Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,163,336 members, 7,853,506 topics. Date: Friday, 07 June 2024 at 06:01 PM

.. - Culture (70) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1833390 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (67) (68) (69) (70) (71) (72) (73) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by bwayomide: 8:19am On Mar 25, 2016
eejo baba,se ao ka omo ileke itun ati ifa ye ni woro kankan ti yio fi pe merindinlogun ni tabi a o ka ni eyokan bi won se di si ara igi re titi ti yio fi pe merindinlogun,ese baba,oodua a gbe wa ooo.
Re: .. by dytex: 9:58am On Mar 25, 2016
eku ise o odua agbewa o ejowo nje tiwon ba ji irawo eniyan nje eniyan le ri gba pada eseun

1 Like

Re: .. by Ifankaleluya: 10:09pm On Mar 25, 2016
bwayomide:
eejo baba,se ao ka omo ileke itun ati ifa ye ni woro kankan ti yio fi pe merindinlogun ni tabi a o ka ni eyokan bi won se di si ara igi re titi ti yio fi pe merindinlogun,ese baba,oodua a gbe wa ooo.

Ao ka Ileke-Itun yen ni eyo ko kan ni.

2 Likes

Re: .. by Ifankaleluya: 10:15pm On Mar 25, 2016
dytex:
eku ise o odua agbewa o ejowo nje tiwon ba ji irawo eniyan nje eniyan le ri gba pada eseun

Baba...ti eniyan kan ba so fun yin wipe ogun kan wa ti e le se. O kan fe gba owo lowo yin lasan ni.

E ke si awon babalawo to gbofa yanran-yanran ki won o ba yin so ifa kale ni, ki ifa o ba yin ba olodumare soro ki eleda yin o so bi e o ba ti rin irin-ajo aye yin . Etutu dara ju egberun-ogun lo..!

2 Likes

Re: .. by wale259(m): 11:24pm On Mar 25, 2016
Sir,ki ni a ma fi Abeere yen se nibe?
Ifankaleluya:
@wildLife
pls i need ur e-mail or line.

1 Like

Re: .. by castrol180(m): 7:58am On Mar 26, 2016
Pls if you are just visiting this thread for the first time but you'd like to either comment or contribute in any way, kindly read the first page about the rules.

No translating the Ogun in English Language
No Phone numbers

In addition, any Oogun Owo, Osole are not allowed and do not post any unverified Oogun.

We do not want anything that would affect the health and spiritual lives of the users. We have noticed some contributors who have being posting incomplete charms but we have warned them to stay away from the thread. What we want is quality and effective Oogun. The only contributor who has being posting reliable Oogun is KadunaSouth but others are just empty trash. Incomplete Oogun have negative impact on people; apart from the fact that it won't work, it'd also waste their money.

Pls adhere strictly to these rules. Thanks.
you also post incomplete ogun on several occasions, just for example where you put ayeta out and u decide to type ewe..... and now u are telling others not to
Re: .. by Ifankaleluya: 2:45pm On Mar 26, 2016
omoemi007:
Kini iwulo ewe akoko

Iwulo ewe-akoko(re do re) po daadaa, koda a ma n fi se awure.

Bayi ni a ti ma n lo fun awure

Ao lo wa ewe-akoko yen ti yio po daadaa...ao wa fi schnapps gidi gbo ewe yen, ao wa ro pada sinu igo yen, ao wa da apo aso fun-fun fun,ao wa gbe si igun(re re) yara.

Ao ma mu die-die ni ara-aro pelu adura,ti a ba ti fe bu,ao fi owo(hand) gba igo yen,ao wa wi bayi pe...''fun mi lowo kin daso fun oo, ai ti fun mi lowo ni ko ti je kin n daso fun oo''. Adura wa yio si gba pelu ogo-Olohun!

Aboru, Aboye, Abo-sise.

2 Likes 1 Share

Re: .. by kuddus: 12:13pm On Mar 27, 2016
ejo e fun wa ni ero eniti won na logun
Re: .. by Aareago1: 12:53pm On Mar 27, 2016
Ifankaleluya:
OSO KEKE KAN TO GBONA NIYI

Ewe-laali

Eyin adire ororo(do do do) merin

Oga aaye kan

Owo-titun (#500 or 1000)

Igba-olomori

Ose

Oyin

Lofinda bintu meji.

Ao gun ewe-lali yen daadaa, ao gun awon eyin yen mo, ao gun ose yen papo mo, ao fi oyin po ose yen, leyin na ao tun po pelu lofinda bintu kan, ao fi owo(money) yen tele(mi do) igba, ao fi Oga yen le owo yen lori ki o gba awo(do do) owo yen, ao gbe ose yen le lori, ao wa lu ose yen laarin ti yio fi kan Oga yen lara, ao wa tun bintu kan to ku yen si. ao de igba yen pa fun ojo-merindinlogun(16days) ki a to ma we ose na.

