Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,155,212 members, 7,825,795 topics. Date: Sunday, 12 May 2024 at 11:42 PM

.. - Culture (97) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1830145 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (94) (95) (96) (97) (98) (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Wolad(m): 8:49am On Jun 02, 2019
FORTHNIGHT:


EJO KINI ORUKO MIRAN FUN EWE URERE?

EWE ODUNDUN lo'n je ewe urere.

1 Like 1 Share

Re: .. by Wolad(m): 8:51am On Jun 02, 2019
Midumighty:
ewe rere ni ede adugbo ni u ti won fi si

EWE ODUNDUN lo'n je ewe urere.
Oyato si ewe rere.
Re: .. by Dadanoah(m): 2:00pm On Jun 30, 2019
Eku bi o ti dara, yio dara fu gbogbo wa ooo
Re: .. by SirGod: 2:59pm On Sep 12, 2019
E ku ise Baba a maa ju yin se oo. E jowo, kini eewo ise yii?
dplanner:
OSHOLE OOJO GBEWA 1-10 MILLION TO DAJU GAN
Patako ese esin , ologbo dudu kan, ori igun kan, ori akala kan,iye agbe 11,iye aluko 11, ikode 11, abo adie funfun, a o jo po, a o po mo ose dudu ,a o ko sinu igba olomori, a o gbe igba yen sinu apo aso funfun , a o wa so kainkain tuntun ta fe fi we sinu apo aso funfun yen kale , dandan ni ki a pa eran kan ni ijo ti a ba pari ise yi, a o ko ma we ose na ni ago kan oru, ni Kete ti a ba we ose na tan, a o ko gbogbo Lajuba ti a fi we wa sile, a o wa pada losi baluwe yen , a o ba iya arugbo kan nibe, a o bere lowo re , million naira , ti o ba mu lowo , yi o lo , kama beru, a o lo jo ko de ninu Ile , o daju , yi o gbe wa. Iwo to ba fe dawo le ise yi pe 07067796292, 07055595911.
Re: .. by SirGod: 8:02am On Sep 13, 2019
Aboru boye o Baba, Ewe a maa je fun o, Egbo a maa gba o, E o ni se to lase Eledumare. E jowo mo nilo ise yi tan ni, kini kin se lati le ri gba tan?
Ifankaleluya:
FUN ENITI KO BA SE ASEYORI LORI GBOGBO IDAWOLE RE TABI TI AWON AGBALAGBA KO JE KO RI ONA ABAYO.

IFA NI AWA NI TI A LE FUN YIN,KO KIN NSE OGUN LASAN.

IFA YI JE AKO ATI ABO.

AKOKO NI IWE(BATH) ASEYORI TI GBOGBO OGUN ATI OHUN TI O BA DAWOLE YIO FI MA SESE
EKEJI NI IMULE AJE TI WON FI MA N YOJU SI ENIYAN LOJU ORUN TI WON YIO SI FI ASIRI OGUN AYE RE HAN E.
IFA ELEKEJI YI, TI O BA SE BI WON TI MA N SE,OKUNRIN YIO LO FUN OJO MESAN,OBINRIN YIO LO FUN OJO MEJE. LEYIN TI O BA LO IFA YI TAN,TI ENIYAN BA LO YA X-RAY NI HOSPITAL,WON A RI IGBA NI AYA WA,IGBA(CALABASH) YEN NI AMI TI AWON AJE YIO FI SI WA LARA TO TUMO SI WIPE AWON AJE KO GBODO FI OWO KAN WA MO.

SUGBON NKO NI NI ANFANI LATI FI IFA KEJI YEN SILE LORI IKANNI YI,NITORI AWON KAN TO JE WIPE IWE OGUN NI WON N TA. AWA SI MO ASIRI WON.TORI AWON IWE KAN NI WON N DAKO FUN YIN,WON KIISE BABALAWO. IRO LASAN NI WON N PA FUN YIN.

