Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,616 members, 7,813,026 topics. Date: Tuesday, 30 April 2024 at 04:54 AM

Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori (71460 Views)

Yara Iwosan Ibile Yoruba / Join This Group Today: Lilo Ewe Ati Egbo Ati Eranko (herbs; The Magic Healer) / LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (Reply) (Go Down)

Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 1:06pm On Mar 20, 2016
Hello @ all, this is healtfirst, the creator of the thread 'LILO EWE ATI EGBO FUN IWOSAN, ITUSILE ATI ASEYORI' We have now moved this lofty idea to our at http://liloeweatiegbo..com.ng/. Pls visit the blog for different Ogun isembaye and counseling.


A ti se atunte IWE IWULO EWE ATI EGBO fun gbogbo awon ti won ba ni ife lati ni iwe ayebaye na. A si ti se si orisirisi ona gegebi a ba se ni agbara si nipa iye owo ti a n ta.

SOFT COPY PRICES

Each Volume goes for 3000 naira only and we already have 9 volumes available

Hurry and get yours...Die Omokunrin o to inkan!

Get a copy today and become a full grown man!


Hard copy is also available.

Fun Ekun rere alaye...liloeweatiegbo@gmail.com

1 Like 1 Share

Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 1:53pm On Mar 20, 2016
Visit the blog for updated Oogun everyday
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by eposho: 7:58am On Mar 21, 2016
It's quite a shame that we have to experience the normal squabble, rancour, hatred,jealousy that we failed to resolve on the original thread. I think that's the reason the babalawo consult the oracle daily.
Anyway life continues.
Hopefully this new approach will pave way for the betterment of mankind .
Ire ohhh.
Ke PE fun wa.baba healthfirst.
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 10:06am On Mar 21, 2016
Thanks for your words and I can assure the readers that they'll continue to benefit from what I'm wiling to share freely as long as I can. It obviously became imperative to move the idea to a blog under my control...as with all things in this world, if control is lacking, destabilization is the inevitable next thing. No one is perfect but for proper growth and advancement, those who initiated an idea must be respected and if he/she need to be put right in some ways, it needs to be done with wisdom not through blackmail. No one is all wise...healthfist inclusive.

On the blog, corrections and observations from readers/contributors are welcome but it must be in a constructive way such that we'll all benefit.

1 Like

Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 1:10pm On Mar 21, 2016
Visit the blog here http://liloeweatiegbo..com.ng/ we'll continue to update it daily

1 Like

Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 11:41pm On Mar 21, 2016

2 Likes

Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by whykay77: 4:06am On Mar 22, 2016
Ok glad to hear this and how about @kadunasouth is he posting on your blog too or he has moved?

1 Like

Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 8:21am On Mar 22, 2016
whykay77:
Ok glad to hear this and how about @kadunasouth is he posting on your blog too or he has moved?

I hope he'll join us soon.

2 Likes

Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 5:30pm On Mar 24, 2016
Ifa ni:
Orunmila lo di agbeka (dmm);
Ifa ni iwaro, iwaro, iwaro;
A dia fun Orunmila Atewonro;
Ti yio ti Ode Orun ro s'ode Isalaye;
O lo si popo Olodumare;
O le gongo k'ale;
Eruku gb'owo kan osi;
Oyele gb'owo kan otun;
O ro, O ro dede s'ori omi;
O wa so oyele s'ile;
O ya enu koto, orin lo bo sii l'enu;
Adiye dudu oyele;
Wa ba wa ye ile yi wo!
Adiye oyele ye ile yi wo!
Aase!
(Ogbe-Ka).
Orunmila a tun Ile wa se! Aase!

liloeweatiegbo..com.ng
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 10:18am On Mar 25, 2016
O dara ki awon to ni asthma ati awon ti aya n dun maa je obe yi:
1. Ewe Marigbojiyan (Luku)
2. Odidi atare kan.
3. Ogiri (ko si maggi)
4. Eja.
5. Ata ijosi die.
Re gbogbo ewe yen patapata lai si
igi! Lo papo. Fi epo kiun si! Se ki o si gbon mu

http://liloeweatiegbo..com.ng/

2 Likes

Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 9:09am On Mar 27, 2016
OOGUN ARUN OJU ARA OBINRIN(candida/yeast infection) http://liloeweatiegbo..com.ng/
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 8:36am On Mar 28, 2016
Oniruru aso kii tan nile alaro
Oniruru ileke kii tan nile Olokun Seniade
Gba fi pamo kii tan nile alantakun
Apo sasara kii sofo
Oniruru ohun rere ko ni tan lowo wa!
Aase
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by Zenlife: 2:21am On Apr 05, 2016
Sir, why not operate this new thread alongst with the blog. The blog is somewhat stiff for user interactions and general benefits.
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 5:18pm On Apr 06, 2016
Zenlife:
Sir, why not operate this new thread alongst with the blog. The blog is somewhat stiff for user interactions and general benefits.

Thanks...while I appreciate your efforts and others on the progress of this idea, I wouldn't want a repeat of what happened on my first thread. The blog is far better.