Pelu Ogo-Olohun yio si ri be.

NOTE; Akii fi omi si oso yen ti a ba n se lowo oo.

Aboru, Aboye!

E seun fun ise yii, sugbon ibeere wa. Bawo ni ise yii se maa sise?
2. Eewo wo ni ise yi ni?
3. Ti eeyan ba lo ose yii tan, se eeyan le na owo ti a fi sori oga yen abi bawo?

E seun. Ko ni tan mbe o.
Re: .. by castrol180(m): 9:35am On Mar 28, 2016
omoalade144:
Inu mi dun gidigidi si iwe tie gbe jade yi, nitori pe, iwe yi wa gege bi agbara fun omo yoruba tooto,
nitori idi eyi, moro
gbogbo wa pe kia nipin ninu iwe yi.
Emi gan papa n tiraka lati nipin ninu
iwe yi .mosi mope lagbara OLORUN ELEDUMARE emi na ani iwe yi lowo.ASE.


Iwe ti won fe ta ni 15,000 naira, bawo le se fe ki gbogbo wa ni lowo? Won ko fe ki a ni iwe na, nitoripe ti won ba fe ka ni lowo ko ni won to ba yen. Egberun meedogun naira

1 Like

Re: .. by alexdan1881: 4:59pm On Mar 28, 2016
kadunasouth:
Asiri Owo(Asiri bibo)
Eye lekeleke odidi kan ao fi orisi owo meji, eyokan lapa otun, ikan lapa osi e.g (1000 naira and 500naira) or 200/100
Ao gbe sinu agbada ao ko opolopo ewe aje lelori ti yio bomole ao wa fi odidi atare meta si ati oko atare meta ati eyo atare meta ao jo ao ma fi miliki olope lo lararo kato soro si eniyan odaju
Ise yi dara debi wipe taba lotan osukan si meji atun ma sise lo larawa, lekeleke ki rinrin idoti asiriwa yio bo, ise yi daju tobarise oti kuro ninu egbe otosi.
Danwo o confirm No repercursion
ESE gan Ni baba olohun ama wa pelu yin. kini OKO ATARE?

1 Like

Re: .. by alexdan1881: 6:27pm On Mar 28, 2016
kadunasouth:
Ogun Asegbe
Ewe imi esu ati alubosa elewe ao gun papo ao da sinu kolobo ao da ogere epo pupa si ao mala
NB Ise yi dara pupo lona eto gege bi owo fun awan janduku wan ko nile diwa lowo toba lo lona aito koni sise kokinsepe man jemu ise nani

Ese baba olohun a ma wa pelu yin. ejo kini onje ( meaning) KOLOBI?

2 Likes

Re: .. by alexdan1881: 6:27pm On Mar 28, 2016
kadunasouth:
Ogun Asegbe
Ewe imi esu ati alubosa elewe ao gun papo ao da sinu kolobo ao da ogere epo pupa si ao mala
NB Ise yi dara pupo lona eto gege bi owo fun awan janduku wan ko nile diwa lowo toba lo lona aito koni sise kokinsepe man jemu ise nani

Ese baba olohun a ma wa pelu yin. ejo kini onje ( meaning) KOLOBO ?
Re: .. by wale259(m): 7:31pm On Mar 28, 2016
E sir,bi eniyan to ti ma n ji bi ago meta,merin lati se adua,se ko se nkankan to ba lo ko to bere adua abi o di ti ile ba mo.
alexdan1881:

ESE gan Ni baba olohun ama wa pelu yin. kini OKO ATARE?
Re: .. by alexdan1881: 10:29am On Mar 30, 2016

Hmmm...ko si wahala fun yin rara.
Mi o ro pe wahala wa fun yin. Ogbona ( Charcoal) lo fe lo. Efi okan bale

1 Like

Re: .. by alexdan1881: 10:42am On Mar 30, 2016
kadunasouth:



OGUN ILE KIKO odaju

Irun, ori, alakan okan aguntan, odidi atare ao jo ao pa tagiri ni pansa ao kosi tabi ka kosi inu owu tutu ao wa kosinu tagiri ao we lowu dudu ati funfun ao bomole
Ofore lowo lowo laguntan nrin ojo odun meji kipa bara, akiri kekere akan koma kole, ojo tabafa ori lama enikan kimagba torikun gbogbo ona ni kola kanmi ninu odun yi kinri owo pari ilemin Mojuba gbogbo eyin ti oloun ko ile ayele lowo iba agbagba iba omode iba okunrin iba obinrin yio ma juwa se o ase edumare
Se Ise yi ko Ni Repercussion?
Re: .. by alexdan1881: 10:53am On Mar 30, 2016
kadunasouth:
[/color][color=#990000]


