Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,160,409 members, 7,843,208 topics. Date: Tuesday, 28 May 2024 at 08:39 PM

O Ma Se O... Eya Ara Eeyan Ree Loju Titi L'abuja Yii - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / O Ma Se O... Eya Ara Eeyan Ree Loju Titi L'abuja Yii (1188 Views)

Ogun Ti Akoba Fe Ki Okunrin Tabi Obinrin Loju Miran Leyin Eni / Awon Ara Ti Mercy Aigbe Tun Da Ni Yii / O Ma Se O, Omiyale Ni Guusu Asia (2) (3) (4)

(1) (Reply)

O Ma Se O... Eya Ara Eeyan Ree Loju Titi L'abuja Yii by SisiGbeborun(f): 1:15pm On Oct 03, 2015
Ado oloro meji to bu gbamu ni'lu Abuja l'anaa ti se'ku pa opolopo awon eeyan ni agbegbe Nyanya ati Kuje, koda, se ni won n ri eya ara eeyan kaakiri oju popo. Ado oloro kan dun nigba ti omobinrin kan n gbee lo si ago olopa kan ni agbegbe Kuje, ti ado oloro onibeji imii si dun ni ibudoko Jikwoyi ni Nyanya, l'oju ona marose Abuja si Keffi.
http://www.sisigbeborun.com/2015/10/o-ma-se-o-eya-ara-eeyan-ree-loju-titi.html
Re: O Ma Se O... Eya Ara Eeyan Ree Loju Titi L'abuja Yii by Nobody: 1:56pm On Oct 03, 2015
ki edua gbawa lowo ekun apokoje bokoharam to npa kukuru to npa gigun ni le naijeria

(1) (Reply)

White People So Racist! / History Of The Yoruba Demon(s) / Protest Letter Against The Oluwo (emir) Of Iwo's Action. Cc All Yorubas

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.