Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,286 members, 7,818,980 topics. Date: Monday, 06 May 2024 at 09:18 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! - Culture (73) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! (171717 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (70) (71) (72) (73) (Reply) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 5:32pm On Nov 12, 2016
Justiceleague1:

ahhhh! Shebi mo sò tèlé. Mo mò pe orukò yi riliwanu.....haaahahahahaha.....
Ogagu Dafidi grin grin

Èèle,ooo, gbo gbo òmó ègbé..well orukò mi ni dafidi.. cheesy cheesy
mo kii gbogbo yii o...ka se ma dupè fun òlòhun fun Trumpu to ti di president ni ilu America. Gbogbo awa,afonja,inu awa dun.. grin

grin

Kinni anfaani towa fun awa omo oodua latari Turumpu to di Aare ilu Amerika? Koye mi o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 5:35pm On Nov 12, 2016
Ogagu Demola aka Demmzy15, a nreti yin nikale o angry grin

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Justiceleague1: 6:13pm On Nov 12, 2016
Rilwayne001:

Ogaagu Dafidi grin grin



grin

Kinni anfaani towa fun awa omo oodua latari Turumpu to di Aare ilu Amerika? Koye mi o

dont mind me o...its just my mischievous nature cheesy
Èèlè oooooo,gbo gbo ègbè òmó the great òduduwa cool grin

2 Likes 1 Share

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by scholes0(m): 6:31pm On Nov 12, 2016
haffaze777:
L'esi omo oluware iyi da iru eleyi l'asa?too Dede eyin ojogbon iyi wa Ni ikale ree mo kii.Emabinu pe ede egba re emi fi ki yin oooo,ba ra'se n se n'ile lisabi agbongbo akala,ololajulo oba rilwayne001 e wa ko ede egba

E jowo, e ja ki a lo Yoruba ajumolo, nitori wipe gbogbo wa ni ibi yii ko ni Egba omo Lisabi Agbongbo Akala.
Abi e fe ki emi naa bere si ni so Ede Ijebu mi ni? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Demmzy15(m): 7:50pm On Nov 12, 2016
Rilwayne001:
Ogaagu Demola aka Demmzy15, a nreti yin nikale o angry grin
Me no hear that one o!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 8:29pm On Nov 12, 2016
Demmzy15:
Me no hear that one o!

Se e gbo Yoruba ni? undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Demmzy15(m): 9:08pm On Nov 12, 2016
Rilwayne001:


Se e gbo Yoruba ni? undecided
Mo gbo o, shogbon eyi te so ti le ju! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 9:19pm On Nov 12, 2016
Demmzy15:
Mo gbo o, shogbon eyi te so ti le ju! grin

Rilwayne001:
Ogagu Demola aka Demmzy15, a nreti yin nikale o angry grin

Referring to this^: "General Demola aka demmzy15, we are expecting you on board"

Ki wa lo le nibe Yoruba yin ko munadoko rara angry

Bawo ni ile-iwe?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Demmzy15(m): 9:39pm On Nov 12, 2016
Rilwayne001:




Referring to this^: "General Demola aka demmzy15, we are expecting you on board"

Ki wa lo le nibe Yoruba yin ko munadoko rara angry

Bawo ni ile-iwe?

Egbon ile-iwe nlo dada o. I kon manage arawa ni o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 9:49pm On Nov 12, 2016
Demmzy15:
Egbon ile-iwe nlo dada o. I kon manage arawa ni o.

smiley wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Demmzy15(m): 9:59pm On Nov 12, 2016
Rilwayne001:


smiley wink
Eyin nko? Kilon happen, kilon sele?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by haffaze777(m): 10:10pm On Nov 12, 2016
scholes0:


E jowo, e ja ki a lo Yoruba ajumolo, nitori wipe gbogbo wa ni ibi yii ko ni Egba omo Lisabi Agbongbo Akala.
Abi e fe ki emi naa bere si ni so Ede Ijebu mi ni? grin

E ma binu eyin ojogbon,mo kan ni ki n jewo wipe egba ni mo ti wa ni,ede Yoruba dun pupo lati so,iwuri nla lo ma n je fun mi nigbati mo ba ranti wipe omo Yoruba ni mi.

