Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,239 members, 7,849,867 topics. Date: Tuesday, 04 June 2024 at 10:55 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (162) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377385 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (159) (160) (161) (162) (163) (164) (165) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Jarus(m): 11:50am On Jan 22, 2009
Mo kan ni kintun yoju si yayin laaro yi ni o. Ekaaro oo. Enle nbeun o.

O digba o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Jarus(m): 11:54am On Jan 22, 2009
@goodass,
'Sulia kan, Ayetoro kan' je asa tuntun ti won da nisin. Nibi fiimu kan ti won pe ni Jenifa ni won gba were e
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 2:06pm On Jan 22, 2009
Jarus:

@goodass,
'Sulia kan, Ayetoro kan' je asa tuntun ti won da nisin. Nibi fiimu kan ti won pe ni Jenifa ni won gba were e

hehe. . . se film Funke Akindele yen? v.funi!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Jarus(m): 2:15pm On Jan 22, 2009
Moyola:

hehe. . . se film Funke Akindele yen? v.funi!
ehn
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 2:29pm On Jan 22, 2009
Mi ri advert e, o funni gann, really wana watch it! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:09pm On Jan 22, 2009
Moyola:

Mi ri advert e, o funni gann, really wana watch it! grin
Moyola:

hehe. . . se film Funke Akindele yen? v.funi!

Haba shocked shocked Lai tii fo foono, o ti npariwo pe o pani lerin. Iru obinrin wo ni tie naa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:12pm On Jan 22, 2009
Moyola:

hehe. . . se film Funke Akindele yen? v.funi!

Anti olodo, ewo ni ede geesi ti e nso ninu tireedi Yoruba E lo sora gan an o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:12pm On Jan 22, 2009
farotika:

Haba shocked shocked Lai tii fo foono, o ti npariwo pe o pani lerin. Iru obinrin wo ni tie naa

ejo, mi ondastand iyen o undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:15pm On Jan 22, 2009
farotika:

Anti olodo, ewo ni ede geesi ti e nso ninu tireedi Yoruba E lo sora gan an o.

Faruuk! bi Farotika de ni angry ilara e ti poju! ah ahn!! ma begi fun e o! undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:15pm On Jan 22, 2009
Moyola:

ejo, mi ondastand iyen o undecided

Fon-on-na ni yooba npe film

Lai ti wo fon-on-na grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:17pm On Jan 22, 2009
Moyola:

Faruuk! bi Farotika de ni angry ilara e ti poju! ah ahn!! ma begi fun e o! undecided

Begi fun tani shocked Igbagbe se o pe obinrin ni o, iwo o ni igi ti o le be fun mi o; emi ni mo le begi fun o ti o ba koja aye re grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:18pm On Jan 22, 2009
mahn!

nko mo o. . .  grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:21pm On Jan 22, 2009
Moyola:

ejo, mi ondastand iyen o undecided

Bo se ye ki o ko oro oke yi niyi: oye nkan ti e so yen o ye mi o.

Olodo nla tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:22pm On Jan 22, 2009
farotika:

Begi fun tani shocked Igbagbe se o pe obinrin ni o, iwo o ni igi ti o le be fun mi o; emi ni mo le begi fun o ti o ba koja aye re grin grin grin

Oti baje ju! angry
Aanu re den semi o!!. . . . tori tin ba mu e. . .uhmmn undecided maa fi kini e fun fere grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:25pm On Jan 22, 2009
farotika:

Bo se ye ki o ko oro oke yi niyi: oye nkan ti e so yen o ye mi o.

Olodo nla tongue

Kilon wori e gan?! O fe ma braggado. . . abi?! angry beta get uze tu reading dhat
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:27pm On Jan 22, 2009
Moyola:

Oti baje ju! angry
Aanu re den semi o!!. . . . tori tin ba mu e. . .uhmmn undecided maa fi kini e fun fere grin

Yeepa shocked shocked shocked Bi o ba je be, joo tete wa mu mi o Abi se ki nwa mu e ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:30pm On Jan 22, 2009
hehe. . . kini wo lo lero pe min so? shocked
Oti yama-yama ju! 'ma fi imu e fun fere' ni mo mean o grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 3:32pm On Jan 22, 2009
grin grin

Farotika ati Moyola. . .se ere ife ni e'nse ni biyii ni abi nkan imii?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:34pm On Jan 22, 2009
Jarus:

@goodass,
'Sulia kan, Ayetoro kan' je asa tuntun ti won da nisin. Nibi fiimu kan ti won pe ni Jenifa ni won gba were e

Booda Judas abi ndan Se fon-on-na ni won ni ki e maa fi gbogbo ojo aye yin wo ni. Eje jawo ninu iwa ibaje, ki e si wa ise kun ise apa yin.

