase binu mo. We need you both. i have been following this thread long ago. alufa, pastor ati onisegun po pupo ti won follow thread yii. ibi ti n ba ti siso efi ori ese mi jin mi. Titiloye247: |
Re: .. by cancioamor: 1:01pm On Mar 19, 2016 |
thank you. please dont forget me as well . cancioamor@gmail.com. ese pupo dominicson: |
Re: .. by Ifankaleluya: 2:02pm On Mar 19, 2016 |
MO FE RO(urge) WA. E JE KA MU ORO(do do) KURO LORI ORO YEN. SE EMO WIPE ORO-SISO OBEY HOOKE'S LAW, BI A BA TI N SO,BEE NI YIO MA GUN(do) SI, UNTIL IT EXCEEDS THE ELASTIC LIMIT. SUGBON TA LO MO IGBA TI YIO EXCEED ELASTIC LIMIT? NO-ONE. SO,LETS STOP POSTING ABOUT IT. KOSI ENIKENI TO N BA ARA WON JA LORI FANRAN YI. LETS CONCENTRATE ON THE SALIENT OF THE THREAD. THANK YOU ALL FOR THE SPOKEN & UNSPOKEN WORDS. I WISH YOU ALL, ALL THE BEST. |
Re: .. by Ifankaleluya: 2:19pm On Mar 19, 2016 |
OSO KEKE KAN TO GBONA NIYI Ewe-laali Eyin adire ororo(do do do) merin Oga aaye kan Owo-titun (#500 or 1000) Igba-olomori Ose Oyin Lofinda bintu meji. Ao gun ewe-lali yen daadaa, ao gun awon eyin yen mo, ao gun ose yen papo mo, ao fi oyin po ose yen, leyin na ao tun po pelu lofinda bintu kan, ao fi owo(money) yen tele(mi do) igba, ao fi Oga yen le owo yen lori ki o gba awo(do do) owo yen, ao gbe ose yen le lori, ao wa lu ose yen laarin ti yio fi kan Oga yen lara, ao wa tun bintu kan to ku yen si. ao de igba yen pa fun ojo-merindinlogun(16days) ki a to ma we ose na. Pelu Ogo-Olohun yio si ri be. NOTE; Akii fi omi si oso yen ti a ba n se lowo oo. Aboru, Aboye! 3 Likes
|
Re: .. by whykay77: 2:36pm On Mar 19, 2016 |
@ifankaleluyah I want to urge you not to post anything that will affect the future of people on here for the sake of those who do not know the consequencies. Not everyone knows what he or she will do to avert the horror when it beckons. Thank you in anticipations. Just a saying. Omo ti ologun arinya kogbudo je aayan. Toto se bi owe awon agba. |
Re: .. by Ifankaleluya: 2:40pm On Mar 19, 2016 |
FUN AWON TI WON N TUN BERE ISOYE IFA-ISOYE ONI OBARA-MEJI NIYI Ewe oniyemiye Ojuso-eko mesan Eiye awoko kan Kuluso mesan Ori-ikun(re mi) Sonso ori ogan Odidi ataare kan ti omo re kan kan ko so'nu Ao jo gbogbo re papo ni, ti a ba lo tan, ao te ni obara-meji. Ao wa pe ifa re bayi; Ikun(re mi) ni fi agbari se ile kelebe(do do do) ni fi ono-ofun sodo Okiti banba won so seu-seu(do do) ope(do re) jo rigidi(do do do) Wa fi inu mi se ibugbe oo Obara-nikosi ifa ma ko mi niye temi lo, Obara-nikosi ao fi sin gbere si aya(do do) 9 fun okunri, 7 fun obinrin. ao da iyoku sinu oyin, ao ma la laro-laro Odu yen niyi nisale yen Aboru, Aboye. 2 Likes
|
Re: .. by Ifankaleluya: 2:46pm On Mar 19, 2016 |
whykay77: Thank you, don't be scared! just bear it in mind that whatever i post here is useful for you peoples & has no side-effect. |
Re: .. by Nobody: 3:21pm On Mar 19, 2016 |
Ifankaleluya: E jowo, bawo ni oso yii se maa nsise ati wi pe ojo wo ninu ose leeyan le lo ise yii? E seun pupo. |
Re: .. by Nobody: 4:31pm On Mar 19, 2016 |
Ifankaleluya.... is dis u ?
