Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,136 members, 7,821,877 topics. Date: Wednesday, 08 May 2024 at 08:48 PM

@adurabibeli_** - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / @adurabibeli_** (247 Views)

@adurabibeli_** Break The Curses And Send Back To The Sender / @adurabibeli_** / @adurabibeli_** (2) (3) (4)

(1) (Reply)

@adurabibeli_** by adurabibeli(m): 4:55pm On Jul 21, 2019
Koko.. OLORUN FI ANU ATI AGBARA RE BE MI WO.

Luke 7:16 Ẹ̀rù si ba gbogbo wọn: nwọn si nyìn Ọlọrun logo, wipe, Woli nla dide ninu wa; ati pe, (Ọlọrun si wa ibẹ̀ awọn enia rẹ̀ wo )

Ti Oba ka Luku 7:11-16 wa ri wipe Jesu se ibewo si Naini, ibewo lo yi ekun ati ibanuje opo Naini di erin ayo ati idunu..

Olorun Akiri se ore le seju be lo fun o .

* Johannu 14:13 - Ohunkohun ti enyin ba si bere li Oruko mi oun naa li emi o se, ki a le yin Baba logo ninu ninu Omo.

*Johannu 11:40 Jesu wi fun pee, Emi ko ti wi fun o pe, bi iwo ba gbagbo, iwo o ri ogo Olorun?

Olorun be Abraham wo osi fun ni Isaak. Gen 18:1-14, Gen 21:1-3.


Olorun be Obed-Edomu wo nipase apoti Eri Osi yi itan re pada larin Osu Meta. 1 kronika 13:14.

Olorun be Opo Naini wo oyi ibanuje re , ekun re osi so di ayo ati erin.. Luku 7:11-17.

Gbadura yi pelu gbobo Agbara re ati Igbagbo re.

1. Dupe Lowo Olorun pe o ka o mo awon alaye enia to wa lorile alaye loni.

2. Dupe lowo Olorun to pa o mo ti yio si ma pa o mo si iwo ati ebi re.

3. Dupe lowo Olorun fun alafia ,dupe fun rije ati riri mu,riri na ati riri lo.

4. Oluwa Olore-ofe gbogbo ese mi niwaju re fi anu darijimi, ese iran mi, ebi mi, ti awon omo mi fi anu re dariji ki ofi anu ati EJE re pa aisedede mi ati ti ebi to be ni waju re re .

5. Olorun mi o anu ti awon ti igbani ri lodo re to fi be won wo lati fi opin si isoro won, ibanuje okan won jeki ri anu na gba loni.

6. Emimimo sanu fun mi ko be emi ati idile wo fun iyipada ti aye yio fi ti ara mi yin o.

7.Olorun aanu Ile mi se aisan, aye mi saisan, ise mi se aisan be mi wo pelu aanu re ki ri igbala fun iwosan .

8.Olorun aanu be aye mi wo, be idle mi wo, be ise mi wo ki o so gbogbo ohun ti oti woo di tito.

9.Olorun Eledumare so egan aye mi, idle mi, ebi mi, egan awon omo mi ,egan ise mi yipada ko so di Ogo ti aye yo ma wari fun .

Olorun Ibewo Olorun Emi Awon Woli yio gbo ebe adura re yio sii bewo pelu anu ati agbara re Loruko JESU KRISTI OLUWA WA. AMIN AMIN AMIN.

Fi Adura yii sowo si awon ore re.. Adura re tigba... Amin.

Oluwa a mu wa dele loruko Jesu Kristi. Amin

#ALMIGHTYGOD #JESUSCHRIST #JESU #BIBLE #BIBELI #EMIMIMO.

(1) (Reply)

Before You Sleep, Meditate And Pray With This / 'fake Jesus' Dies A Few Days After Visiting Kenya / Iran Lured El-zakzaky Into Shiite With Money – Islamic Movement Leader’s Brother

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 13
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.