Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,161,588 members, 7,847,481 topics. Date: Saturday, 01 June 2024 at 06:23 PM

The Most Powerful Native Doctor In Nigerian - Business - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Business / The Most Powerful Native Doctor In Nigerian (107 Views)

Native Doctor Storms His Bank To Demand Access To His Money (pics/video) / Lady Invites A Native-Doctor To Fight Bank For Wrongly Debiting Her (Video) / Dangote Makes The List Of The 2018 Most Powerful People In The World - See Full (2) (3) (4)

(1) (Reply)

The Most Powerful Native Doctor In Nigerian by arisekola11111: 2:31pm On Mar 23
À kìí rí ìdí òkun
A kìí rí ìdí ọ̀sà
Ayé kò ní rí ìdí wa o
Nítorípé Ifá kan ló wí lọ́jọ́ Kínní wípé:
Olúkòbínú l'orúkọ tí à á pe Ifá
Ọlọ́mọ àjíyọ̀sínú ni orúkọ tí à á pe Odù
Òjíníkùtùkùtù-rẹ́rìnín-la-ìlú-já l'orúkọ tí à á pe oṣù para Òòyọ ló ní tí ẹ bá rí wa kí ẹ máa yọ́nú sí wa
Ẹ̀kúkú ló ní tí ẹ bá rí wa kí ẹ máa kó burúkú inú yín dànù
Nítorí ẹnìkan kìí fi oyin s'ẹnu sín'tọ́
Ìlú kìí gbá ara wọn jọ bá iyọ̀ ṣ'ọ̀tá
Ayé kò ní gbógun tì wa o
Gbogbo ohun tí a bá ńfẹ́ ní ti rere ni ayé yóò máa fẹ́ fún wa láṣẹ Èdùmàrè

Translation...
The secrets of the ocean remain a mystery
The secrets of the lagoon are unknowable
Humans will not discover your secrets
Because it is one Ifá verse that says:
Olúkòbínú (the Chief without malice) isthe name we call Ifá
Ọlọ́mọ àjíyọ̀sínú (a good hearted person) is the name we call Odù
Òjíníkùtùkùtù-rẹ́rìnín-la-ìlú-já (someone who wakes early in the morning smiling across the town) is the name we call oṣù para
It is Òòyọ who says if you see us,you should be happy with us
It is Ẹ̀kúkú who says if you see us, you should discard the evil in you
Because nobody holds honey in his mouth and spits in disgust
A whole town does not gather together and make enmity with the salt
People will not declare war on us People will not refuse our words
Whatever our wishes are, provided they are good will receive the blessings of the society by the power of Èdùmàrè - Àṣẹ
For more information you can call on this number+2348074260464
WhatsApp +2348074260464

(1) (Reply)

Learn How To Make 50k To 100k Daily / Gtbank Service Unavailability / How To Create Free International Tiktok Account In Nigeria

Viewing this topic: 1 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 15
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.