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by haffaze777(m): 10:33pm On Nov 12, 2016
Rilwayne001:


grin grin

Ede Yoruba ponbele la n so ni ori tiredi eleyi. Ede egba yii le pupo, o yato gedegbe si Yoruba tiwa n'Ibadan. angry
gringrin Emi naa man mo kan ro wipe ki n lo wo nii boya oma je yin.oti wa da mi loju gbangba bayii wipe ko si ede ti ale fi we Yoruba ajumolo gbogbo waa

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by scholes0(m): 10:42pm On Nov 12, 2016
haffaze777:


E ma binu eyin ojogbon,mo kan ni ki n jewo wipe egba ni mo ti wa ni,ede Yoruba dun pupo lati so, iwuri nla lo ma n je fun mi nigbati mo ba ranti wipe omo Yoruba ni mi.

Ododo oro.
Aji se bi Yoruba laari, Iran Yoruba o je se bii ti baba nla enikeni.

Bawo ni igbadun ti Ipari ose?

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bree01: 2:46am On Nov 13, 2016
scholes0:


Ododo oro.
Aji se bi OYO laari, OYO o je se bii ti baba nla enikeni.


Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by scholes0(m): 5:24am On Nov 13, 2016
bree01:
...
Hahahaha, erin yn pa mi ni owuro yii.
Oyo ni tele tele, ni aye atijo, sugbon ni isisiyii, gbogbo eya meya ti o wa ni inu iran Yoruba ni o je ki Yoruba le fi owo sanya lonii.
Ni paapaa ju lo, awon Ijebu, awon Ekiti, awon Egba, ati awon Oyo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by haffaze777(m): 7:43am On Nov 13, 2016
scholes0:


Ododo oro.
Aji se bi Yoruba laari, Iran Yoruba o je se bii ti baba nla enikeni.

Bawo ni igbadun ti Ipari ose?


A dupe fun olodumare oga ogo,gbogbo nkan lo n lo Dede bi otile je wipe eto oro aje orile ede yii ko lo Dede,aye ope si nyo ninu oro wa.ka sa ma dupe fun olorun to n da emi wa si,bawo ni gbogbo Ijebu abi eyin na ti lo si oke okun?

2 Likes 1 Share

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 11:12am On Nov 13, 2016
Demmzy15:
Eyin nko? Kilon happen, kilon sele?

Ninu ose yi tabi eyi to n bo lagbara Olohun smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Demmzy15(m): 1:21pm On Nov 13, 2016
Rilwayne001:


Ninu ose yi tabi eyi to n bo lagbara Olohun smiley
Insha'Allahu, Olohun ma se fu yin.

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 1:35pm On Nov 13, 2016
Demmzy15:
Insha'Allahu, Olohun ma se fu yin.

Reading that and it sounds so Yoruba in my mind.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Demmzy15(m): 2:22pm On Nov 13, 2016
Contact17:


Reading that and it sounds so Yoruba in my mind.
Lol, that's why I put in the "u"

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by alphagate: 4:05am On Mar 21, 2017
Ẹ kú ohùn ọmọ kóòótù o jíire bí? Inú mi dùn láti sọ fún yín wípé ànfààní láti kọ èdè yorùbá nírọ̀rùn ti jáde. Mo ri wípé ó nira fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ láti kọ èdè yorùbá pẹ̀lú ẹ̀rọ ayára bí àṣá. Ìdí ni yi tí mo fi ṣe ohun tí a le fi máa kọ èdè wa (Yorùbá) ati Igbo ati Hausa. Ẹ lọ sí àdírèsì yii gazaliwakil.com.ng
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by delpee(f): 9:23pm On Mar 22, 2017
Eleyi dara pupo! Mo sese ri ibi to won ti nko ede Yoruba nikan lori NL ni.

