Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,449 members, 7,850,570 topics. Date: Wednesday, 05 June 2024 at 03:49 AM

Oriki Orile - Literature - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Oriki Orile (10593 Views)

Orin Orile Ede Naijiria Ni Ede Yoruba Ati Ni Geesi (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Oriki Orile by oloriireomo(m): 3:09pm On Sep 11, 2013
IKOYI ESO


Aporogunjo ikoyi gbera n le o dide ogun to lo,
Ojo kinni to nikoyi ku, oju mi paa lose agba ni mi Ko tii da,sugbon mo kuro lomo agbekorun lo inu oko.
Won gbele won bo onikoyi mo nipekun orisanla,agbedegbede onikoyi lo sun ibe,Atari onikoyi Ko sun ibe, eyin lomo asiju apo piri dagba ofa sofun,pofun yoo yo dagba ofa sile,omo aku fepo tele koto,omo igunnugun bale won a jori akalamagbo bale won a jedo

1 Like

(1) (Reply)

The Last Venture / Let's Discuss Yoruba Literature... / A Saint In Disguise

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.