Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,328 members, 7,850,171 topics. Date: Tuesday, 04 June 2024 at 03:41 PM

? - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / ? (7605 Views)

.. / The Origin Of Ibile Ife (2) (3) (4)

(1) (2) (Reply) (Go Down)

? by OmoOsanyin: 9:23am On Jan 22, 2016
?
Re: ? by slyng(m): 9:38am On Jan 22, 2016
126 lolz
Re: ? by OmoOsanyin: 9:41am On Jan 22, 2016
1. AWURE
Ewe odan, ewe alo, awe obi ifin kan, awe obi ipa kan, ewe abo, a o gunpo mo ose, a o ko sonu igba. Wiwe.
(Ofo re)
odan loni ki efi ohun rere dan mi wo, alo ni ki efi ohun rere lomi, abo ni bo oloja loju tifi ohun owo re tore, ojumo ki mo ki enia ma se owo lore, omode, agba, okunrin, obinrin ilu yi, ese mi lore o. Wiwe lemeta ose.

2. OKELE
Epo igi oguru guru, eru, esu pupa, a o se lagbo. Mimu ife kan lojumo ati wiwe.

3. Ehin Didun
Oku elena 9, eyo atare 9, aoja aran ope laikan le, aolo, aofi sin gbere 9 si ehin na.

4. ETI DIDUN
Koko to wa lara ako yunrunyun, aojo, ao lo ikandu mo, aofi adi si, aoma fi iye aparo kan si eti na.

5. EFORI
Akuro alantakun mesan, oko ti won ro ti si be be ona a o lopo ko kunna. Ao fi sin mesan si iwaju ori.
Re: ? by Ousmaf(m): 9:55am On Jan 22, 2016
Eku ojumo baba, ejoo efunwa ni number 168: gbetugbetu, Olohun Oba Edumare a ma fun yin se.
Re: ? by Lionhearted: 10:37am On Jan 22, 2016
Eku ise takun takun.

Edakun e ma fi awon ise ti awon eni janduku tabi eni ibi le fi pa omo araye lara sita.

Number 4 yen se owa fun eni ti kigboran daadaa?
Re: ? by OmoOsanyin: 11:09am On Jan 22, 2016
Ki le ma fe lofun? Ogun GbetuGbetu ti a ni lagbara gan, nitori awon o ni jamba, ko ni da ki a gbe sori afefe. Ti e ba fe, e kan mi sori email: theherbalist@india.com

Ogun GbetutuGbetu
Panumo abo, panumo abafe, eyo atare meje...a o ko ni ikobere, a o pa akuko adie...a o ran ni onde awo kawo.
Re: ? by OmoOsanyin: 11:09am On Jan 22, 2016
@?
Re: ? by OmoOsanyin: 11:15am On Jan 22, 2016
Lionhearted:
Eku ise takun takun.

Edakun e ma fi awon ise ti awon eni janduku tabi eni ibi le fi pa omo araye lara sita.

Number 4 yen se owa fun eni ti kigboran daadaa?
eseun, oti o, fun eti didun. Ama fi iye ti e bere sita laipe.
Re: ? by OmoOsanyin: 7:24pm On Jan 22, 2016
JEJERE (Cancer Eyikeyi)

Ao re carrot wewe, ao see pelu alubosa aayuu lilo pelu omi osan wewe. Mimu ni ife kankan 3x - 6x ni ojo,
Re: ? by OmoOsanyin: 7:31pm On Jan 22, 2016
ALAARE OMO (Sickler)

Sibi alubosa aayu lilo kan. Eyin tutu meta, iyo isebe die, sibi witi (wheat) lilo kan, ao gbe ororo olifi (olive oil) kanna, ao da gbogbo kinni wonyi sii, ao roopo daadaa. Yio ma la.
Re: ? by OmoOsanyin: 7:48pm On Jan 22, 2016
ARA TITOBI JU (Obesity)

Omi ti a fun lara alubosa onisu (isebe) pelu omi osan mimu, maa muu tele inu araaro fun osu kan.
Re: ? by OmoOsanyin: 8:13pm On Jan 22, 2016
AWOSA AISAN KINDINRIN

Ewe tamishushu lilo, koobu omi osan wewe kan, idaji koobu omi ti a fun lara alubosa aayuu, idaji koobu ororo olifi (olive oil), poopo, maa mu sibi kan lojoojumo.
Re: ? by simpleworld: 3:50pm On Jan 23, 2016
baba pls ogun inaru ti a peni kokoro inu eje.
Re: ? by Raydos: 5:13pm On Jan 23, 2016
Aboru Boye Oooh
Re: ? by Lionhearted: 5:21pm On Jan 23, 2016
OmoOsanyin:
eseun, oti o, fun eti didun. Ama fi iye ti e bere sita laipe.