1.
IWE ASEYORI.

EWE-IYALODE TI KO JA TI KO LU 201, AKO-OKUTA MESAN, ATI EPO-OBO NI AO FI SE AGBO YEN. OMUNU EWE-IYALODE MESAN ATI EPO-OBO DIE NI AO GUN PAPO,TI AO PO MO OSE DUDU DIE TI AO FI SE OSE RE.AO KO AKO-OKUTA YEN TELE IKOKO,AO FI EPO-OBO YEN LE LORI,AO WA KO GBOGBO EWE YEN LE LORI. AO BU OMI TO PO DADA SI,AO GBEKA INA NI DEDE AGOGO-MEFA IROLE. TI AGBO YEN BA TI JINNA,A KO GBODO FI IDI RE KAN ILE OO. A LE WA AKO-OKUTA TI O TOBI DADA KI A GBELE LORI. AO WA KO GBOGBO EWE YEN KURO,AO LO DA SI ORI-AKIITAN. SUGBON,A KO NI KO AKO-OKUTA YEN KURO.
FUN ENITI KO BA NI AGBARA LATI PA ODIDI ERAN,AO TI RA(BUY) ORI ORUKO ATI ESE RE MERERIN SILE,AO KO SINU AWO ABOKADELE DUDU,AO BU EPO PUPA SI LORI. TI O BA DI NI AGOGO-MOKANLA ALE,AO SE ADURA SI,AO LO GBE SI ORITA-META,A KO GBODO WEYIN TI A BA TI GBE KA LE OO.
AO NI SUUURU KI O FI DI AGO-KAN ORU,TI AGO-KAN ORU BA TI LU NI AO FI AGBO YEN WE PELU KENKEHIN TITUN. TI A BA TI WE TAN,AO RI KENKENHIN YEN MOLE,AO KO AKO-OKUTA YEN LO DA SI ORITA-META LORU YEN,A KO SI GBODO WO EYIN TI AO FI WOLE PADA.

GBERE IFA YEN; ESO-LOWEREJENJE MESAN ATI OMO-IRULA MESAN NI AO LO PAPO TI AO FI SIN GBERE MERIN NI AYA APA-OTUN,META NI EYIN APA-OTUN ATI GBERE META NI AYA APA-OSI,MERIN NI EYIN APA OSI. LO BA TAN.

IKILO RE OOO
OBINRIN KO GBODO WE IWE YEN OOO. TI OBINRIN BA WE,AWON IYAMI MA FUN NI EIYE NI OOO.

2
IMULE AWON AJE TO DAJU
ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO GBOGBO IFUN ADIE YEN TI A YO LATI IDI,TORI A KO GBODO PA ADIE YEN LORI,LATI IDI(OBO) NI AO TI GE,TI AO SI TIKO GBOGBO IFUN RE JADE. TI A BA TI KO TAN. AO KO SINU IGBA(CALABASH) YEN,AO WA KO EWE AJE-OBALE TO PO DADA SI LORI. AO WA DE IGBE YEN PA. AO GBE SINU IKOKO,AO GBE KA INA. AO DE KOKO YEN,A KO GBO RO PAPO TI YIO FI JO TAN. TI O BAJO TAN TI ATI LO,AO WA TE NI ODU-IFA OSA-MEJI. AO WA PE IFA RE SI. SUGBON N KO NI FI IFA YI SILE TAN TORI AWON TI WON N TA IWE-OGUN.

NOTE;;
TI O BA NILO GBOGBO IFA YI TAN,FI NUMBER RE SILE LABE KIN NI YI. PELU OGO OLORUN,MA SI FI SILE FUN OOO.

ABORU,ABOYE,ABO-SISE.

1 Like 1 Share

Re: .. by Nobody: 10:07am On Sep 13, 2019
Re: .. by dplanner: 12:57pm On Sep 20, 2019
Aku ola JIMOH ONI, Eku ojo meta e so pe eri owo mi mo , walahi owo lo di ju ,. Mo akosejaye ati irawo re ko le mo ona abayo si ogun aye re , eleyi ko si irawo ti ko le lo yato si iwo to ba ni idiwo lara , pemi fun akosejaye ati irawo re sugbon o fe ko ooo, 07055595911, 07067796292 tabi whatsapp lori mtn. Ise yi ko ja mo fe se ogun owo tabi gbewa kan , iwo na kuro ninu osi, pelu igbiyanju, tori aiduro re , ona lo fi ja si , opo lo ti se orire lati Ara ise yi , Ko da awon ti America gan gba dun re ka tun wa so iwo to wa ni Nigeria .