OGUN ISORA AIKU
Adigbanaku mesan eyo atare mesan ao lo kuna dada ao fi sin gbere mesan sori opari



[color=#006600][/color]

Se ama se igbin yi lepo lata ni

1 Like

Re: .. by Rokeeb75: 7:50pm On Mar 30, 2016
Moki gbogbo awon agba agba ton fi tewe te gbo se awon omo eniyan ni anu oo, Ewe yo maje fun yin lase Edumare..... Edakun Efun mi ni Ise MAYEHUN to daju ti eniyan le lo fi ba eniyan Soro lati ori Phone ti yo si se bi a tinfe... Ejowo
Re: .. by Ifankaleluya: 8:07pm On Mar 30, 2016
Ifa so ninu odu-mimo re Ogbe riku sa.

Ogbe sa

N o la

Ogbe ko sa

N o la

Oriire Agbo nii s'Agbo nire kaa oko

difa fun Alakoko(re mi mi mi)

A bu f'osorun akoko(do mi mi)

Alakoko oo, Oba lo je!

Osorun re Oba lo je!

Ifa bo ba semi(re mi) titi

ki o gbemi dele Aje(re mi)

kinrinjin(re re re),kinrinjin(do do mi)

Ibi rere n l'ope n gbemi i re,

Ori o ba semi titi ki o gbemi dele

ire gbogbo kinrinjin, kinrinjin

Ibi rere n l'ope n gbemi re.

Lagbara lowo Eledumare, Ori wa yio se wa titi, yio si gbe wa dele(mi mi) Ire gbogbo. Ase!

Aboru, Aboye, Abo-sise.

2 Likes

Re: .. by Ifankaleluya: 8:17pm On Mar 30, 2016
IFA ERO TI A MA N SE SINU ILE TABI SHOP
Ewe-ekuku,
Ewe-ekuya,
Ewe-imi esu
Ejo-aro kan to tobi
ao gbele larin ile tabi shop yen,
ao fi eja-aro yen tele koto yen,
ao ko ewe-imi esu le lori
ao wa ko awon ewe yen toku si
ao wa fi yepe ki mole(mi do),
Awon agbalagba ki yio le wo ile tabi shop wa lati di wa lowo..!

3 Likes

Re: .. by Rokeeb75: 10:02pm On Mar 30, 2016
[color=#990000]EJOWO MOFE MAYEHUN EYI TI A LE FI GBA NKAN NI OWO ENIYAN LATI ORI PHONE.... EJOWO MA DUPE DUPE TI EBA SE MI LORE YI..
Re: .. by cancioamor: 10:50pm On Mar 30, 2016
she nkan etoyin lefe fi gba. tio ba ti je nkan eto yin, eyi ti mofe fun yin koni sise ooo?
Rokeeb75:
[color=#990000]EJOWO MOFE MAYEHUN EYI TI A LE FI GBA NKAN NI OWO ENIYAN LATI ORI PHONE.... EJOWO MA DUPE DUPE TI EBA SE MI LORE YI..
Re: .. by Djbless: 12:18am On Mar 31, 2016
ejo baba mo send message kan si yin lori email eti dami loun
Re: .. by Tevez83839: 6:51am On Mar 31, 2016
Number mi niyi baba healthfirst .pls add me to whatsapp group 08162736520
Re: .. by mrdayo23456: 9:25pm On Mar 31, 2016
Baba mobeyin efunmi ni ogun ti eniyan lefi ba oyibo soro tia funi lowo
Re: .. by zenith329: 10:10pm On Apr 01, 2016
Ejo, kilo je koro isin?
Re: .. by dominicson: 12:18am On Apr 02, 2016
Zenlife:
@Healthfirst
Baba ejowo e funwa ni oogun ki iyawo mon see bi oko baa ti fe ni gbogbo igba. E seun. Edumare a to ju yin fun wa o. Ewe a je o.



Perhaps you need to pay her dowry again!

But this time to Osumare. It is always found at the riverside. When it is found, the simple ritual is made there, saying: Osumare, Osumare, Osumare, lati ijo alaye ti d'aye ni iwo Osumare ti n se oko odo, ko si si enikankan ti n ba o du. Lati oni yii lo enikeni ko gbodo ba mi du (your wife's name), be it her parents, her work, her boss, her anything. Mo ti mu owo ori re(do) wa fun iwo Osumare loni o, emi nikan ni kin ma ba se loko-laya o, ife t'emi nikan ni ki o ma gbile ninu re, oro mi nikan ni ki o ma wo o l'eti." You will then take one of the moneys paid to osumare, give to your wife to buy you something with it.

2 Likes

(1) (2) (3) ... (67) (68) (69) (70) (71) (72) (73) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 46
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.