|
Re: .. by dominicson: 4:34pm On Mar 19, 2016 |
I think one more can still come out into the light, with a serious warning though. This Imule, 'Oloherenhere', is very good. Even if one needs a good job. A job of your choice. Or wherever your need is, you will get your choice. But if you wish not to work or do anything, and wish to be living big, try 'Al'apa ma sise, Am'ona owo ma re...' That's another Ifa/Imule entirely. Back to Oloherenhere, this Ifa/Imule is in two parts. You can do it the same day, but if you can't make it doing the two the same day, it is recommended you do its Ese(do do) before its Etu(do do). Imule: Oloherenhere (Osa meji, Osa Eleye!) Ese: the first part. A o wa akuko adie ti o se se la ogbe (ti ogbe ori re se se yo). A o pa, a o ge si merindinlogun. A o fi epo pupa din(fry). A o ko sinu taasa tuntun. Ikilo/warning: everything that you use to prepare this delicacy: knife, spoon, pot/pan, and all, should be disposed of into a river, and never be used again. If not, the very many guests that are invited will also share whoever use those cutlery. Having served it, a o fi ebu re te Odu/Ifa awon mummy mi beside that awo ipese ti a wa eran naa si, a o kun'le, a o so wipe: (Psalm) Iba, iba, iba. Ela ro wa, Ifa ti o ba n be l'okun Ela ro wa, Orunmila bi o ba n be l'osa Ela ro wa, Osa Eleye, Ela ro wa. Nko pe yin fun iku o, bee nko pe yin fun arun (wa fi action gidi si ni o; you have to brace yourself, because you may experience the presence of your guests, even if you may not see them. This is because they would have smelled it while it was still on the fire frying.) Nko pe yin fun faari o! Mo pe yin ki aye omo Olufe(Olu Ife) le tuba tuse ni o. Oloherenhere, Oloherenhere, Oloherenhere, se bi eye ori agbon(coconut) ni e n se. Ibe(there) le gbe n pe (congregate), ibe le gbe n je(do), ibe le gbe je(re), ibe le gbe mu, ibe le gbe ro(do). E wa lo ro nitori oro emi lagbaja omo lagbaja. E lo ro nitori a ti l'owo(getting rich) mi, e lo ro nitori a ti bi'mo mi, nitori a ti l'aya, a ti d'olokiki mi. Gbogbo eyin Eleye ni mo be(plead), eyin Aje aye o! Eyin Aje orun o! Eyin a je eegun(bone)! Eyin a je eran! Eyin a je edo! Eyin a je oronro ogalanta! Eyin a mu eje(blood) eeyan(person) ma bi! Eyin Aje(witches) sanmo mejeeje. Eyin Aje ile mejeeje. Eyin aje dudu. Eyin Aje funfun. Eyin aje pupa. Eyin Aje kalakinni (do mi do mi). Eyin Aje batabata(do mi do mi). Emi Lagbaja omo Lagbaja, mo di opo yin mu l'ori a ti l'owo, l'aya... Osa Eleye Oo! Ti o ba je wipe eyin(back) re l'o fi pon awon Aje wa si'le aye, ki o sa ere tete ki o lo gba ire ola(re do) t'emi wa fun mi o. (To be continued, pls) 4 Likes |
Re: .. by Nobody: 4:36pm On Mar 19, 2016 |
The indians are best known for the production of rings, such as Magic ring, success ring, protection ring, goodluck ring and so on, my question is shey our own power neva reach the level of producing such rings ? just like the indians |
Re: .. by dominicson: 5:18pm On Mar 19, 2016 |
skypeme: Bros, we, the Yorubas, have things that are more potent/powerful than the indians. Indians ba wo! Ibi ti olukuluku ba se awo de ni! Me o, I've seen things, only I may never be able to reveal ninety percent of them! Imule la fi se! |
Re: .. by Zenlife: 6:30pm On Mar 19, 2016 |
Titiloye247: Same here sir. I appreciate. Ossezx@gmail.com |
Re: .. by skamo74: 6:50pm On Mar 19, 2016 |
Haba! Sir sorry for saying this I think it's now clear you are not on this forum for the good of it. what are you really teaching people here? Are you using style to sell yourself as the biggest Babalawo? it seems you have a lot of power you want to use or test. awon agba bo won ni " Igberaga ni siwaju iparun" ati pe " Agba to ba lomi ninu kin pariwo". Sir can't you start your own forum on IFA or what ever. Everybody has been pleading with you but you still want to pick fight with Baba heartfirst. sir, since you came on this forum you've managed to create a lot of confusions for us who are learning. the simple truth is that Baba healthfirst and Baba kadunasourh and others has help us alot. we tested what they teaches us and we conformed it to be true. sir, if you have some just teach and stop urging for war. sorry my view Ifankaleluya: 1 Like |
