Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,231 members, 7,818,781 topics. Date: Monday, 06 May 2024 at 03:00 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! - Culture (8) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! (171703 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (73) (Reply) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 1:51pm On Dec 23, 2009
@ everyone
SE E GBORO IFELEKE SHA!,, ABI AWON EFCC TI GBEE NI, LOL wink grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 8:25pm On Dec 23, 2009
adolfe bad:

Eyin omo yoruba gbogbo bawo le se n prepare fun kristmas? E se jeje o

Omo Hausa, lol, daadaa l'awa omo Yoruba wa o, Odun ti ndun sugbon ti awon ara wa ni ile ifowopamo ti ise nbo lowo won yii da bi nkan ooo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dominique(f): 10:47pm On Dec 23, 2009
Remii:

Omo Hausa, lol, daadaa l'awa omo Yoruba wa o, Odun ti ndun sugbon ti awon ara wa ni ile ifowopamo ti ise nbo lowo won yii da bi nkan ooo.

omase o! sad
Olorun yo o pese ise gidi fun gbogbo won ni odun tun tun.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 5:16pm On Dec 25, 2009
Could some translate this to English for me? : Gambari nta nanma, eran nta eran.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 5:48pm On Dec 25, 2009
[size=18pt]~*~*EKU ODUN KERESIMESI~*~*[/size]
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 5:48pm On Dec 25, 2009
Orilee9ice:

@ everyone
SE E GBORO IFELEKE SHA!,, ABI AWON EFCC TI GBEE NI, LOL wink grin grin


i WAS WONDERING ABOUT HIM too. Hope he's okay sha
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 6:08pm On Dec 25, 2009
Orilee9ice:

@ everyone
SE E GBORO IFELEKE SHA!,, ABI AWON EFCC TI GBEE NI, LOL wink grin grin

E beere re lowo tubabie, a dabi eni wipe won mo ara won tayo NLand, lol
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dominique(f): 7:00pm On Dec 25, 2009
Remii:

Could some translate this to English for me? : Gambari nta nanma, eran nta eran.