alphagate:
Ẹ kú ohùn ọmọ kóòótù o jíire bí? Inú mi dùn láti sọ fún yín wípé ànfààní láti kọ èdè yorùbá nírọ̀rùn ti jáde. Mo ri wípé ó nira fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ láti kọ èdè yorùbá pẹ̀lú ẹ̀rọ ayára bí àṣá. Ìdí ni yi tí mo fi ṣe ohun tí a le fi máa kọ èdè wa (Yorùbá) ati Igbo ati Hausa. Ẹ lọ sí àdírèsì yii gazaliwakil.com.ng

Ise nla ni lati fi aami si oro pelu foonu abi taabu. E ku ise o!

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by alphagate: 9:52pm On May 17, 2017
delpee:
Eleyi dara pupo! Mo sese ri ibi to won ti nko ede Yoruba nikan lori NL ni.



Ise nla ni lati fi aami si oro pelu foonu abi taabu. E ku ise o!

Pẹ̀lú gazaliwakil.com.ng/yoruba ó ti di ìrọ̀rùn. Yálà lórí fóònù tàbí táàbù tí ó ní web browser.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by richylaw(m): 9:27pm On Jun 18, 2020
Lẹ́hìn bíí ọdún mẹ́tàlá tí fọ́ńrán èdè Yoruba yi ti bẹẹrẹ, mo ni ki n wa se ẹ n lẹ ní bẹ yẹn o. Mo ri wipe bo ti lẹ jẹ wípé gbogbo rẹ dákẹ́ mírín mírín, ìfẹ́ èdè ati àsà wa n bẹ l'ọ́kàn awon eniyan lọpọlọpọ. Bi o ba se e se, inu mi yio dun ki gbogbo wa tun pada wa si fọ́ńrán yi , ki a si mu dun bi o ti se ma n dun tele tele ri... Ire o

Baálè wink

2 Likes

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by N3cR0mAZc3R(m): 3:37pm On Jun 28, 2020
The Oluronbi Folklore

By: Bola Olalekan

Onikaluku jeje ewure (everyone promised to offer a goat)
Ewure, ewure (goat, goat)

Onikaluku jeje aguntan (everyone promised to offer a sheep)
Aguntan bolojo (A fleshy sheep)

Oluronbi jeje omo re (Oluronbi promised to offer her child)
Omo re apon bi epo (Her child who is as light skinned as palm oil)

Oluronbi O! (Oluronbi O!)
Jo’in jo’in (*make that up*)

Iroko (a mighty tree in the forest)
Jo’in jo’in (*make it up*)

Oluronbi O! (Oluronbi O!)
Jo’in jo’in

Iroko
Jo’in jo’in

1 Like 1 Share

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by GreatManBee: 1:32am On Aug 07, 2020
E ku ikale o.

Nn ora o. Nn okun o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Konquest: 2:43pm On Jan 15, 2021
dominique:
e kaasan awon eyan mi. se aran ya? smiley
Kilo de ni tori Olorun?... grin

Didn't know you are "Yoruboid" all this while Dominique.
I was searching for how to reach out to you easily when
I stumbled on this thread.





P.S. Dominique, I've been on Nairaland since 2005 when I was in my early
30s and I created a 2nd account in 2008 which I'm using here now.

I've NEVER been banned or labelled as derailing a thread before now.

What is the best the method of sending a complaint to you over a DEFAMATORY
and clearly malicious accusation that was made against me and which
was forwarde to you? Would that be via email or on NL?

This is to prevent anybody on NL from abusing the NL system by just making
false complaints to the Mods without the other person getting to defend
himself or herself.

Thanks and looking forward to your response, and hope this will be
resolved ASAP.

(1) (2) (3) ... (70) (71) (72) (73) (Reply)

Most Frequently Used Insult In Nigeria / Funny But Wise African Proverbs. / Efik/ibibio Names And Their Meaning

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 35
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.