Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,861 members, 7,838,085 topics. Date: Thursday, 23 May 2024 at 03:15 PM

.. - Culture (36) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1831569 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (33) (34) (35) (36) (37) (38) (39) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Nobody: 2:06pm On Nov 29, 2015
x

2 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 6:35pm On Nov 29, 2015
ayokomi1010:
Aye mojuba o,moki gbogbo ojogbon ti olorun ni Ki won mafi tewetegbo se Omo araye lore,e Jo mobere Ogun kan tosi dunmi lokan,e si Dami loun ejowo mofi olodumare be gbogbo ile,Ogun na nipe ti nkan Omo kunrin ba kere ju OJO ori re lo,atipe oyun funfun Jade ni nu nkan omokunrin re,Ki le Ba obinrin lajosepo ju ekanlo ti a fi sunlo,kini mole lofun ejowo,baba ati gbogbo ojogbon e sanumi
Re: .. by Nobody: 6:37pm On Nov 29, 2015
EJOWO BABA KINI WON LO EWE PANDORO FUN?
Re: .. by omoalade144(m): 8:05pm On Nov 29, 2015
Aye totoooooo!!!
Re: .. by omoalade144(m): 8:41pm On Nov 29, 2015
ejoo sir mo fe ki e funwa ni ogun aworo ti ale fi fo nkan bii [table] oja tabi [banner or flex]
Re: .. by Nobody: 9:00pm On Nov 29, 2015
.
Re: .. by kadunasouth(m): 9:19pm On Nov 29, 2015
omoalade144:
ejoo sir mo fe ki e funwa ni ogun aworo ti ale fi fo nkan bii [table] oja tabi [banner or flex]
Ogun itaja tale fofo ntafeta tabi ayika ibi tati taja
Ewe abamoda epo obo ata ijosi gbogbore niwan ba niwanba(small small) ao gun month ose dudu ao fi fo nkan ta feta opari

2 Likes

Re: .. by Ifadamilola30: 10:12pm On Nov 29, 2015
healthFirst:
104
EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9
Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua.
E dan wo ke fun mi labo.

Mo ki yin lopolopo, baba Healthfirst, e dakun se ao se aseje yi Lepo Niyo??

1 Like

Re: .. by omoalade144(m): 10:26pm On Nov 29, 2015
Ese lopolopo, odua a gbewa o.
Re: .. by Ifadamilola30: 8:04am On Nov 30, 2015
healthFirst:
104
EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9
Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua.
E dan wo ke fun mi labo.

IBA!! Baba Healthfirst, baba Kadunasouth, ati eyin Awo, e dakun e gbami!! ti mo ba ti nto, inu inkan omo kunrin mi ma n tami, a si tun ma gbona. E dakun e gbami. O se pe Osekan ti eyi bere!! E gbami, eo ni foju sunkun ikankan ninu awon omo yin!!
Re: .. by kadunasouth(m): 8:58am On Nov 30, 2015
Ogun Fun Eni To nse Ise Isegun ti kokinri customer dada
Eso ewe oyo lopolopo, Ewe taba ao jo papo ma odidi atare kan ao mala pelu oyin lararo

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 9:05am On Nov 30, 2015
Ifadamilola30:


IBA!! Baba Healthfirst, baba Kadunasouth, ati eyin Awo, e dakun e gbami!! ti mo ba ti nto, inu inkan omo kunrin mi ma n tami, a si tun ma gbona. E dakun e gbami. O se pe Osekan ti eyi bere!! E gbami, eo ni foju sunkun ikankan ninu awon omo yin!!

Awan Apere Arun iba lopo leleyi bi atosi, ogun atosi lemalo
Egbiyanju eleyi

OGUN ATOSI:- Bara, baaka, egbo jebo, kanhun bilala, ao la bara si meji, ao ko gbogbo egusi inu re kuro, ao wa ge si wewe, ao ko sinu ikoko agbo, ao se gbogbo re lagbo pelu kanhun bilala na ti oba ti jina daadaa, eni na yio ma mu ilaji gaasi cup stainless laro ati laale

2 Likes

Re: .. by dosht(f): 11:53am On Nov 30, 2015
healthFirst:
104
EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9
Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua.
E dan wo ke fun mi labo.
Se a le ko ifun eja na kuro?
Se eja aro dudu tabi eja aso?
Se kosi ni ipalara fun ogberi?

