Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,180 members, 7,821,992 topics. Date: Thursday, 09 May 2024 at 12:01 AM

@adurabibeli_** - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / @adurabibeli_** (239 Views)

@adurabibeli_** Break The Curses And Send Back To The Sender / @adurabibeli_** / @adurabibeli_** (2) (3) (4)

(1) (Reply)

@adurabibeli_** by adurabibeli(m): 4:44pm On Jul 21, 2019
Nje iwo gbagbo pe Ojo Ola Re le dara ju Isaju re Lo..


Jobu 42:10. OLUWA si yi igbekun Jobu pada, nigbati o fun awọn ọrẹ rẹ̀: OLUWA si busi ohun gbogbo ti Jobu ni rí ni iṣẹpo meji.

Ma se woo gbogbo isoro re ti o dojuko tabi ti o dojuko o lowolowo, gba Olorun gbo , ma se tesi imoran enia sugbon tesi imoran Olorun ki osi ma se asoro ninu oro Olorun ti ise BIBELI, ki osi kun fun adura laisimi ati laise aree.


Jobu 42:12. Bẹ̃li OLUWA bukún igbẹhin Jobu jù iṣaju rẹ̀ lọ; o si ni ẹgba-meje agutan, ẹgba-mẹta ibakasiẹ, ati ẹgbẹrun ajaga ọda-malu, ati ẹgbẹrun abo kẹtẹkẹtẹ.

*Olorun adani magbegbe atu ori eni ti kosuwon se ti o ri idojuko ati ilakoja re tori wahala re, aini re, iponju re odamiloju ti iwo ba gba gbo iwo yio ri ogo OLORUN , EMIMIMO dide ninu anu re mu igba rere de ba oluka adura yi ati idile re.*AMIN

*Mo gba adura fun o Olorun to de ba Jobu lalejo to mu ki igbehin re daraju ti isaju re lo loni gangan bi oti ka adura yii Itan aye re, idile re, ise re, ti awon omo re ki iyipada ko de ba.AMIN .

Emimimo ko de ba o lalejo loni lati mu igba re , igbehin re ko dara ju isaju re lo loruko JESU ..AMIN .**


#ALMIGHTYGOD #JESUSCHRIST #JESU #BIBLE #BIBELI #EMIMIMO.

(1) (Reply)

Who Is Jesus? - Jesus Is The Firstborn Of All Creation / Is Mormonism Christian? / Pope Francis Changes The 'our Father' Prayer.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.