ASEJE ATI OSE AWURE PELU ASIRI BIBO TO DAJU TARA
Eja aro gbigbe kan , akuko adie funfun kan , ewe ogo to po die, ewe aje to po die, egun ekun die, egun Erin die, egun efon die, ata ijosin 21 , epo , iyo, iru, alubosa, sise re , a o lo awon egun yi kuna dada, a o da sibi Kan, a o gbe si egbe Kan , a o gun eja aro, ewe aje die, ewe ogo die, alubosa, iru, ata ijosin, a o lo won pa po , a o wa fi ese fa ori akuko adie yi tu , a o gba eje re sinu igba kan , a o wa th gbogbo iye ara akuko adie yi, a o ko sinu doo , a o wa ge adie yi si koniye, a ko gbogbo ifun re si inu odo , a o wa fi adie na se aseje lepo niyo , a o wa fi ewe aje se osuka sile , ori ewe yi ni a o gbe aseje yi le , wa fi awon egun ti a lo te Ifa ogundabede, a o ro itan re le lori , a o da sinu obe na , a o wa koje ni gbigbona, a o ma yo gbogbo egun re sinu abo kan , a o wa da egun adie yi pada sinu isasun na , a o wa ko osuka yen ati ewe ogo to se ku mo tinu odo yen , a o wa gun mo ose funfun , a o fi eje adie yen po dada , a o wa ko si inu isasun to a Fi je aseje yen , a o fi omori re de , a wa ma we ni emeta lose , aro ni wiwe re , Idi isasun yi ko gbudo kanle o, a o ma ri owo ni ona kona to daju
ITAN RE
Piripiri ni aje Nke wokun, , parapara ni Ida Nke wole , bi ihuhu ni iye nla lara adie , ojo ti adie ba ti sunkun bibo asiri bayi ni orisa n fi iye basiri re, Iran awon ekun ki ba won je eran ikasin, asiri efon ki tu loju olodan , ogo mi ti de loni ki igba olowo o je mi ni Kia Kia , Mo fe gba jare owo Faye ki won da asiri owo to gbe nkan rere se bo mi loni , nitori gbogbo ara ni sefunsefun ni se are tire , ao se adura si o Opari , oni mejemu ooo, iwo to ba fe se gbo mejemu ko to se ooo. Ikilo o san ju ebo ruru lo
Re: .. by SirGod: 12:00pm On Sep 21, 2019
Aboru boye oo Baba.

E dakun e jowo, Awon agba agba meta wonyi ni mo fe ba ni gbolohun, ati wipe o to ojo meta kan ti mo gbohun won kehin.

Awon naa ni;
1) Healthfirst
2) Kadunasouth ati
3) Ifankaleluya.

E jowo o se koko si mi noo,
Oodua agbe wa oo,
Ase ee.
Re: .. by Yode138: 10:10am On Oct 08, 2019
biometrics:
Aboru boye....?
Ema bami ka lo...
biometrics:
thank God today is December 1st
Eni ni ojo akoko osun titun December.
Let those that have used any charm here that has worked for him or her come forth and share any particular charm rhat works out on this 'itakun'.
I have used Imule Asefijin and it works. Any other person to testify to any other medicine on this thread?

Aboru boye baba... E bawa repost ise Imule asefijin na. Isese agbeyin o.
Re: .. by 08101646045atwp(m): 2:11am On Nov 07, 2019
Aku'ijometa ninu ile mimo yio, moki gbogbo eyin atonisona, ninu ile mimo yi, mosi tun nfi akoko yi ki ( ojogbon K.S) ti won je oludasile ikanni yi wipe aku'atijo o, akoni sasise'o, mori wipe opolopo awon eniyan wa nbere orisirisi awon oropataki ti won kosi ri enidawon lohun ibere won gege bi won se nfe, gege bia ti nse ni won odun die seyin, mobe gbogbo ile wipe ki emabinu siwa, se kamaparo, WhatsApp group lofa, sugbon ni oruko baba wa oludasile ikanniyi ( K.S) ohunkohun ti eyin eniyan wa ba nfe mofe kie mabere bai, Lati akoko yi di ipari odun yi ki eledumare'o sowa ju opin odun lo, gbogbo eyi ti Olorun oba batifi agbara waka nibe ni yio si yanju patapata. Nitori odaju wipe Olorun oba loni aseyori lodo. Mogbadua wipe akoni sasetio. Ajuwase'o

2 Likes 1 Share

Re: .. by dplanner: 2:38pm On Dec 03, 2019
Aku osu tuntun , yi o San wa si owo, alafia ati ohun rere gbogbo, awure ti a ma fi da gbere fun osi , to se wipe eyan meje lo ma da owo se ati ri eyan merin o ku eyan meta, to ba ni fe si kan si lori 07067796292 tabi ko whatsapp mi , osu yi na ni , o je bo se je .