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:14pm On Nov 30, 2015
dosht:

Se a le ko ifun eja na kuro?
Se eja aro dudu tabi eja aso?
Se kosi ni ipalara fun ogberi?

Ko si ipalara nibe. E ko ifun inu e danu sugbon, eja na ko gbudo ge ja.

2 Likes

Re: .. by Bostilo: 3:40pm On Nov 30, 2015
E jowo kini eni tikoba kin je eja oro lelo dipo?

healthFirst:


Ko si ipalara nibe. E ko ifun inu e danu sugbon, eja na ko gbudo ge ja.

2 Likes

Re: .. by wale259(m): 5:16pm On Nov 30, 2015
Iba Akoda,Iba Aseda,Iba Gbo Eyin Agbalagba Lokunrin,Lobirin....E jo mo fe iranlowo eyin Awo lori ise ti mo n se ki le rise gba rowo gba....Clearing and forwarding ni Apapa....mo n sun mo nji ni lai rise gba....E sanu mi ooo

1 Like

Re: .. by ayokomi1010(m): 5:45pm On Nov 30, 2015
e Ku ojoro,ejo ajowo ni Almelo fun ikan Omo kunrin,to tu oyun jade ti o Ba tun to oju nkan Omo kunrin a ma ta gidi gan,e dakun kini a le lo si
Re: .. by wale259(m): 7:26pm On Nov 30, 2015
kadunasouth:
Ogun fun eni ti aye ban dalamu
ewe lapalapa pupa pelu ewe agogogun, ebo obo ao gun mo ose dudu ao ko sinu igba olomori ao eedu eyokan ao kibo ose na larin ao ma fiwe.
Wan atuwo lorore
Baba kaduna,Ejo kini oruko miran fun ewe agogogun abi oroagogo ni e n so ni.ese sir

1 Like

Re: .. by wale259(m): 7:29pm On Nov 30, 2015
kadunasouth:
Ogun Fun Eni To nse Ise Isegun ti kokinri customer dada
Eso ewe oyo lopolopo, Ewe taba ao jo papo ma odidi atare kan ao mala pelu oyin lararo
Sir,se eni to nse ise clearing and forwarding na le lo ko le ri ise gba abi onisegun nikan lo wa fun?
Re: .. by wale259(m): 7:34pm On Nov 30, 2015
healthFirst:
104
EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9
Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua.
E dan wo ke fun mi labo.
Sir,se lepo,niyo ni atipe ale ja taba fe bere si je...se koni hutuba bi Oun
Re: .. by Snowealth: 7:46pm On Nov 30, 2015
wale259:

Baba kaduna,Ejo kini oruko miran fun ewe agogogun abi oroagogo ni e n so ni.ese sir
E jowo se a le ko ose naa si inu ike Funfun olomori abi dandan ni ko je pe inu igba ni a ma ko si. E seun o, agba ko ni tan lorile.
Re: .. by YourNemesis: 8:15pm On Nov 30, 2015
Aboru Aboye nibi.
Ewe ati egbo a je o!
Re: .. by ayokomi1010(m): 8:33pm On Nov 30, 2015
e kale babakaduna ati gbogbo Omo Awo,ejo e Funmi ni Ogun tole pa arun Lara OKUNRIN ti oyun jade loju nkan omokunrin re ti o basito oju nkan Omo OKUNRIN amata gidigidi,ejowo efunmi ni Ogun iwosan re nisi edakun
Re: .. by kadunasouth(m): 9:11pm On Nov 30, 2015
wale259:

Baba kaduna,Ejo kini oruko miran fun ewe agogogun abi oroagogo ni e n so ni.ese sir
Ewe Agogo igun watun peni ogbe ori akuko owa lodo awon elewe omo otoni oro agogo, oro agogo kokin se ewe egun sakasaka ni

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 9:23pm On Nov 30, 2015
ayokomi1010:
e kale babakaduna ati gbogbo Omo Awo,ejo e Funmi ni Ogun tole pa arun Lara OKUNRIN ti oyun jade loju nkan omokunrin re ti o basito oju nkan Omo OKUNRIN amata gidigidi,ejowo efunmi ni Ogun iwosan re nisi edakun

Atosi lo ndayin lamu, oti pe larayin lofa


OGUN ATOSI:- Bara, baaka, egbo jebo, kanhun bilala, ao la bara si meji, ao ko gbogbo egusi inu re kuro, ao wa ge si wewe, ao ko sinu ikoko agbo, ao se gbogbo re lagbo pelu kanhun bilala na ti oba ti jina daadaa, eni na yio ma mu ilaji gaasi cup stainless laro ati laale