"Sulia kan, Aiyetoro kan" embarassed Booda oniranu tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:36pm On Jan 22, 2009
Moyola:

hehe. . . kini wo lo lero pe min so? shocked
Oti yama-yama ju! 'ma fi imu e fun fere' ni mo mean o grin

Rara o sad Kini mi ni o gbudo fi fun fere o grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:37pm On Jan 22, 2009
debosky:

grin grin

Farotika ati Moyola. . .se ere ife ni e'nse ni biyii ni abi nkan imii?

Nkan imi ni o! emi o kin sere ife grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:38pm On Jan 22, 2009
farotika:

Rara o sad Kini mi ni o gbudo fi fun fere o grin grin

hehe! se dandan ni grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:45pm On Jan 22, 2009
debosky:

grin grin

Farotika ati Moyola. . .se ere ife ni e'nse ni biyii ni abi nkan imii?

Booda tibosky, ma-fi-lo-mi-n-da-si, ewo ni tiyin ndan Se o fe fe Moyola ni Ma tie daba e rara ti o ba fe ki n wole agbara fun o angry angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:48pm On Jan 22, 2009
lol! wo ile agbara. . . oun sogun ni? shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:51pm On Jan 22, 2009
Moyola:

hehe! se dandan ni grin

Beeni o. Tulasi si ni pelu grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:55pm On Jan 22, 2009
Moyola:

lol! wo ile agbara. . . oun sogun ni? shocked

Fi bobo yen sile joo angry angry Nkan ti agba fi jo omode lo, ko ni fi han, ti o ba fi han ko ni fi le lowo cool cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:56pm On Jan 22, 2009
farotika:

Beeni o. Tulasi si ni pelu grin

Lo ba Toyin angry

Mi o se nada! grin

farotika:

Fi bobo yen sile joo angry angry Nkan ti agba fi jo omode lo, ko ni fi han, ti o ba fi han ko ni fi le lowo cool cool

E rora! koyi le to yen tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Jarus(m): 5:04pm On Jan 22, 2009
@Moyola,
Yooba ni o ni abi Awusa? Nitoripe moka nibikan ti oso pe omo ilu Jalingo nio.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Jarus(m): 5:11pm On Jan 22, 2009
farotika:

Booda Judas abi ndan Se fon-on-na ni won ni ki e maa fi gbogbo ojo aye yin wo ni. Eje jawo ninu iwa ibaje, ki e si wa ise kun ise apa yin.

"Sulia kan, Aiyetoro kan" embarassed Booda oniranu tongue
Booda Farotika, eni a bu tele ni? Sugbon emi ko ni bu yin pada.
Emi ko kin wo fiimu rara. Koda, gbogbo fiimu ti monwo ninu odun kan ko to meta. Nigbati awon ara ibise mi npariwo fiimu jenifa ni emi na bani kinjasi. Nimobagba sidi naa lowo ore mi.
Boolu alafesegba ni emi man wo dada.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 5:16pm On Jan 22, 2009
moyola shocked shocked
ewo ni ere ori itage ti onse nibiyi
oya afara, kuro nibiyi
boooda farotika yen, asewo ponbele ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 6:55am On Jan 23, 2009
Moyola:

Lo ba Toyin angry

Mi o se nada! grin

E rora! koyi le to yen tongue

Wo, Moyola ori ikunle ni mo wa; jowo se temi. Mo fe fi da e loju loni pe mo ni agbara ati toju iwo ati Toyin leekan naa grin Mo si nfi asiko yi da e loju pe ko ni si ija laarin eyin mejeeji rara, nitoripe enikan ko ni di enikeji lowo grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:01am On Jan 23, 2009
Jarus:

Booda Farotika, eni a bu tele ni? Sugbon emi ko ni bu yin pada.
Emi ko kin wo fiimu rara. Koda, gbogbo fiimu ti monwo ninu odun kan ko to meta. Nigbati awon ara ibise mi npariwo fiimu jenifa ni emi na bani kinjasi. Nimobagba sidi naa lowo ore mi.
Boolu alafesegba ni emi man wo dada.

Se o ti wa don jasi bayi Ouch!!

(1) (2) (3) ... (159) (160) (161) (162) (163) (164) (165) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 44
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.