Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,155,393 members, 7,826,517 topics. Date: Monday, 13 May 2024 at 03:25 PM

Sisigbeborun N Ki Gbogbo Mumini Ati Mumina Ododo Ku Odun O - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Sisigbeborun N Ki Gbogbo Mumini Ati Mumina Ododo Ku Odun O (1133 Views)

Ebe Awon Agba Ti Eniyan Mafi Nri Aye Se Ni Irorun Lori Oun Gbogbo Taba Fe See / Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori / LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Sisigbeborun N Ki Gbogbo Mumini Ati Mumina Ododo Ku Odun O by SisiGbeborun(f): 9:03am On Sep 24, 2015
Won ni b'odun ba ba ni l'aye, ope lo ye ka maa da. Mo n fi asiko yi ki gbogbo awon omo iya wa ninu esin Islam ati paapa gbogbo ololufee SisiGbeborun ku odun oni o. Emi wa a se pupo re laye ati laaye wa. Adura mi ni wipe ki odun y'abo fun gbogbo wa, eyi ti oju wa de ti ri yi naa, ayo, idunnu ati ore-ofe Allah ni ka fi se, Amin! E ma wa gbagbe, ti e ba fe fi eran odun mi ranse, eyin e sa ti fi ranse si ori ero ayelujara wa - gbeborunsisi@gmail.com..(hehehe).
http://www.sisigbeborun.com/2015/09/sisigbeborun-n-ki-gbogbo-mumini-ati.html

(1) (Reply)

Nigerian Baby Names: 80 Unique (hand Picked) Igbo Names For Boys / The Unique Dance Step In Tiv Land / Africas Most Voluptous Women

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.