Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,160,550 members, 7,843,713 topics. Date: Wednesday, 29 May 2024 at 10:14 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (163) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377131 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (160) (161) (162) (163) (164) (165) (166) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:07am On Jan 23, 2009
tkb417:

moyola shocked shocked
ewo ni ere ori itage ti onse nibiyi
oya afara, kuro nibiyi
boooda farotika yen, asewo ponbele ni

Booda gbegele ati iborun, se won fi yin so Moyola ni ndan Abi ewo lo kan lemomu pelu itan aja O je lo maa sogba e, bi beeko, wa kan idin ninu iyo tongue Shio, ofuutu feete, aasa ti o ni koun angry

Kini itumo gbogbo oruko buruku ti o nso mi yen naa Se mo sewo de odo iyawo e ni ndan Abi o ti buru ju ti agbalagba bi temi ba ni iyawo meji ninu tireedi yi grin cool

Ka sora o cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 7:41am On Jan 23, 2009
Booda gbegele ati iborun, se won fi yin so Moyola ni ndan Abi ewo lo kan lemomu pelu itan aja O je lo maa sogba e, bi beeko, wa kan idin ninu iyo Shio, ofuutu feete, aasa ti o ni koun

Kini itumo gbogbo oruko buruku ti o nso mi yen naa Se mo sewo de odo iyawo e ni ndan Abi o ti buru ju ti agbalagba bi temi ba ni iyawo meji ninu tireedi yi

Ka sora o
agbedo!!
aburo temi ni Moyola, ko de le fe eni to ti ni aya nile
akin se ogun orogun ni idile tiwa. wa aya keji re siwaju
ole oloju kokoro. odoko ponbele
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bubblegum(f): 7:55am On Jan 23, 2009
e ka ro gbogbo yin. e jo ta ni o leko poem ife(luv) ni yoruba. poem ife ti o da gan. thanks
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 8:27am On Jan 23, 2009
e ka ro gbogbo yin. e jo ta ni o leko poem ife(luv) ni yoruba. poem ife ti o da gan. thanks
and what are u doing here? embarassed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by spikedcylinder: 11:07am On Jan 23, 2009
bubblegum:

e ka ro gbogbo yin. e jo ta ni o leko poem ife(luv) ni yoruba. poem ife ti o da gan. thanks

Tani aunty Dolapo fe ko poem ife fun bayi o? E tete so o! tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 11:48am On Jan 23, 2009
tkb417:

agbedo!!
aburo temi ni Moyola, ko de le fe eni to ti ni aya nile
akin se ogun orogun ni idile tiwa. wa aya keji re siwaju
ole oloju kokoro. odoko ponbele

Iwo o se fi Moyola sile ki o se nkan to ba wu. Je ki nso fun e, Moyola ko ni le je, be si ni ko ni lemu lai jepe o ri mi cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:07pm On Jan 23, 2009
tkb417:

and what are u doing here? embarassed

Ki ni itumo gbogbo ede geesi ti iwo nso nibiyi angry Ka sora o angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 12:30pm On Jan 23, 2009
Jarus:

@Moyola,
Yooba ni o ni abi Awusa? Nitoripe moka nibikan ti oso pe omo ilu Jalingo nio.

hehe. . . ati yooba ati awusa, gbogbo mo se grin

tkb417:

moyola shocked shocked
ewo ni ere ori itage ti onse nibiyi
oya afara, kuro nibiyi
boooda farotika yen, asewo ponbele ni

Egbon to shan! wink
emi naa ri pe acewo ni bobo yen. . . mo maama sora fun gidigani embarassed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 12:35pm On Jan 23, 2009
farotika:

Wo, Moyola ori ikunle ni mo wa; jowo se temi. Mo fe fi da e loju loni pe mo ni agbara ati toju iwo ati Toyin leekan naa grin Mo si nfi asiko yi da e loju pe ko ni si ija laarin eyin mejeeji rara, nitoripe enikan ko ni di enikeji lowo grin cheesy

For d fact pe o ko dispute pe oti ni iyawo sile, ma ba e so lero. smiley
Ese gan eku ife, broda Farotika olojukokoro grin. . . . fimisile, mi o se o! oti e saanu Toyin rara embarassed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:38pm On Jan 23, 2009
bubblegum:

e ka ro gbogbo yin. e jo ta ni o leko poem ife(luv) ni yoruba. poem ife ti o da gan. thanks

Ti o ba fe awon oro ife ti o wu ni lori, iwo sa ti kan si mi grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 12:42pm On Jan 23, 2009
farotika:

Ti o ba fe awon oro ife ti o wu ni lori, iwo sa ti kan si mi grin grin grin

Ha!! Ikoja aye shocked
Brooda otin tresspass! wala lon ba boyen o
Nitori Olorun, fi sista mi sile o! grin

bubblegum:

e ka ro gbogbo yin. e jo ta ni o leko poem ife(luv) ni yoruba. poem ife ti o da gan. thanks

Bawoni sista kiss
Poem Ife?!!! ma wori, e lo koh ni ede geesi, maa tun ko fun e ni yooba grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 1:39pm On Jan 23, 2009
Ti o ba fe awon oro ife ti o wu ni lori, iwo sa ti kan si mi

ajepe ojo iku ti fede fun yin niyen
ejo ka sora o angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 1:42pm On Jan 23, 2009
Egbon to shan!
emi naa ri pe acewo ni bobo yen. . . mo maama sora fun gidigani

aburo to wa alright!
shey o wapa? i trust u jare. oo ni problem temi basi wa ni landi yi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by spikedcylinder: 5:17pm On Jan 23, 2009
tkb417:

ajepe ojo iku ti fede fun yin niyen
ejo ka sora o angry

Broda! Se won ba yin wi ni? Abi ewo lo wan ja yin je bi pana pana ni sinyi? tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 7:44pm On Jan 23, 2009
Broda! Se won ba yin wi ni? Abi ewo lo wan ja yin je bi pana pana ni sinyi?
ah! ewo lokan ti e nibe
shey iwo ori wipe bobo yen fema ba bubblegum tage ni?
ko joo rara
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 7:45pm On Jan 23, 2009
shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bubblegum(f): 8:56pm On Jan 23, 2009
spikedcylinder:

Tani aunty Dolapo fe ko poem ife fun bayi o? E tete so o! tongue

mo fe ba oremi kan ko poem ife ni. se iwo le ko poem ife to da ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bubblegum(f): 9:00pm On Jan 23, 2009
Moyola:

Ha!! Ikoja aye shocked
Brooda otin tresspass! wala lon ba boyen o
Nitori Olorun, fi sista mi sile o! grin

Bawoni sista kiss
Poem Ife?!!! ma wori, e lo koh ni ede geesi, maa tun ko fun e ni yooba grin

mo wa okay o. mo dupe fun olorun. se iwo no wa okay. inu mi adun ti o ba le ko poem ife fun mi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:42am On Jan 26, 2009
Moyola:

Ha!! Ikoja aye shocked
Brooda otin tresspass! wala lon ba boyen o
Nitori Olorun, fi sista mi sile o! grin
Bawoni sista kiss
Poem Ife?!!! ma wori, e lo koh ni ede geesi, maa tun ko fun e ni yooba grin

Moyola temi nikan, se mi o le fe iwo ati egbon e ni tongue

Atipe se olodo ni e ni ti o fi le ke ewi ife ni ede yooba E gbo o, ti enikeni ba fi ede geesi soro ninu tireedi yi, kele a gbe o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:52am On Jan 26, 2009
tkb417:

ajepe ojo iku ti fede fun yin niyen
ejo ka sora o angry

Kini tie na iwo bobo yi, iwo lo tun kan e pelu eja tutu ti mo tun sese ri yi Se aburo e tun ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:53am On Jan 26, 2009
tkb417:

aburo to wa alright!
shey o wapa? i trust u jare. oo ni problem temi basi wa ni landi yi

Boya lo mo pe omode ni e, o o laya akeboje cool wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:57am On Jan 26, 2009
spikedcylinder:

Broda! Se won ba yin wi ni? Abi ewo lo wan ja yin je bi pana pana ni sinyi? tongue

Woo sinlinda, ma da bobo yen lohun jare, ko ni ise miran ju ko ma tele awon omo olomo kiri. Alaini ikan se, apa ati oniranu ni oruko re grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by spikedcylinder: 8:04am On Jan 26, 2009
farotika:

Woo sinlinda, ma da bobo yen lohun jare, ko ni ise miran ju ko ma tele awon omo olomo kiri. Alaini ikan se, apa ati oniranu ni oruko re grin cheesy

R'erin Sita! (LOL) grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:02am On Jan 26, 2009
bubblegum:

mo fe ba oremi kan ko poem ife ni. se iwo le ko poem ife to da ni?

ok je ki nfun e ni eleyi:

