Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,078 members, 7,835,635 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 12:47 PM

Ìkede Sí Gbogbo Omo Yoruba Nipa Kristi - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ìkede Sí Gbogbo Omo Yoruba Nipa Kristi (441 Views)

Oro Nipa Aferi / Oro Nipa Osole Owo Nla / Ebe Awon Agba Ti Eniyan Mafi Nri Aye Se Ni Irorun Lori Oun Gbogbo Taba Fe See (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ìkede Sí Gbogbo Omo Yoruba Nipa Kristi by Hoodrat(m): 11:19am On Nov 02, 2022
ÌKEDE SÍ GBOGBO OMO YORUBA NIPA KRISTI

Alaafia ni fun yin.

Awa ni ijo aparapò Israeli ninu Kristì (Israel United in Christ), Ijo onigbagbo ti a dale ni odun 2003 ni ìlu America. A fé gbe ihinrere otito Kristì kakiri agbaye si iran awa ti baba baba wa jiya isowo ęrú kíkó ati imunisìn, tí a npe ni colonisation.

Otito ni wipe: kí won to pè wa ni omo Afrika, tabi omo Naijiria, Israeli ni Oluwa pe wa. Sugbon ati igbati won ti ko wa l'ęrú, awon oyinbo onijoba ileto ti b’oju wa si iran awa omo Yoruba. Nítootó, awa gaan ni omo Israeli ninu bibeli tí won tuka si inu ilę Afrika, ti won si fon kaakiri agbaye n’igba òwò ęrú Atlantiki, ati Iha Sahara. Ituká s’inú awon ilu wòn yi sele gege bi gbogbo asotęlę awon woli n’inu bibeli mimo. Iwé òpòlopò miran si j’erí si otitó yí.

Ati pese awon aworan iyalenu melo kan fun yin, lati s’alaye otito iran ati ogún wa gege bi omo Israeli ninu Kristi. E fi ìbeere yin ransę si wa, ki e sì kàn si wa lati eyikeyi ero ibanisoro wonyi:

Facebook.com/IUICNigeria
YouTube: IUICNigeria

(1) (Reply)

#esuisnotsatan: The Significance And Misconception Of Esu, Walk Every 24th Of... / Yoruba Council Set To Host 6th World Omoluabi Festival / Pets Control Fumigation Services

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.