Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,163,407 members, 7,853,799 topics. Date: Saturday, 08 June 2024 at 01:47 AM

Help Needed With Yoruba Proverbs - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Help Needed With Yoruba Proverbs (3374 Views)

Alaafin Of OYO With Yoruba Descendants In Brazil (pictures) / Your Favourite Yoruba Proverbs! / Igbos come show your proverbs skills (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Help Needed With Yoruba Proverbs by Xtfield(m): 7:33am On Feb 13, 2011
Please I need help with Yoruba proverbs. At least I need one proverb each that starts with the first letter of the Yoruba alphabet e.g

1. A - Aigbofa la n woke, ifa kan o si ni para
2. B - Bi owe bi owe ni a nlu ilu ogidigbo, ologbon nii joo, omoran nii moo
3. D - Didun lo dun ti a n ba ore jeko, tile oge to oge je F
4. E
5. E - Ehinkule lota wa ile ni aseni n gbe
6. F -
7. G - Gele o dun bi ka mo o we, ka mo o we ko dabi ko yeni
8. Gb - Gbogbo alangba lo d'anu dele, a ko mo eyi t'inu nrun
9. H
10. I - Ile oba t'o jo, ewa lo busi
11. J
12. K - kaka ki kiniun se akapo ekun, onikalulku a maa sode tire lotooto
13. L - Lala to lo oke, ile ni o n bo
14. M -
15. N -
16. O - Owe lesin oro, oro lesin owe, bi oro ba sonu, owe ni a fi nwa a
17. P - Palapala ki i se eran ajegbe
18. R -
19. S -
20. S
21. T - Teni ni teni; b'àpón sun'su, a bù f'ágùntàn rè
22. U
23. W
24. Y - Yiyo Ekun tojo ko
Please kelp me with anyone that you know of the ones that I cannot remember. I need this very urgently.
Thank you and God bless.
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by finek: 12:51am On Apr 15, 2011
A - A kii fá orí igún, ki a fá ti àkàlàmàgbò, ki o wa di orí àtíòro ki a ni ọbẹ kú.
B - Bi a kò ni nkan àgbà, bi èwe la nrí.
D - Dìdìnrìn kii ba'ni l'ágbà, kékeré lo ti nba ni lọ.
E - Ebi npa mi o ni ti pe a nwẹ ọṣẹ, ákáṣú ẹkọ l'oògùn rẹ.
Ẹ - Ẹni to fun abuké l'ẹwu wọ lo fun l'áyè a ti jó ijó àìkúrò l'ágbo.
F - Fúnrara ọkẹrẹ lo npe ọdẹ ninu igbo.
G - Gàmbàrì to ma dun oyè, a de Sábó.
GB - Gbogbo àlùwàlá ológbò, ko kọja ati k'ẹran jẹ
H - ?
I - Íná ti ko ba to'na ni i'tọ ìgbín lè pa, ti íná ba tó'ná, ìgbín a maa jona t'ìkaraun t'ìkaraun.
J - Jẹjẹ lo ma npe lọwọ ẹni, to ba ti ndi pàpápà, nkan mii lo ma nti ẹyin rẹ yọ.
K - Ki a ba olówó gbe ko ma f'owó mọ ni, o sàn ju ki a ba òtòṣì gbe ko tun maa ko ni l'ádìyẹ tà lọ.
L - Lekeleke to mba maalu nṣọrẹ ọna atijẹ lo nwa kaakiri.
M - Mọja mọsa ni ti akikanju, akikanju to ba mọọ ja ti ko mọọ sa, maa b'ogun lọ.
N - Nigbati kiniun ti nṣe ẹṣọ, ori igi l'ọbọ wa.
O - Òjò to pa àlapà lo sọ di oun àmúgùn fun ewurẹ.
Ọ - Ọba ran ni niṣẹ odo Ọba kun, iṣẹ Ọba ko ṣee kọ, odo Ọba re ko ṣe ki ori bọ.
P - Pashan ti a fi na iyale, o nbe l'oke aja fun iyawo.
R - Ríró àrá kii ṣe ẹgbẹ dundun ìbọn.
S - Sísè ni wọn nse awọ ko to le ka oju ílú.
Ṣ - Ṣágo nbu'gò, ẹlẹnu roboto méjì nbu ara wọn.
T - Ti èèrà ba fi'ni pe'gi, a nf'ọwọ wọ danu ni.
U - ?
W - Wèrè dun wò, ko ṣe bi l'ọmọ
Y - ?