1 Like

Re: .. by dplanner: 2:35pm On Dec 04, 2019
IWO TO BA NI FE LATI JOIN WHATSSAP GROUP IRIN AJO OLA ATI ASEYORI (ROAD TO SUCCESS) https:///HqU7tUZ8LRV8h6tzMkBX8a OR 07067796292

1 Like

Re: .. by dplanner: 2:51pm On Dec 05, 2019
MO AKOSEJAYE ATI IRAWO RE KO LE MO IPIN RE NINU AYE , EYAN TO BA NI FE SI, KAN SI MI LORIWHATSAPP 07067796292.
Re: .. by johndoe16784: 11:52am On Dec 19, 2019
...
Re: .. by biometrics: 1:26am On Jan 11, 2020
Happy New Year to everyone all. Moki gbogbo ile patapata pe ekun odun o.

1 Like

Re: .. by omomajemuorun: 4:33pm On Jan 11, 2020
Ejo sir e fun mi ni email address yin .
Email temi niyi Omomajemuorun @gmail.com
Oro Pataki kan wa timofe ba yin so.
Ewe a ma je o.


ALIUDAVID:
ERO ADAAJINA TABI TI ENIYAN BA TE OGUN MOLE.
Ti o ba wu ni, ao wa igbe abo ewure ao po pelu ori, a o mafi ra ibi ti o wu.
fun egbo ti ko jina, ao sa igbe ewure naa ti yio gbe ao ma ku si oju egbo naa.

MADARIKAN
ao fa irun ori wa ti yio dan, ao gbe ile(ground)koto, ao da irun naa si, ao wa yaa igbe le lori, ao fi odindin atare kan le igbe naa lori ao wa yepe le lori,
o kere sugbon o daju.
IBA EYIN AGBAGBA, IBA EYIN TO LAYE
Re: .. by omomajemuorun: 5:21pm On Jan 11, 2020
Shomar:
Inu mi dun bi mo se wo gbogbo ohun ti o wa lori ikani yi. O wu mi lati fi kun, sugbon mi o ri ohun ti ko si nibi. A mo enikeni le bere ohun ti o ba je tuntun to fe. Mo se ileri pe awon baba ma gbami laye lati fun yin. Iba eyin baba teni ile awo yi o o o. Eyin na ni mo ni ke gbami laye.

Aboru boye o! Edakun, Oogun tin tari ibi danu, e ba wa ju sita
Ewe a ma je o
Re: .. by dplanner: 2:43pm On Jan 14, 2020
MO KI GBOGBO ILE PATA, EYI NI OGUN AROBI TO DAJU TARA
A O FI IKODE OJUDA HA ORI APARO KAN LENU , A O FI ODINDI ATARE KAN SI LEGBE NINU APE , A O JO , A O LO KUNA DADA , A O WA BO EKO ELEWE KAN SI INU IGBA KAN , A O BU OMI DIE SI, A O FI ALAKAN AYE KAN SI KO FO EKO YI , TO BA FO , A O TUN DA EBU ISE YI SI KO FO PO DADA , TO BA FO TAN , A O WA GBEMU ISE TI DE NIYEN , AWON ONA TO GBA SISE PO, A MA GBOGBO ABURU TO BA KO NI DE ODO WA , CONFIRMED NI OOO, 07067796292 .
Re: .. by dplanner: 2:53pm On Jan 14, 2020
OGUN TI A FI WE GBOGBO ABURU , EGUN ATI ABILU BURUKU DANU KURO NI ARA . TI ONA SI LA FUN WA NI TARA .
Ewe orijin , ewe kilefimise, epo obo , epo ajeobale , eku asin kan , oga gbigbe kan, aidan gbigbe kan, opolo gbigbe kan , odindi atare kan, a o jo po , a o lo kuna dada, a o da si meta , apakan a o po pelu ose ati adin dudu , a o ma we lale , apakeji sinu epo pupa , a o ma law leyin iwe lale , eleketa fifo eko mu tabi otin lararo . Odaju gan . 07067796292 .
Re: .. by Brayss(m): 8:59am On Jan 28, 2020
kadunasouth:







OGUN ALAKALA
Aoje atare 7/9 pelu gbolohun yi ao tusi igberi wa ao wa sun
Arapasa loruko ta npe ile aye 3, olokanran gunkan lanpe esu odara 3,Mariwo ye ye ye lanpe ogun 3, efun kimu igun 3, edi kidi ile 3, Akiki odidi made ku iroju ana 3, Odumare jowo bamisegun alakala kiosi gbemileke otami Odumare Ase
Re: .. by Brayss(m): 8:41pm On Jan 29, 2020
kadunasouth:
Fun gbogbo omo ilewe lati pass Exam (secondary/university)
Eso werenjeje eyo meta eyo atare Meta ewe alupaida meta ewe atare die ao lo papo ao fi sin gbere meta si orun owo wa mejeji odaju
NB ti exam bati ku ose kan lati sin, lasiko tasin owo yio ma hunwa sugban mumara oti bere ise niye
Re: .. by Theishow: 12:16am On Feb 11, 2020
Ejowo... e funwa ni email address yin sir
Re: .. by Theishow: 12:39am On Feb 11, 2020


Ise yi ki se ise eyo kan...o si sowon pupo...e kan si mi lori e-mail...ao le fi ise yi sita lofe rara.

ekaale baba, ejowo e fun mi ni WhatsApp number yin
Re: .. by Brayss(m): 5:34pm On Feb 11, 2020
kadunasouth:
ISOYE TA NFI RANTI GBOGBO NKAN
Akuko to batobi dada ao tu iye abiya re ti apa otun ao lomo eyo atare meta tapa osi eyo atare meta ao fi tapa otun sin gbere meta si abiya otun tapa osi si abiya osi ti aba gbagbe nkan kan ao fi apa lu apawa lemeta bi adie pelu ofore ao ranti nkan nan lese kese odaju
OFORE
Bi adie bafi apalu apa pipi iyere aso 3times kin ranti nkan bayi bayi opari.
Fun ibere kansimi lori email mi
Re: .. by Brayss(m): 7:11pm On Feb 11, 2020
Ifankaleluya:
OSO KEKE KAN TO GBONA NIYI

Ewe-laali

Eyin adire ororo(do do do) merin

Oga aaye kan

Owo-titun (#500 or 1000)

Igba-olomori

Ose

Oyin

Lofinda bintu meji.

Ao gun ewe-lali yen daadaa, ao gun awon eyin yen mo, ao gun ose yen papo mo, ao fi oyin po ose yen, leyin na ao tun po pelu lofinda bintu kan, ao fi owo(money) yen tele(mi do) igba, ao fi Oga yen le owo yen lori ki o gba awo(do do) owo yen, ao gbe ose yen le lori, ao wa lu ose yen laarin ti yio fi kan Oga yen lara, ao wa tun bintu kan to ku yen si. ao de igba yen pa fun ojo-merindinlogun(16days) ki a to ma we ose na.

Pelu Ogo-Olohun yio si ri be.

NOTE; Akii fi omi si oso yen ti a ba n se lowo oo.

Aboru, Aboye!
Re: .. by Brayss(m): 3:34pm On Feb 12, 2020
Ifankaleluya:
EBE AWON AGBA

A o lo epo-obo, a da senu ona,a po mo ose, a wa fi iyo fon inu-isasun tuntun kekere kan,ao gbe ose yen sinu re, ao wa fi odidi igbin kan bo inu ose yen. O di wiwe leyin ojo keje ti a se ose yi.

Abori, Aboye, Abo-sise!
Re: .. by SirGod: 1:53am On Mar 09, 2020
Baba E seun oo
Re: .. by SirGod: 1:56am On Mar 09, 2020
Baba pls I need ur contact.
Re: .. by dominicson: 3:27pm On Jun 01, 2020
It freezes my blood anytime I see oshole or ise owo that can bring a fixed amount like 50k, or awure 9k or oshole 200k, or oso gbe wa 5m. I would think what kind of charm or oshole would now fetch me 100m. Yes, 100m. And yes too, for those that would say 'just 100m'. Why 100m? The first day of this year I had a very strong feeling someone is going to bless me with that amount before the last day of this year. This, I'm very sure those scam babalawo won't have ise to bring such amount. I know. I have that conviction. There's nothing like oshole 50k, osole 1m. I'm not saying such ise won't work, but telling me it brings a particular fixed amount for everyone who uses it is what I won't concur with. I was born into this. Parents and grandparents are into mysticism. African science! None of these forebare ever mention such. There was a particular incidence that involved this present writer that uphold my belief in this. It even changed the minds of those who believed such. In the midst of initiates, n old man was encouraging us to prepare a particular charm that would fetch 100k that very day which nothing would stop it. Everyone was preparing his own, so was I. I joined the train for just one reason: I participated because I remember an incidence that happened one day with my late father. We visited a close friend of his, an awo. Met him eating, offered us water to wash our hand, meaning we should join him. I was surprised my father collected the water, signifying his intention to eat. While would my father want to eat when we barely finished eating pounded yam and bush meat before we came. I was more surprised because my father was a meat eater. I and my other siblings did bet on number of morsels he would swallow during a meal. Some would bet on 2 and some on 3. No one ever bet on 4 or more. There was even a day none of us won, he swallowed just a morsel, but plenty meats. Now the food the man offered had just two meats. Father extended the water to me, and made face before I could protest. I was literally playing with the food, while father swallowed 4 morsels in the course of the meal. None of my siblings and cousins believed me that papa could swallow 4 morsels when later I told them.

