Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,061 members, 7,849,289 topics. Date: Monday, 03 June 2024 at 05:58 PM

Mama H.I.D Awolowo Ti Lo Sun Ninu Oluwa - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Mama H.I.D Awolowo Ti Lo Sun Ninu Oluwa (640 Views)

Oluwo Of Iwo To Engrave Faces Of Mandela, Nkrumah, Awolowo, Others On Stone / Photographer Wo Ni Yoo Jẹ Ẹbun Owo #0.5m Ninu Odun 2017 / Obasanjo Ni Oun Fi (n287bn) Owo Ti Abacha Ji Sile Ninu Apo Ijoba Ni O! (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Mama H.I.D Awolowo Ti Lo Sun Ninu Oluwa by SisiGbeborun(f): 9:27pm On Sep 19, 2015
Won ni oja l'aye, gbogbo wa naa bayi la de wa na oja naa, bope boya, onikaluku a pada re'le naa ni. Mama, Oloye Hannah Idowu Dideolu Awolowo (HID) ti r'orun alakeji. Omo odun mokandinlogorun (99 years) ni mama n se ki olojo to de, ko da, osu meji pere lo ku ki mama HID pe omo ogorun odun. Iroyin ti a ri gbo ni wipe nkan bii wakati die seyin ni mama dake. Ireti wa ni wipe laipe, awon molebi a fi oro sita, lati se ikede iku mama.

(1) (Reply)

PHOTO: Pastor Kumuyi Visits To New Ooni Of Ife, Preaches To Him. / Dance Yoruba Used To Worship Sango / Eze Ndigbo Nairaland. What Happened

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.