gambari nt mamma nko nse ede yoruba, hausa ni. means mola is selling meat

~~~EKU ODUN KERESIMESI GBOGBO OMO LEYIN KIRISTI NI NAIRALAND. . .ODUN A YABOOOOO!!! smiley cheesy~~~
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FayeZik(f): 2:23am On Dec 26, 2009
Remii:

Could some translate this to English for me? : Gambari nta nanma, eran nta eran.

Remii
Tin ba translate oro re si ede oyinbo, ti enikan ba bu mi, ki o ya gbeja mi o.
Gambari nta nanma, eran nta eran means 'Gambara is selling smoked meat, animal is selling animal'
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 9:03am On Jan 01, 2010
^^^^ @fayesik, mimi kan ko si. O see gan an, mo lero wipe maalu lonje nanma, I know better now, Thanks a lot.

Happy New Year to all.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FBS: 11:54am On Jan 01, 2010
Gbogbo ile, eku odun titun yi o! Oluwa Olorun Oba A dawa si o! cheesy

@Orile9ice, oremi ataata! Bawo ni le? awon temi nko? se gbogbo e n'dun? how was the New Year parriy? cheesy
Iya mi ti de si ibi bayi, won de ti ri omo'mo won. Adupe ni owo Baba l'oke!

E jowo eyin eniyan. . .Ifeleke nko?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by biina: 6:54pm On Jan 01, 2010
E ku odun, e ku iye'dun, odun titun yii a y'abo fun gbogbo wa. Iwo yi emi, a tun parapo wa yo ni.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 6:57pm On Jan 01, 2010
happy new year, my lovely people kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tubabie(f): 12:59am On Jan 02, 2010
Eyin eeyan mi , aku alaja odun, emi wa a se opo e lagbara Olorun. Eku igbadun, ekaabo si inu odun isimi yii grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FayeZik(f): 3:26am On Jan 02, 2010
Eku alaja odun o, eyin temi ni NL. 2010 a yabo fun gbogbo wao. Idunnu ati ayo ni a o fi lo odun na ja. ire ati aanu oluwa yo ma wa pelu gbogbo wa ati awon ara ile wa o (amin).

Hmmmm! a si ku ti omo Nigeria ti o fe so wa loruko. Nigeria ko ni baje o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by geogentle: 11:40am On Jan 02, 2010
Eyin omo Oduduwa, mo ki gbogbo yin lookokan. Alale ile yoruba yio gbe gbogbo wa o. A si ku odun, a ku alaja odun. Emi wa a se pupo re. Lola Eleduwa gbogbo ire ti o to si wa ninu odun yii ko ni fo wa. Oba kabikabi ode orun a ka gbogbo ibi kuro ni ona wa gbogbo. ire ow, ire omo, alekun anfani ati alafia ti nse bale oro ni Eleduwa a fi te wa lorun ninu odun titun yi. Odun yi a se wa so'wo, a se wa s'mo. Alakoba o ni ko ba wa, gbaya gbaya ko ni gba aya wa, gbomo gbomo ko ni gbe wa lomo, gboko gboko ko ni ya lo de wa. Ire o, ire gbangba,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 11:54am On Jan 02, 2010
tubabie:

Eyin eeyan mi , aku alaja odun, emi wa a se opo e lagbara Olorun. Eku igbadun, ekaabo si inu odun isimi yii grin

tubabie, ni bo loo fi Ifeleke sii? or are you not your brother's keeper? grin grin grin

FayeZik:

Eku alaja odun o, eyin temi ni NL. 2010 a yabo fun gbogbo wao. Idunnu ati ayo ni a o fi lo odun na ja. ire ati aanu oluwa yo ma wa pelu gbogbo wa ati awon ara ile wa o (amin).

Hmmmm! a si ku ti omo Nigeria ti o fe so wa loruko. Nigeria ko ni baje o.

Fun gba die naa ni, adun ni yoo gbeyin ewuro lagbara Olorun. Aa kuku yee. Nkan maa pada bo si po laipe.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tubabie(f): 1:57pm On Jan 02, 2010
Remii:

tubabie, ni bo loo fi Ifeleke sii? or are you not your brother's keeper? grin grin grin


Ifeleke ke? cheesy Mo ni ro pe o n gbadun odun pelu awon ara ile e.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by IYANGBALI: 2:56pm On Jan 02, 2010
awon ti won ma ntu brassiere ni NL ti fi ifeleke ifelepon pamo sinu bra won, o wa nibe to nmi hele hele grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by ifyalways(f): 3:36pm On Jan 02, 2010
Eku odu gbogbo Omo Oduduwa.
@FL gators ati Toyosi,wishing u a beautiful and stress-free 2010.Alafia front,back,right and left kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by skfa1: 3:37pm On Jan 02, 2010
Eyin temi ni abule, ki lon she le men grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 6:41am On Jan 03, 2010
ifyalways:

Eku odu gbogbo Omo Oduduwa.
@FL gators ati Toyosi,wishing u a beautiful and stress-free 2010.Alafia front,back,right and left  kiss

I meela. smiley
Takia ma dear, the best for you this year kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 12:14pm On Jan 04, 2010
EYIN Ore mi GBOGBO, FBS, TUBABIE, CHOMATEX, OLUSENCHO, IFELEKE.A.B.B.L Happi new year oh!
