Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,161,158 members, 7,845,814 topics. Date: Friday, 31 May 2024 at 04:31 AM

Oro Buruku Ti Messi So Fun Luis Enrique - Sports - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Sports / Oro Buruku Ti Messi So Fun Luis Enrique (425 Views)

"If Real Madrid Turns Out Be Laliga Champion"- Luis Enrique / Barcelona Must Score Five Goals Vs Juventus - Luis Enrique / Barcelona Out Of Europe And This Is What Luis Enrique Had To Say (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Oro Buruku Ti Messi So Fun Luis Enrique by Olajuwonryan(m): 8:06pm On Jan 29, 2015
Abolade Olajuwon Ryan

Sebi awa so fun yin wipe gobe sele ni Barcelona, wipe ko si irepo laarin Messi ati Luis Enrique. Mo so wipe oka ma fo, wipe a ma to ri fur* adiye.

Gbogbo oro ti Bartomeu ati Enrique n so fun wa wipe ko si gobe kankan, oro ife ni o, iro bansa!

Mathieu Jeremy, alayo Barcelona lo ba awon elero amititi orile ede France, RMC, wipe "igba ti a de lati isinmi ni gobe sele.

Ni Messi ba gbagbe ara re, bi a se n gbaradi, ni o ye ki won fun fere fun Messi fun ika ti won se e fun, Enrique ko si fun fere fun boolu na.

"Ni gobe ba sele, Messi ba so oro buruku si Enrique, o binu so awon oro won yi ni, Enrique ko lati dake fun, awon mejeeji ba wo'nu ija oro.

"Sugbon, ko ye ki oro na fa wahala to yen, awon oniroyin lo gbe gbigbona ju. Nitori a si je Barca ni oro na je be, awon eyan ma n karamo gbogbo nkan ti a ba se, won ko reti iwa buruku lati odo wa rara."

Ese ti kika.

1 Like

(1) (Reply)

Enyeama In Fresh Links With Liverpool / What A Game! / Breaking:realmadrid Sacks Carlo Ancellotti

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.