Orekelewa mi owon
abewa sola
lojo ti mo ti foju kan o
ni ewa re ti ndamilorun
mo ni teleyi o ba jaya eni
a saa jele eni grin grin
Orekelewa mi owon

Afunleyinju mi owon
se looto ni ife foju ni
nitori gborangandan ni oju mi la
sugbon ti nba ri e, mi o le  je
ti nba ri e, mi o le mu
jowo joruko mi, nitori o ba e lewe mu
Afunleyinju mi owon

Adumaradan mi owon
ofa ife ti o ta si mi
oti wo mi lokan to bee gee
ti nba ri e, aye a di porofo
iwo ni mo fe maa jiri
ni ojoojumo aye mi
adumaradan mi owon grin grin grin grin grin grin grin grin grin grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 10:36am On Jan 26, 2009
farotika:

Moyola temi nikan, se mi o le fe iwo ati egbon e ni tongue

lai lai!! se oti gbo nkan ti TKB so fun e? o le fe sista yen o! undecided
Likewise emi naa tongue

farotika:

Atipe se olodo ni e ni ti o fi le ke ewi ife ni ede yooba E gbo o, ti enikeni ba fi ede geesi soro ninu tireedi yi, kele a gbe o.

Emi o le salai ma fi ede geesi soro, nitorina e yonda emi nikan embarassed tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 11:38am On Jan 26, 2009
Moyola:

lai lai!! se oti gbo nkan ti TKB so fun e? o le fe sista yen o! undecided
Likewise emi naa tongue

Emi o le salai ma fi ede geesi soro, nitorina e yonda emi nikan embarassed tongue

Hmn, hm, aati seyi si ooooooo, je ka se bayi: ti o ba ti le se temi, mo maa yonda e grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 11:59am On Jan 26, 2009
eh ehn o! ma se bayi nau grin
kini option 2? angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 5:06pm On Jan 26, 2009
Moyola:

eh ehn o! ma se bayi nau grin
kini option 2? angry

O seni laanu pe ko si ona miran afi ti o ba gba fun mi grin cheesy

Moyola, mo setan lati fi gbogbo nkan ti o ba nfe te o lorun, iwo saa ti se te mi cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 5:19pm On Jan 26, 2009
O seni laanu pe ko si ona miran afi ti o ba gba fun mi

Moyola, mo setan lati fi gbogbo nkan ti o ba nfe te o lorun, iwo saa ti se te mi
ole oloju kokoro
Toyin nikan soso lati fi fun e, se ori gbogbo awon ti onfi oju ri yen, oju e lori won, ete e koleba won

jekin kawon fun e
Moyola-aburo mi atata, smurf, bubblegum
bowun e ko fidi jale, ko si ohun to masele

ole wombia tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 5:42pm On Jan 26, 2009
tkb417:

ole oloju kokoro
Toyin nikan soso lati fi fun e, se ori gbogbo awon ti onfi oju ri yen, oju e lori won, ete e koleba won

Eyi tumo si wipe Agbado inu igo ti di awomaju fun adie. [i][/i]
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 5:47pm On Jan 26, 2009
farotika:

ok je ki nfun e ni eleyi:

Orekelewa mi owon
abewa sola
lojo ti mo ti foju kan o
ni ewa re ti ndamilorun
mo ni teleyi o ba jaya eni
a saa jele eni grin grin
Orekelewa mi owon

Afunleyinju mi owon
se looto ni ife foju ni
nitori gborangandan ni oju mi la
sugbon ti nba ri e, mi o le  je
ti nba ri e, mi o le mu
jowo joruko mi, nitori o ba e lewe mu
Afunleyinju mi owon

Adumaradan mi owon
ofa ife ti o ta si mi
oti wo mi lokan to bee gee
ti nba ri e, aye a di porofo
iwo ni mo fe maa jiri
ni ojoojumo aye mi
adumaradan mi owon grin grin grin grin grin grin grin grin grin grin grin grin

farotika, e ku ise opolo. Emi ro wipe Agunleyinju ni dipo Afunleyinju se e le se alaye iyato boya yoruba egbe lemi gbo smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 11:22am On Jan 27, 2009
farotika:

O seni laanu pe ko si ona miran afi ti o ba gba fun mi grin cheesy

Moyola, mo setan lati fi gbogbo nkan ti o ba nfe te o lorun, iwo saa ti se te mi cool

Oun she mi, Farotika o de nshe mi. . . anipe mio se! tongue

(1) (2) (3) ... (160) (161) (162) (163) (164) (165) (166)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 45
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.