Mo korin fun gbogbo wa pe, (going down memory lane, The Good Women Choir led by Mrs Fashoyin in Ibadan ile)

Odun yi a yabo ko ni le koko mo wa, odun yi a yabo ko ni le koko mo wa
Ohun ti a dawo le, A YORI, Ohun ti a bere lo'luwa yo see, Odun yi a yabo ko ni le koko mo wa
Olorun o seun to'dun to ko ja, (a.b.b.l) someone can complete this part 4me as i cant seem to remember this part of the Good women Choir song)
Eni ko yi bi, e maa banu je, edumare ti segun a se danu
Olowo a maa ri se, Onisegun a bo'de pade
Ayun lo, a yun bo lo'wo ye nu, Amin!
Odun a yabo fun wa. Amin, Odun a yabo fun wa ase!!,

@FBS, Eku afojuba Mumsie o! se otutu o mu won ju sha? e maa Flenjor lo oh! 9ice one!

THIS IS OUR YEAR TO SHINE IJN! AMEN! wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 12:20pm On Jan 04, 2010
H
mmmm! a si ku ti omo Nigeria ti o fe so wa loruko. Nigeria ko ni baje o.
@fAYEZIK
Hummmmmmmmm my sistha, abi o, o fe so waa lenu but olorun o ni fun see, waa woo bi won sen check wa in airport this last week, especially ti o ba ti ni pali abi oruko 9ja, Olorun ti segun sha! 9ja o ni baje o!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FayeZik(f): 7:52pm On Jan 05, 2010
Emi ti nreti pe ti nba ma lo si 9ja laipe, ao ma se pap smear ni airport ni. Olorun sa ko wa yo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 7:40pm On Jan 09, 2010
[img]http://www.wired-and-inspired.ca/EDEL435/process/storytelling.jpg[/img]

Ebe fon l'abata
E yo obe, yo aake ti
omi ni e ro pe omu ku ni

******************************************

Ogun logbon eniyan ni ko mo epile si owe yoruba
nitori idi yi
mi o si so ipinle owe yi


**********************************************************

Ni odun gbere!!
Akoni olode nkan nbe
Oguniyi ni nje
Ode aperin ni Oguniyi
Osi ti di opolopo igun

Ni irole ojokan
ti Oguniyi dege gege bi asa re
Oguniyi kan eranko nla kan - EFON
Oguniyi luko
Ohun ati Ibon owo re,
ni nwa yo kele kele ti ofi sunmo efon na
afi KEM!!!!!!!!!!!!!!!!!!
ni o ba yin Ibon owo re

Efon ke rora!!!!!
ni dagbo ru, ni da gbogbo e ru
afi fia fia fia, ni ma ja lo
kia Oguniyi ti gba te le
Ni to pa se e lo

Nigbati efon de abata kan
Afi gburu!!!!!!!!!!
O wo lu le, osi gbe emi mi
Awon ara abata yi
Won ba ko ra jo
Eni mu obe mu obe, eni mu aake mu aake
Afi kia, won lo re bu efon

Aipe re ni Oguniyi yo lehin wan
ni oba wipe haaaaaaaaaaaaaaaaaaa!
Ebe fon l'abata
E yo obe, yo aake ti
omi ni e ro pe omu ku ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by segoye2(m): 8:49pm On Jan 09, 2010
Dear All,

You can now write for free on Media Lens Africa (www.medialensafrica.com)

They currently look for writers/reporters/contributors/editors etc, send your articles to hotnews@medialensafrica.com our segoye4@gmail.com

You stand a chance to secure an access as a contributor on the website after a long tested walking of sending in articles.

Log on to the website and see how you can use it to read the entire world.

Media Lens Africa gives all news without exception.

Regards,

Media Lens Africa website Administrator.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FayeZik(f): 3:48am On Jan 10, 2010
@ faakay

Emi lero wipe 'e ba efon l'abata' ni won wi ni. Se 'abasa' ni tabi 'abata'? Ati wipe kinni nje bee?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 4:29am On Jan 10, 2010
FayeZik:

@ faakay

Emi lero wipe 'e ba efon l'abata' ni won wi ni. Se 'abasa' ni tabi 'abata'? Ati wipe kinni nje bee?

thanks for the correction. mo ma make atunse
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by blandyne(f): 10:45pm On Jan 11, 2010
Sorry for derailing this thread but i really need someone to translate this for me : [b] MI O MO YEN[/b]





I posted it in the translation thread, unfortunately no one reply to me. Thanks.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tubabie(f): 11:05pm On Jan 11, 2010
MI O MO YEN = I don't know that
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by IYANGBALI: 8:20pm On Jan 12, 2010
blandyne:

Sorry for derailing this thread but i really need someone to translate this for me : [b] MI O MO YEN[/b]





I posted it in the translation thread, unfortunately no one reply to me. Thanks.



it means come make we fok

(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (73) (Reply)

Most Frequently Used Insult In Nigeria / Funny But Wise African Proverbs. / Efik/ibibio Names And Their Meaning

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 39
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.