I'll occasionally post here but the main postings will continue on the blog.
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 5:21pm On Apr 06, 2016
visit the thread and make your contribution and observations...no one is an island of knowledge...corrections are welcome as long as it's for the good of all.
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 6:19pm On Apr 06, 2016
Ogbe Eyonu

Eye abapa we
Eye abese we
Eye abiru wemu-wemu
Orisanla Oseeremagbo
Awon ni won lo oja Agunregejege
A wa Awo titi
Awa o r’Awo
A wa Awo de Iliki
A wa Awo de Iwonran
Nibi ojumo rere ti n mo o wa
Ago o Mesiada temi n mu s’odun n’Ife Ooye
Won l’omo eku lo gbe e lo
Mo ni omo eku ko to Ago o Mesiada temi i gbe lo
Esu ode a de panpe
Ni yoo se elenini omo eku
Won lomo eja lo gbe e lo
Mo ni omo eja ko to Ago Mesiada a temi i gbe lo
Esu ode adegere
Ni yoo se elenini omo eja
Won lawon omo eye lo gbe e lo
Mo ni omo eye ko to Ago Mesiada a temi i gbe lo
Esu ode adate
Ni yoo se elenini omo eye
Won lomo eran lo gbe e lo o
Mo ni omo eran ko to Ago Mesiada a temi i gbe lo
Esu ode ayinlasa
Ni yoo se elenini omo eran
Won lomo eni lo gbe e lo
Mo ni omo eni nigbanteyin eni se
Mo ni omo eni yoo gbo ogbo oluyeeyetuye
Omo eni yoo gboo ogbo oluyeeyetuye
Omo eni yoo gbogboogbo
Omo eni yoo totooto
Omo eni yoo lalaala
Omo eni yoo bibiibi
Omo eni yoo rereere
Omo eni yoo fa’kun ola lale aye ja gberegede
Awon ogbe re o gbon o
Awon ogbe re o mo
Awon ogbe re o mo pe Ifa Ola n’Ifa a wa o
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 11:25am On Apr 07, 2016
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by Nostradamus: 9:36am On Jun 28, 2016
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 10:39am On Jun 28, 2016
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by BioTeck: 2:46pm On Jun 30, 2016
E ku ise takuntakun
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 9:31am On Jul 03, 2016
blog updated with various healing herbal formulas...and out herbal book still available for sale...visit the blog today http://liloeweatiegbo..com.ng/
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 6:22pm On Jul 06, 2016
blog updated...visit for various kind of healing herbal formulas...our book on healing still available for sale
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 5:23pm On Jul 09, 2016
1 ARUNKARUN
Baka, isu alubosa, alubosa elewe, ewe taba, egbo tude, ipeta, ao gun won po mose dudu. Odi wiwe.

visit the blog for more
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by dagu: 11:23pm On Jul 13, 2016
You have come here to dupe again after the commotion you caused on your whatsapp group. We can never believe you again, you're a scammer. O kan n ki ifa iro ni, o mo ifa kankan. Go and sell your book for your family member. Stupidd guy.
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 1:12am On Aug 03, 2016
dagu:
You have come here to dupe again after the commotion you caused on your whatsapp group. We can never believe you again, you're a scammer. O kan n ki ifa iro ni, o mo ifa kankan. Go and sell your book for your family member. Stupidd guy.

what commotion are you talking about...i created a group with rules but suddenly it was turned to a marketing arena with fake people. i left the goup...what wrong did i do to warrant your claim?
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 1:15am On Aug 03, 2016
Visit our blog for updated Oogun everyday...for those who wish...nothing is by force.
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by ANAKONDA: 7:37pm On Aug 06, 2016
AyeMoJuba:
Hello @ all, this is healtfirst, the creator of the thread 'LILO EWE ATI EGBO FUN IWOSAN, ITUSILE ATI ASEYORI' We have now moved this lofty idea to our at http://liloeweatiegbo..com.ng/. Pls visit the blog for different Ogun isembaye and counseling.


E ku aigbagbe wa.
E jowo kini a le lo fun ki iho idi maa yun enia. Igba miran a dabi wipe kokoro nrin ninu iho idi na ? E seun pupo.
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 2:21am On Aug 12, 2016
ANAKONDA:



E ku aigbagbe wa.
E jowo kini a le lo fun ki iho idi maa yun enia. Igba miran a dabi wipe kokoro nrin ninu iho idi na ? E seun pupo.

E lo sori blog wa, eo ri orisirisi oogun kokoro ara nibe
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by ANAKONDA: 7:52am On Aug 12, 2016
AyeMoJuba:


E lo sori blog wa, eo ri orisirisi oogun kokoro ara nibe


E se pupo. Ajinde ara yio maa je o.
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 3:53pm On Aug 31, 2016
Iwe Iwulo Ewe ATi Egbo si wa fun tita...e lo sori blog wa fun itonisona lati ri iwe na ra...o wulo pupo fun teru tomo. Die omokunrin o to inkan
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 12:48am On Nov 04, 2016
A ti se atunte IWE IWULO EWE ATI EGBO fun gbogbo awon ti won ba ni ife lati ni iwe ayebaye na. A si ti se si orisirisi ona gegebi a ba se ni agbara si nipa iye owo ti a n ta.

Volume 1....2,500 naira
Volume 1&2...4,000 naira
Volume 1, 2 & 3...5,500 naira
Fun awon ti won ko si nilu Eko, ki won fi owo Courier kun owo volume ti won nife si.
Re: Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori by AyeMoJuba: 8:34am On Nov 29, 2016
A ti fi orisirisi awon iwulo Ewe Ati Egbo si ori blog wa...E lo sibe lati je anfaani awon asiri wonyi. Aye wa fun yin lati kan si wa fun awon asiri miran sugbon gegebi a ti se alaye siwaju, e gbudo setan lati san owo diedie fun awon asiri te ba beere fun yato si awon eyi ti a ti fi sori blog. Iba Awon Ajunilo.

(1) (2) (3) (Reply)

Intersting Facts About The Kalabari Ijaws Of Rivers State (PICTURES) / Igbo Marriage And Bride Price: Put The Records Straight (Represent Your Culture) / Alaafin Of Oyo & Ooni Both Bow To Greet Each Other (Photo)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 52
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.