Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,161,449 members, 7,846,879 topics. Date: Saturday, 01 June 2024 at 05:28 AM

Yoruba News, Daily Update. - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Yoruba News, Daily Update. (650 Views)

Funny Yoruba News: Mark Zuckerberg In Nigeria & Other Stories (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Yoruba News, Daily Update. by Ayemileto(m): 8:27pm On Dec 08, 2017
E Dese duro fun George:: Awon Odo be awon oludije Yoruba PDP.

Egbe awon odo Yoruba ninu egbe oselu PDP, Iyen Yoruba Youth Vanguard, ni o ti rawo ebe si Omowe Tunde Adeniran ati awon omo Yoruba miran ti on dije fun ipo Alaga ninu egbe PDP lati dese duro fun Oloye Olabode George.

Oloye Olabode George ni o je Igbakeji Alaga egbe naa nigba kan ri.

Egbe awon odo naa, ni won fi ebe yii lede nipase Alaga won, Segun Adigun laana, ojo Keje osu Kejila odun 2017.

Ninu oro egbe naa ni won ti fihan pe ti awon oludije yooku ko ba dese duro, O see se ki Ipo Alaga egbe ti o to si Yoruba bo si owo ogbeni Uche Secondus ti o je ondupo lati apa Guusu Orilede yii.
Re: Yoruba News, Daily Update. by Ayemileto(m): 7:24pm On Dec 09, 2017
E Wa Nnkan Se Soro Epo to Won Gogo – NLC.


Egbe Ayow Osise L’orilede yii, Nigeria Labour Congress, lo ti fi aidunu won han lori oro epo to won gogo L’orilede yii.
Egbe naa ni o soo di mimo pe ko ye ki orilede Naijiria si maa ra epo wole leyin Ogota odun ti won ti sawari epo lopolopo.
Ninu oro ti Aare egbe naa, Ayuba Wabba fi lede lojo Abameta, ni egbe naa ti juwe oro naa gege bi iwa ika ti o sanfani fun awon die.
Ninu oro naa ni won ti juwe oro epo to won gogo gege bi ohun amoomose lati ri ere pupo nitori akoko odun ti o wa nitosi ni awon omo orilede yii maa n lo epo ju.
Egbe naa ni o wa rawo ebe si Ijoba lati wa nnkan se soro naa Kankan.

(1) (Reply)

PHOTOS: 80-yrs-old Alaafin Of Oyo Welcomes Twins With One Of His Wives, Memunat / Check Out Oluwo Of Iwoland's Speech At 2nd Edition Of Bola Tinubu Youth Summit / Stop Promoting Igbo Culture

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.