@Xtfield, Hope you find these useful,
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by finek: 1:52pm On Apr 29, 2011
A - A kii fá orí igún, ki a fá ti àkàlàmàgbò, ki o wa di orí àtíòro ki a ni ọbẹ kú.
B - Bi a kò ni nkan àgbà, bi èwe la nrí.
D - Dìdìnrìn kii ba'ni l'ágbà, kékeré lo ti nba ni lọ.
E - Ebi npa mi o ni ti pe a nwẹ ọṣẹ, ákáṣú ẹkọ l'oògùn rẹ.
Ẹ - Ẹni to fun abuké l'ẹwu wọ lo fun l'áyè a ti jó ijó àìkúrò l'ágbo.
F - Fúnrara ọkẹrẹ lo npe ọdẹ ninu igbo.
G - Gàmbàrì to ma dun oyè, a de Sábó.
GB - Gbogbo àlùwàlá ológbò, ko kọja ati k'ẹran jẹ
H - ?
I - Íná ti ko ba to'na ni i'tọ ìgbín lè pa, ti íná ba tó'ná, ìgbín a maa jona t'ìkaraun t'ìkaraun.
J - Jẹjẹ lo ma npe lọwọ ẹni, to ba ti ndi pàpápà, nkan mii lo ma nti ẹyin rẹ yọ.
K - Ki a ba olówó gbe ko ma f'owó mọ ni, o sàn ju ki a ba òtòṣì gbe ko tun maa ko ni l'ádìyẹ tà lọ.
L - Lekeleke to mba maalu nṣọrẹ ọna atijẹ lo nwa kaakiri.
M - Mọja mọsa ni ti akikanju, akikanju to ba mọọ ja ti ko mọọ sa, maa b'ogun lọ.
N - Nigbati kiniun ti nṣe ẹṣọ, ori igi l'ọbọ wa.
O - Òjò to pa àlapà lo sọ di oun àmúgùn fun ewurẹ.
Ọ - Ọba ran ni niṣẹ odo Ọba kun, iṣẹ Ọba ko ṣee kọ, odo Ọba re ko ṣe ki ori bọ.
P - Pashan ti a fi na iyale, o nbe l'oke aja fun iyawo.
R - Ríró àrá kii ṣe ẹgbẹ dundun ìbọn.
S - Sísè ni wọn nse awọ ko to le ka oju ílú.
Ṣ - Ṣágo nbu'gò, ẹlẹnu roboto méjì nbu ara wọn.
T - Ti èèrà ba fi'ni pe'gi, a nf'ọwọ wọ danu ni.
U - ?
W - Wèrè dun wò, ko ṣe bi l'ọmọ
Y - ?

Hope you find these useful,
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by Seun(m): 11:09am On Dec 30, 2013
Bump. Which tools are you guys using to type the character accents?
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by ladionline: 1:02pm On Dec 30, 2013
Seun: Bump. Which tools are you guys using to type the character accents?
Oga seun, then say na 'device' o, na tolexander talk am. I gwanna step up to da plate too.
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by Tolexander: 2:01pm On Dec 30, 2013
ladionline: Oga seun, then say na 'device' o, na tolexander talk am. I gwanna step up to da plate too.
i meant the device you are using for posting. Nokia phone, bb phones etc. Nokia phones like xpressmusic is good for posting with grave and acute accent.
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by ladionline: 3:09pm On Dec 30, 2013
Tolexander: i meant the device you are using for posting. Nokia phone, bb phones etc. Nokia phones like xpressmusic is good for posting with grave and acute accent.
Yes I know thats what you mean. Just felt like invoking you on the post bruv.
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by StarFlux: 3:34pm On Dec 30, 2013
Sùúrù ni bàbá ìwà.
Oh, somehow missed S already being filled out.

Here's one with Y:
“Yan àkàrà fún mi wá ká jìjọ jẹ ẹ́”: àìtó èèyàn-án rán níṣẹ́ ní ńjẹ́ bẹ́ẹ̀.
Found it here: http://yoruba.unl.edu/yoruba-1.php.htm
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by ladionline: 5:24pm On Dec 30, 2013
Starbaba, thanks for the alt. Good work.
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by StarFlux: 7:58pm On Jan 01, 2014
ladionline: Starbaba, thanks for the alt. Good work.
Thanks! Very much appreciatedsmiley I'm on a computer. Apart from the accents which most phones should be able to produce, I think there's an app for Android to make the dots (Yoruba keyboard).

Ẹkú ọdún tuntun!
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by Tolexander: 10:18pm On Jan 01, 2014
ladionline: Yes I know thats what you mean. Just felt like invoking you on the post bruv.
lol grin
you aren't serious!
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by Tolexander: 10:24pm On Jan 01, 2014
A- a kì n fi okó nlá dérù ba arúgbó,
a kì í bánisùn kí á fani ní itan ya!
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by ladionline: 7:24am On Jan 02, 2014
^^Iyen laye atijo, owe yen ti yipada bayi o, o si ti di 'a kii deru oko nla b'obinrin', ore mi, o je lo obudeeti owe yen, agbonrin eshi lo shi nje l'obe. Awon mama ti senpe o, ehen. cheesy
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by ladionline: 7:29am On Jan 02, 2014
StarFlux: Thanks! Very much appreciatedsmiley I'm on a computer. Apart from the accents which most phones should be able to produce, I think there's an app for Android to make the dots (Yoruba keyboard).

Ẹkú ọdún tuntun!
Kabiesi o, aseyi samodun o, oro gbogbowa a dayo o. Oluwa aseun re fun gbogbo wa o, ami ase edumare.
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by StarFlux: 9:54pm On Jan 04, 2014
ladionline: Kabiesi o, aseyi samodun o, oro gbogbowa a dayo o. Oluwa aseun re fun gbogbo wa o, ami ase edumare.
Wà á gbó!
Re: Help Needed With Yoruba Proverbs by ladionline: 12:20am On Jan 05, 2014
StarFlux: Wà á gbó!
Ase wah ntireke. Aro aro mor.

(1) (Reply)

Most Populous Language In Nigeria apart from pigin and english / African Beads. / Okrika People Of Rivers Expose Boobs Of Their Ladies 2 Welcome Them 2 Womanhood

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 26
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.