Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,691 members, 7,816,824 topics. Date: Friday, 03 May 2024 at 05:58 PM

Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re (17276 Views)

Tani Jesu Nse - Jesu Ni Aworan Olorun / Asiri Owo Nla / A Nairalander Realeases His First Song - Olorun Ikore (lord Of The Harvest) (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re by ayokomi1010(m): 10:55pm On Dec 18, 2016
moki Gbogbo ojise Olorun ,emi awon woli a tiwa lehin o,Olorun orimolade,captain Abiodun,bilewu oshofa,ayobabalola,agbojesu,adeola,ati Olorun fakeye,Olorun jolugba,a bawa se o,oun ti o mumi da ikanni yi le,moje eniti o ti idile alawo jade wa,baba mi si lo kewu loju ona Islamic, sugbon sibe Olorun ni koti de ibiti oun fe lo fun iranse oun,loba lo ninu igoke emi 90 days,ti koni ariyan jiyan ninu,osidi Woli Olorun alaye loju ona ijo mimo Cherubim & Seraphim, Olorun silo gidi gan ti mofi mo nigbati moba ara mi,ninu okan Pataki ninu omo ti baba yi bi,ti won sifi asiri adua,Ati iru awon asiri nla to wa larin Olorun ati awon woli re, abajo ti Bibeli wipe (ASIRI OLUWA WA PELU AWON TI O BERU RE, YIO SI FI WON MO MAJEMU RE. ORIN DAFIDI 25:14.) ti enikeni bawa ni Olorun o fi asiri nla re han awon woli ododo re,ajepe iru enibe koni imo ijile ninu oro Olorun, Pataki nipe mowari bi aye se lo loni,lojeki da ikanni yi sile,opo enia loti rope kosi agbara adua mo,pe kosi oruko Olorun ti je mo,koderibe,koda oti jeki opo ojise Olorun gan ti darapomo aye,woti wo pe ewe ati egbo nikan ni ona abayo,pe adura ko gba mo koderi be o,toripe opo o mo base be Olorun ni,atipe opo o ni ASIRI ijinle awon woli lailai,lowo,kepemi Iwo da o loun ni Olorun wi,eyi lo mu mi Da group yi sile,Ki Gbogbo woli ojise Olorun ododo,tikise ti esun,dara po mo ikanni yi ti wasi salabapade ASIRI adua ati eto adua lokan o jokan,to yato si ogun,tori opo ojise Olorun tidi alawo kode Wumi be,Bibeli wipe awon enia mi segbe tori won koni IMO,o le darapo mo ikanni yi fun iranlowo adua ati iranwo awon woli Olorun,Iwo woli o le darapo mo ikanni yi lori wathsapp mi 08135072961/08075198871.JESU ni Oluwa Hallelujah. 4rm SNR AP PRT S.A. AGBOOLA. (Akiyesi mife ija esin,eleyameya,tabi lati fi enu abuku kan ijo tabi eka kan,tabi ojise Olorun kan,misi fe Ki enikeni fi number si Ori ikanni yi,sugbon o le fi eto adura sile,tikibati se ewe ati egbo.

1 Like

Re: Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re by ayokomi1010(m): 11:23pm On Dec 18, 2016
ETO ADUA SOLOMON
ENI keni ti o bafe ojurere ati anu lati odo Olorun ,Ki o te aso funfun sile Ki o,duro Lori re,o dara ju Ki o wani ihoho,Ki o wa pe oruko yi, ELI YA AGLA,ADONAI JOD HE FO HE.21×,KI o wa ka 1Awon Oba 8:1-30. ti a base adura na ao di eni nla.

1 Like

Re: Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re by ayokomi1010(m): 8:52am On Dec 19, 2016
Alafia ni fun Gbogbo eyin ayanfe JEHOVAH
Adura ojo oni niyi,oni ni 19/12/2016,adura yi ni awon eniyan Olorun malo nigbati osun badi mokandilogun
ao ka psalm 61,ni iye igbati a ba lagbara atika,ti ao si gbadura na bayi
YAVAH-JIRE" Oluwa olupese,Alagbara julo iwo ni eniti ohun Gbogbo ko soro fun,loni tise ojo kokandinlogun osun yi,jowo mase jeki oro mi di isoro fun mi,ranmilowo lona mi Gbogbo loni Ki o si bukun mi,Ki o sifi ere sori ise mi,gbemiga ki o sifi oju rere re yimi ka,nitori Jesu Kristi Oluwa wa.Amin.adura yi ni fun ojokokandilogun ninu Gbogbo osun iyowu koje,jesu ni OLUWA,

fun Iwo Woli prophet and prophetess ti o fe dara po mo eto yi Lori whatsapp Ki o add number mi yi,08135072961/08075198871. tabi Iwo ti o fe iranlowo woli.
Re: Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re by ayokomi1010(m): 8:10pm On Dec 27, 2016
alafia Olorun ko ma ba Gbogbo enia,mo fe fun wa ni awon adua ti a le gba Ki Odun titun le di irorun fun ni mo bo
Re: Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re by Lekanewenje: 3:29pm On Nov 29, 2018
ATUDE OSE"
ewe lapa funfun mesan, ewe ewuro ojoo mesan, ewe efinrin mesan, ewe ajaobale mesan, yerupe ago kan osan ati toru, ao gun mose, ao fiwe fun ojo meta pere lori ni ago kan oru ni wiwe re o, ti abatiwe ose ye pari, ao tu kanhinkanhin yeka, ao sonu ni o. Odaju
ISE GBEWA OWO KAN WA NILE BAI
Todaju gan
Asefun awon omo egbe nani tori odun na ti sunmo
Ati danwo
Anfani wafue lati dan ise nawo lodowa
Gbewa owo ni
Ojotabalo
Ojo keji niyo gbewa
Olepemi toba nifesi
09077966532

(1) (Reply)

Adeboye & Wife Folu, Sing For Oby Ezekwesili On Her 60th Birthday (Video) / Another Gospel: The Benny Hinn Experience / Why Do Celestial Church Of Christ Members Go Bare-footed?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 27
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.