Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,724 members, 7,837,630 topics. Date: Thursday, 23 May 2024 at 08:35 AM

Vigilante Promise To Fight Boko Haram, Se Photo - Crime - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Crime / Vigilante Promise To Fight Boko Haram, Se Photo (394 Views)

I’m Not Ready To Die For Nigeria" - Soldier As He Prepares To Fight Boko Haram / FG Deploys Drones To Fight Boko Haram / US Sells N181bn Warplanes, Weapons To Nigerian Government To Fight Boko Haram (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Vigilante Promise To Fight Boko Haram, Se Photo by iroyinawikonko: 5:18pm On Jan 25, 2019
AWA ỌLỌDẸ ṢETAN LATI KOJU BOKO HARAM - ỌDẸTỌLA
Iroyin Awikonko 21 mins ago Eto Aabo,

Folukẹ Aduragbemi, Ọsun

Aare egbe olode nipinle Ọsun, Oloye Hammed Nureni ti so pe se lawon ologun orileede yii kan n gbiyanju lasan lori oro ikọ boko haraamu ti wọn n fojoojumo yọ orileede yii lenu, ko si bi agbara won se le kawọ won, ayafi tijoba ba sise papo pelu awon ọlọdẹ.

Nibi eto kan ti egbe naa se nilu Osogbo, laipe yii ni aare won, eni ti gbogbo eeyan mo si Ọdẹtọdẹ, ti ni idi to fi dabi eni pe ọrọ ikọ asekupani ohun n di ojoojumọ bii ẹkun apọkọjẹ ko ṣẹyin bo se je pe ilana ẹkọ awon ologun ko fun won lagbara lati wo kọrọkọndu ibi tawon ikọ naa n farapamo si.

Oloye Nureni so siwaju pe, "a bi awa olode sinu ise wiwonu igbo tosan-toru ni, a si mo oniruuru iriri ti a maa n ba pade ninu igbo, eko lasan lawon ologun gba,o yato si abinibi, tijoba ba le sisẹ po pelu wa, eyin naa a ri i pe isinmi ati ifokanbale yoo ba wa kaakiri orilẹede yii.

"A ti setan lati ti awon agbofinro leyin lori ipese eto aabo fun emi ati dukia awọn araalu lati alẹ digba ti ile ba mọ, idi niyen ti a fi n ke si awon ijoba lati sedanilekoo fawon omo egbe wa lori ona eto aabo to ba ti aye ode oni mu.

"Lati le mu ki iee yii rorun fun wa, a nilo ọkọ nla to se e gbe wonu igbo kaakiri, ko sibi ti a ko le de ti ọkọ to dara ba ti wa, ko si si asiko ti a kẹẹfin awon odaran nibikibi ti a ko nii lo kiakia. READ MORE https://www.awikonko.com.ng/2019/01/awa-olode-setan-lati-koju-boko-haram.html

(1) (Reply)

‘french Spiderman’ Arrested After Scaling Manila Skyscraper / Woman Says She Don't Know Why She Did This / See Photo Of Man That Kills And Buries His Lover Over N.5M In Ogun

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.