He later told me he forced himself to eat it because some other time you may need the food badly and once they see you as classy people now, you may not be invited. It's not only food. You may need something desperately from them...

So, I used the said oshole that could fetch 100k. It was during those period I do use imule like my life depended on it. Barely 5 minutes after, a young man called me, he introduced himself, his name and his friend who gave him my contact. I said jokingly, "omo mi daada ni" meaning his friend (who linked us) is my good son. He said "yes, that's the very reason I am calling. I also want to be one of your good sons. Please, store my number, so I can call you anytime. And please send me the other number... I mean your account number, I want to give you something to buy recharge card."

And in less than 2 minutes, a seven figure amount strolled in as recharge card money.


There are several factors that determine how much a particular work will fetch...


These works/charms/oshole are like seeds. Where a seed is planted determine the harvest. A seed planted in well prepared fertile land will definitely surpass those planted in desert, or amongst thorns, in yield.

Kannakanna Kan, kowe Kan, eyin ororo oojo Kan, atare Kan, ewe afeloru, if burnt and used once, everything, the same day, with gin, will definitely bring whoever uses it money. No doubt. But I will never tell you it can bring 10m because it has once done for someone, because it has also returned just the capital invested for another person.

2 Likes 1 Share

Re: .. by kehnton(m): 5:30pm On Jun 28, 2020
boluwatife2313:
121 ogun ayeta ao po ojuolongbo to po ao po mose dudu a o ma fiwe ni ojo wednesday bi ojuolongbo base njabo ao jo pelu eyo atare meje fun okunrin mesan fun obinrin ao da sinu oti ao ma mu ni ojo wednesday

ejowo, kini oju ojuolongbo
Re: .. by 08101646045atwp(m): 2:45am On Jul 29, 2020
Fun Covid-19
By Kabiesi Oonirisa.

Afi Awon alumni yi sile fun anfani gbogbo aye
Nitori ojo ti nro ti koida, akoitimo iye eniyan tomapa, ojo ekun koniro lewalori tebitara'o

Awon alumoni naniyi
*ALUBOSA*
Ao ge alubosa si wewe, ao bu si igun yara wa, omanle Asian kiaisan ni inu ile yala otiwa ninu ile tele, tabi osesefe wole alekuro ni igun ile na ati gbogbo ile ti age si.

ELENKEJI TOTUN DABIRE: ao mu alubosa ti age si wewe, ao fi si atelese wa, ao wo ibose si omanda arunkarun duro ninu ago ara ni, ositun man tun gbogbo ago arase.

*ISU OGIRISAKO*
Ogirisako naa situn dara ninu awon egbogi fun iwosan: aomu ogirisako yi aogesi wewe, ao reƩ pelu omidun ati osan wewe tabi omi ati omi osan wewe, tabi emu ewa jinpo odimimu, gasi kan lojumo.

*EWE EWURO*
Ewuro, imiojo, Aidan, eeru awonka, alubosa. Bakanna ao gun papo ao sa si inu ile, tibagbe odi finfin ni turari, gbogbo ohun to nje Asian afojuri ati aifojuri ni yiolelo.

Asitunlemu turari yi bakanna, kiabu sinu omi gbigbona, kia fin pelu dida bulanketi bori pelue ki orure le WO ago arawa.

*EWE EWURO*
Ao gun kunna dada, bi agunmu, kiema busi omigbigbona fun mimu ni ekan lojumo.

*EWE AKOKO*
Ao gun Ewe akoko ati ewe dongoyaro pelu eso dongoyaro papo mo ose iwe eyikeyi, odi wiwe lararo.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni (AAA) ALUMONI AWON AKONI lori WhatsApp

ele fi orukoyin sile si ori :-
https:///8ahrCpBnxgS3qHb0L63Hp8

:- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mase fi number re si abe comment'o
Whala koni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o

(1) (2) (3) ... (94) (95) (96) (97) (98) (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 70
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.