Teba ti se ogun yi tobadi owo asale tefe losun ki eje water melon ti koro tikoro inure leo ma je papo teba ji laro kutu kie to jeun emu omin stainless kan before 7days oun to nse yin yio di oun gbagbe, iba eyin Ajunilo

2 Likes

Re: .. by wale259(m): 9:46pm On Nov 30, 2015
kadunasouth:
OGUN ISOYE
Ewe akoko 16 ori akuko adie togbo dada odidi atare kan aojo ao ma fi oyin la
Sir,se omo odun meta le lo ogun isoye yii?

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 11:14pm On Nov 30, 2015
wale259:

Sir,se omo odun meta le lo ogun isoye yii?

Beeni lila diedie fun tomode tagba odara

1 Like

Re: .. by Shantozy: 11:28pm On Nov 30, 2015
OGUN ANU fun omo university lati mari anu gba nibi gbogbo..e daku efun mi sir!
Re: .. by bwayomide: 7:38am On Dec 01, 2015
mo ki eyin baba mejeji ni kiki ola,olohun a ma ranyin se ooo,imo yin ko ni dobaa lola olohun,ejoo se {ewe oyo} yi ni a npe ni {ewe ayoyo tabi ewedu}.
Re: .. by Ifadamilola30: 8:42am On Dec 01, 2015
kadunasouth:


Awan Apere Arun iba lopo leleyi bi atosi, ogun atosi lemalo
Egbiyanju eleyi

OGUN ATOSI:- Bara, baaka, egbo jebo, kanhun bilala, ao la bara si meji, ao ko gbogbo egusi inu re kuro, ao wa ge si wewe, ao ko sinu ikoko agbo, ao se gbogbo re lagbo pelu kanhun bilala na ti oba ti jina daadaa, eni na yio ma mu ilaji gaasi cup stainless laro ati laale