Ooda
Re: ? by OmoOsanyin: 6:43pm On Jan 23, 2016
simpleworld:
baba pls ogun inaru ti a peni kokoro inu eje.
AGUNMU NARUN

Egbo agbonyin, egbo olosan, isu gbegbe, ota'nu iroko, eeru, aidan, ifere, baka, iseta, elubo ogede omini, elubo ogede agbagba, isirigun, atare mewa, ata ijosi ati sugar, a o gunwon po ni agunmu, ale see ni capsulu tabi tabilet.
Ewe Aje o.
Re: ? by ALIUDAVID: 10:53pm On Jan 24, 2016
Baba omoosanyin ekale o moti send mail si email ti efi sita sugbon mi otit ri esi baba ebami check e, isese agbewa o...iba agbagba iba eyin to laye..
Re: ? by OmoOsanyin: 1:42pm On Jan 25, 2016
ALIUDAVID:
Baba omoosanyin ekale o moti send mail si email ti efi sita sugbon mi otit ri esi baba ebami check e, isese agbewa o...iba agbagba iba eyin to laye..
ati fi esi si ori email yin, e lo yewo. Adua agba.
Re: ? by ALIUDAVID: 7:56am On Jan 26, 2016
OmoOsanyin:
ati fi esi si ori email yin, e lo yewo. Adua agba.

baba mi o ri esi yen boya e send email yin si aliudavidodunayo@gmail.com isese agbewa iba agba agba o.
Re: ? by Makapounse(m): 9:40am On Jan 26, 2016
153. Ifa Isegun ? , A ma ju yin se oo
Re: ? by Makapounse(m): 11:07am On Jan 26, 2016
55. Iriran ? 64. Aseta Eyonu Araiye ?
Re: ? by Makapounse(m): 11:08am On Jan 26, 2016
55. Iriran ? 64. Aseta Eyonu Araiye ?
Re: ? by OmoOsanyin: 2:17pm On Jan 26, 2016
ALIUDAVID:


baba mi o ri esi yen boya e send email yin si aliudavidodunayo@gmail.com isese agbewa iba agba agba o.
a ti fi esi lori email tuntun yin.
Re: ? by Raydos: 5:46pm On Jan 26, 2016
Ejo Ogun Wo Ni Mo Le Se Ti Mo Maa Fi Gbo Esi-Ayo L'ori Idanwo Ti Mo Fe Se Yii? - Mofe Jeki Gbogbo Awon Toba Fe Mark Exam Mi, Ki Inu Won Maa Dun Ti Won Ba Ti Ri Oruko Mi.
Re: ? by Lionhearted: 5:48pm On Jan 29, 2016
Eku ise o.
Ogun wo leyan le lo ti inu imun (nose) ba wu ti eemi (breath) eni na ba n run?
Re: ? by ALIUDAVID: 10:08pm On Feb 01, 2016
Ekale gbogbo ile ejo eni ti o ba ni ogun arobi todaju(BACK TO SENDER) ko ju sita fun afani gbogbo wa... Iba agbagba iba eyin to laye..
Re: ? by 08101646045atwp(m): 2:09pm On Feb 24, 2016
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ajuwase'o
Re: ? by OmoOsanyin: 4:33pm On Feb 24, 2016
smiley
Re: ? by OmoOsanyin: 4:36pm On Feb 24, 2016
:/
Re: ? by OmoOsanyin: 4:37pm On Feb 24, 2016
smiley
Re: ? by OmoOsanyin: 4:38pm On Feb 24, 2016
sad
Re: ? by OmoOsanyin: 4:40pm On Feb 24, 2016
wink

(1) (2) (Reply)

Nigerian Mother In Law Could Be Trying To Break Up My Marriage / Andoni Forum (anyone)? / Why Do Igbo Kids Ignore Elders?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 22
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.