Re: .. by cancioamor: 6:50pm On Mar 19, 2016 |
Thank you baba ifankaleluya and healthfirst Ifankaleluya: |
Re: .. by zenith329: 10:05pm On Mar 19, 2016 |
[quote author=dominicson post=43910265]I intended posting ten confirmed Imule, but now I'm afraid the next eight could make the female ones among us 'fly'. So helpless I am to help those I know they really need these imule here! Ejo sir, mo need awon imule yii, pls, kindly send it to my e mail : johnmike329@yahoo.com 1 Like |
Re: .. by akingbemi(m): 10:37pm On Mar 19, 2016 |
KEHINDE633:Ofo Nikan Ni Tabi Pelu Atare, 1 Like |
Re: .. by dominicson: 11:07pm On Mar 19, 2016 |
dominicson: Yes, a o gbe etutu yii jina si ibi ti a n gbe. Ekuru meje ti a jo pelu atare kan ni a o fi te odu osa eleye ti a o fi won(bu si ori) ipese yii. Ti o ba se e se, oru ojo yii gan ni odara ki a se ikeji(the second part) ti o lo bayi: Ebu. Oromodie (a chick) ati atare kan, a o jo, a o da ebu yii si inu igba olomori kekere kan. A o tun jo alapandede ati atare kan, a o da sinu igba kekere miran. A o jo eye ega kan ati atare kan, a o da sinu igba olomori keta. Ti o ba di agogo kan oru, a o te aso funfun si ile ni gbangba abe sanmo. A o joko le lori ni ihoho. A o wa akara elepo meta. A o fi akara kan je ebu inu igba kan. So, akara meta, igba meta. Ki a to je, a o so wipe: Eyin alaye, mo ba yin mule loni o. Emi o ba yin fi omo mi mule o. Emi o ba yin mule a n pa ara eni l'aya, l'omo... Emi wa ba yin mule kin le la, kin n le lu, ki n le ri owo se fuja. Ti eran ba n wu yin je, awon ota mi ni ki e ma mu pa je lokokan o. 3 Likes |
Re: .. by wale259(m): 11:36pm On Mar 19, 2016 |
Sir,ki ni a ma fi te ifa Osa meji na,se iyereosun ni abi awon ewe ti agun papo yen. cancioamor: |
Re: .. by dominicson: 12:01am On Mar 20, 2016 |
Imule 4: Olongbo nla kan, owo eyo ogoji(ailu), ewe oriji oojo, atare kan. A o jo papo, ao te ebu yii ni ogbe meji/eji ogbe, a o ro itan/ofo/gbolohun/psalm re si, a o ro sinu ato/seere/ado. Psalm: Iweku-ni-iweku, iweja-ni-iweja, a difa fun okanlenirinwo n'ijo ti won lo re yan ipin l'odo Oodua. Won pin aje(wealth) fun Olubini, won pin okun(re do) fun Olurada, won pin ide fun Osun, won pin oje fun Orisa-nla, won pin irin dudu fun ogun, won pin igba omi fun Agbonmeregun, won pin ile(land) fun Oba l'ode Oyo(do mi), won pin isekuse fun Esu Odara. Asotito bo s'ile, o gba aje lowo Olubini, o gba okun lowo Olurada, o gba ide lowo Osun, o gba oje lowo Orisa-nla, o gba irin dudu lowo Ogun, o gba igba omi lowo Agbonmeregun, o gba ile lowo Oba l'ode Oyo. Won wa ni ki Esu o mu isekuse owo re wa, Esu ni ki won o fi ti oun ji oun. Won ni ee ti ri? O ni se bi oba ni eyin, ologinni ni oun. Ati ile, ati ona ni oba fi n ji ologinni, eyin alaye, e wa fi adun aye gbogbo ji mi. Orijin lo ni ki e fi gbogbo ire ti n be ni ode isalaye ji mi. Nitoripe apejin(do do do) ni ti ogoji, e fi ire nla nla ji mi, e fi asise mi gbogbo ji mi o. 4 Likes 1 Share |
Re: .. by wale259(m): 12:25am On Mar 20, 2016 |
Sir,se ale ni lilo ebu yi ati wipe se gbogbo igba ta ba fe lo ni a o ma te ifa eji ogbe si lati pe ohun re si...Aye ologini ni abi Oku re,kini a ma fi lo sir. dominicson: |
Re: .. by dominicson: 12:31am On Mar 20, 2016 |
wale259: Eko tutu la a fi lo. Owuro kutukutu la a lo. Aaye ologinni nla la a lo. Ti a ba ti pe gbolohun si ki a to ro sinu ato, o ti daa. 2 Likes |
Re: .. by wale259(m): 12:40am On Mar 20, 2016 |
E se sir,Agba yin o ni baje dominicson: |
Re: .. by Lero70: 3:50am On Mar 20, 2016 |
@Dominicson Ejowo efunmi ni phone no. Ati email add yin 1 Like |
(1) (2) (3) ... (64) (65) (66) (67) (68) (69) (70) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 97 |