Modupe lowo yin baba mi kadunasouth ati baba Healthfirst!!. Maa gbiyanju ee wo, ma funyin labo!! Eo ni foju sunkun omo lola OLODUMARE, lola awon iyami abeni aboju merindinlogun, lola orunmila ati lola laaroye!! Ejowo baba, teba le funmi nise ti mio fini ko aarun lara obinrin mon, e dakun e funmi, inu mi yio dun!! Ewe ati Egbo yio ma je funyin!!
Re: .. by Ifadamilola30: 10:03am On Dec 01, 2015
cool
Re: .. by Ifadamilola30: 10:07am On Dec 01, 2015
keyguy59:
AFOSE ase oka ati odindi atare kan ao Jo papo ao fi sin
gbenre kan si isale ete ao ma fi ahon kan
Okigbe ida ogbe pada sodo eni sawa)ao wa agbon
tobo sile funrare ao da lu lori ao lo efun ati osun po ao
ro sinu agbon yen ao gbe sile di aro kutu ojo keji aoji
po ao gbemu laiti soro si eni keni ao lo la agbon toku
mole lorita laro yen otan
MALU-opolo odidi kan ao fi okun di ese re ao wa ewe
ina esinsin ewe airagba ewe oyin ewe sawerepepe
pelu iyo ao lopo ao fi kun eyin opolo yen ao maki
opolo yen pe "se ofe kuni? maiku, ori unfo e? Edo unrin
e?, aragbigbona ni? Tio ba ti wa ku ao wa tu okun ese
re ao jopo mon ijakariwo ati odidi atare kan ao fi se igbadi tabi tira ti won ba luwa mon ao sowipe "OJO TI
OPOLO BATI KUN OSUN SAWEREPEPE OJO NA NI RORUN
Amudo: imi ewure oriso,imi aguntan oriso,ewe
rekureku. Eso agunmona ao gunpo aofi awo ojiji di mo
ara aba irin ni owo mejeji aofi owu dudu ati funfun
wepo o4 ibiti ewure abaso ewure si ni susi. Ibiti abaso
aguntan si ni susi .rekureku kifo koja oju
ona.agunmona kiraye gun igi re jake ao daruko obirin nasi ao kan mo ara igi abo odaju gan o
ASEJE OWO NLA TODAJU- ewe tanapowo 50, iyere
lopolopo, ao fi se akuku adie je, lepo niyo, ao ge ori ati
ese adie naa ao ri mole ao se aseje naa, ao ri owo
lopolopo
OWO-ao te ifa ejiogbe sile ao pe ofo yi si lori-Oludari
aye loruko ti anpe ifa,ina kaan loruko ti anpe etu,ojo ti
obinrin bati di aya oba ojo naa ni won fi owo tire wo,ki
tomode tagba ma fi owo wo emi lagbaja omo lagbaja
loni,ao koju seyin fi ese osi ta yepe naa.(A le ra nkan
ni owo eniyan ki won ma gba owo,eri daju pe efun won ni owo won)use it for your own protection
AGBELEPOTA: Ori ako alangba1, ao fi osun pa, ao ko
atare9 si lenu,ao jopo ao fi sin gbere mesan si arin ori.
OGUN EYONU AIYE: Odidi ladaripon1, Ewe ewuro oojo,
odidi atare1. aojopo, ao da sinu epo pupa ao ma la.
TI AKIFI RANTI SA OGUN SENIYAN.
Ewe igbagbe eyo atare 7 fun obinrin 9 fun okunrin ao
lopo gbere 11 lori.
ORUKA AYETA:ao ge igi atori mejo(coolni
dogbandogba,oruka irin dudu mejo,awo{skin}o
wawa,odindi atare kan,ao jopo ao ko gbogbore sinu
igo kan ao fi etu die foko mu ao ki oruka kan bowo.Efi
etu die si adie lenu kie ki oruka kan bo lese ki wa
yibon si wo.
ogun ki ole ma wole;ao ge ora ara ewure die ti
aguntan die ati ti elede die sinu fitila kan,ao fi ewe ko
ti won pe ni idariko tabi modesina si ao fi fitila miran
de,ao we lowu dudu ati funfun a o gbeko enu ona
OGUN ORUKA ANO SUBU.
Bo wu ki enia ti tobi to tabi ki agbara re ju ti enikan ti a
ba fi oruka yi na yio subu lese kan na.
Ewe ina gbigbe ao lo pelu alahannahan ao pa bara
kan ni oko [parsa] ao ko egbogi ti alo yi si ao wa ko
oruka irin iye ti aba fe si ao wa osun ti won fi kun ibeji lara ao ko le oruka yi na ao de pa mo bara na ao lo ri
si idi ogede wewe gba ijo meje ao lo ko oruka yi ni ijo
keje ao to ju re.
Lilo re:- ao fi ikan bowo fi na enia yio subu.
OSOLE NLA TODAJU- odidi tagiri mejo a o ge wo si meji
meji ti yo wa je 16, a o ko won sinu isasun pelu ori
eiye akala, olongbo kan, iru woro ti ko ni iyo ko po die,
ati ewe orijin a o jo gbogbo re a o si lo kuna daada a o
ma bu ebu na die si owo osi wa a o si fi oyin gidi po a
o fi lo ni eekan losu o ti di dsame date ta lo la o tun lo ni d following month, odaju baba mi kan lo fun mi.
OTIDE OOOOOO, AMUDO AMUDO AMUDO, tested and
OKAY AMUDO... Ewe ogbo meta, ewe apada meta, odidi oga kan, omi
toromini, Áo jopo ao p month ose, ao ko sinu aso
funfun, ao so ko si ibikan ninu ile (house) ti kogbodo
kan ile, (ground). Tia abafe lo ao bu die ninu ose ye ao
ho si owo, ao daruko obinrin ti a fe lo fun sinu re, ao fi
we owo mejeji. OFO RE.... Ogbo loni kio gbo temi lonni, apada loni kio ma le pa oro mi da, aso alaso ni oga
ngba, ekuin ekekun ni toromini nji sun, ekun mi ni ki
lagbaja ma sun loni o . ODAJU
Ogun Asma
Ikarahun igbin ao lo dada yio kuna ao walo sugar
oni koro eyo meta mon ti yio kuna dada ao mala yio
gbadun pelu ogo oloun


MALU-opolo odidi kan ao fi okun di ese re ao wa ***ewe
ina esinsin****

Mo ki yin lopolopo baba keyguy59, e dakun se Ewe Ina ati Ewe Esinsin ni e fe type sibe yen abi Ewe Esinsin?? Oodua yio gbeyin!!

(1) (2) (3) ... (33) (34) (35) (36) (37) (38) (39) ... (99) (Reply)

Viewing this topic: 1 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 65
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.