Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,476 members, 7,816,122 topics. Date: Friday, 03 May 2024 at 05:48 AM

Ogun Awon Bàba Wa - Culture (4) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Awon Bàba Wa (326260 Views)

Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai / Asiri Ogun Awon Baba Wa (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply) (Go Down)

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Zalam5: 1:29pm On Feb 25, 2016
E jor sir se ama gun adiye yen nin aaye ni abi bawo
??[color=#990000][/color]
Re: Ogun Awon Bàba Wa by tayooluwole: 2:55pm On Feb 25, 2016
[quote author=ayokomi1010 post=40681283]moki gbogbo omo Yoruba mosi ikanni yi fun afani opolopo omo odudua fun Ogun nla Awon baba wa ni ile karo ojire ti o ti sonu ti Ati sodi ohun igbagbe ti awon alawo funfun si fi etan ati owo gba kuro lowo wa,esin o sope ka ma se ASA ibile wa o,omo Yoruba eje karonu o,Ikilo mi o fi aiye gba enikeni lori ikanni yi fun oro ti koye omo Yoruba tabi ebu iwa ibaje fifi ago ibanisoro sori afefe,atipe oun gbogbo tabafe ko si ori afefe komu ogbon dani kosi wulo fun Awon eniyan ki o si ma pawonlara odua agbe wa o[/quote

Eku ise ooo Baba, yi o maa ju yin she oooo, agba yin akale... E jowo, OGUN IKIYA nko
Re: Ogun Awon Bàba Wa by tayooluwole: 3:14pm On Feb 25, 2016
ayokomi1010:
moki gbogbo omo Yoruba mosi ikanni yi fun afani opolopo omo odudua fun Ogun nla Awon baba wa ni ile karo ojire ti o ti sonu ti Ati sodi ohun igbagbe ti awon alawo funfun si fi etan ati owo gba kuro lowo wa,esin o sope ka ma se ASA ibile wa o,omo Yoruba eje karonu o,Ikilo mi o fi aiye gba enikeni lori ikanni yi fun oro ti koye omo Yoruba tabi ebu iwa ibaje fifi ago ibanisoro sori afefe,atipe oun gbogbo tabafe ko si ori afefe komu ogbon dani kosi wulo fun Awon eniyan ki o si ma pawonlara odua agbe wa o

Baba, eku ise, agbayin adale... Baba e jowo, OGUN IKIYA TO DAJU nko
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:40pm On Feb 26, 2016
e kule o gbogbo omo odudua mo se ise awo losi orilede BENIN, ni koje ki e ri mi lori ikanni yi lati bi ojo meta,sugbon ope fun olorun molo layo mobo layo motun ba eyin na layo eledumare Seun
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:55pm On Feb 26, 2016
OSOLE
eye igun toni ifun ninu eyokan,okete oojo tutu kan,odidi atare kan,ata ijosin Kongo kan,ewe lapalapa funfun to resile 101,ao jo po ao fi ori po,ao mabu diedie laro laro ao mafi eko gbigbona lo

2 Likes

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 3:09am On Feb 29, 2016
Ekaabo Alagba Ayokomi ekuise Eledua omaa ranyinse eosinii saseti lagbara Olorun.
Ejowo se ise osole yi ko leyin (repercussion)
Re: Ogun Awon Bàba Wa by akingbemi(m): 3:25pm On Feb 29, 2016
ojukoro:
Ogun Isoye.Ewe oniyemiye,eye awoko,iwe newspaper ti ko ni aworan pupo, Igbo die, ao jo po, ao ma bu diedie si oyin igan.lila ni idaji.o da gaaaaaaa
ese
Re: Ogun Awon Bàba Wa by akingbemi(m): 3:30pm On Feb 29, 2016
[quote author=akingbemi post=43359254] ese[/quot
ejo e funmi no Ogun ifunra
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Ayomidegbenga1(m): 1:46pm On Mar 01, 2016
Baba e fun wa ni ogun ikiya
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Zalam5: 1:51pm On Mar 01, 2016
marv006:


Iba Eyin agba o. Se ao fi aso funfun ti a ko ose ko si oke ni, abi a le fi si ibi to ba wuwa.
Ejo oruko miwo ni atun lepe ,,,,odu ori ewe ahunekun?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 1:30am On Mar 04, 2016
ALIUDAVID:
EYONU AWON AGBA ATI APAMOWO OWO..
Ikoide meta,
Alanbere meta,
Odidin atare meta,
Ao jo won po, ao fi sin gbere yii orun owo wa mejeeji, ao po eyi ti o ku mo ose dudu ao ma fi we...

OGUN ATUDE TODAJU...
Ewe tude,
Egbo tude,
Odindin atare,
Ao jo po, ao lo kuna dada ao ma fi epo pupa lo.

Iba eyin agbagba iba eyin to laye..
ejowo se oloyunnbere todabi alangba ni enso ni tabi ambere (kini pelebe kekeke bayi tomaankoro)
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 1:41am On Mar 04, 2016
ayokomi1010:
OSOLE OWO
Okan maalu ti ko wo omi,omudun ewe akoko 101,pati omonigedegede,epo jebo,ao lo awon ewe yi,ao ge okan maalu yan si 16,ao se pelu epo iyo,ati ata ijosi,ti o ba tutu,ao da sinu Awo funfun,ao wo aso to dara,ao joko si aye to dara,ao pe Ohun re si,ao wa je obe na,
Ohunre:- igbe nla ni eran nla ke,e ma GBE owo nla wa fun mi,enikan kiridi omonigedegede o,ki e wa Fi owo nla bemi nise loni. ao ma je obe na diedie fun ojo merin tabi marun,osise gan ni o
ejowo baba se akoniikuro lojukan naa tabi ki alosi ibiise titi ojomerin tabi marun taofije obe yentan.
Se aomaa gbeelena (warm) e lojoojumo. Eseun pupo mo nreti esi yin.

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 1:51am On Mar 04, 2016
08101646045atwp:
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ajuwase'o
ejowo tani eyin? Se babalawo niyin? Bawoni asele kan sii yim?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Lero70: 2:06am On Mar 04, 2016
ayokomi1010:
enikeni ti o ba ni oro ida konko lati bami so Ki o kan simi lori (prophet.nase.Solomon10@gmail.com) tabi whatsapp 08135072961 tabi 07087811181,abanise a ba wa se tiwa o amin
ejowo baba efunwa ni e-mail yin mii nitoripe motigbiyanju eleyi leemeji tiwonnsope kowa recognized. Phone temi kosigba whatsapp Esee
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ALIUDAVID: 2:19pm On Mar 04, 2016
Lero70:

ejowo se oloyunnbere todabi alangba ni enso ni tabi ambere (kini pelebe kekeke bayi tomaankoro)


Bee ni

alanbere ni won saba ma n pe, won tun pe ni oloyunbere n aa
Re: Ogun Awon Bàba Wa by kuddus: 9:07pm On Mar 06, 2016
ejo sir efun wa ni aluwo todaju
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 3:54pm On Mar 31, 2016
ogun Awon baba wa on wathsapp group, 08135072961

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by ECadmin: 8:03pm On Apr 02, 2016
nje a ti ri enikeni to confam (confirm) ise baba yi? ki iru eni bee so fun wa. ki a le Ni iwuri die. E shey o.

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by taofeekjimoh: 9:55pm On Apr 18, 2016
E jowo baba,ewe amaa je o,e seun gan,Oloiun a bawa dupe fun yin o.E jowo se lale lamaa fi foko mu,abi laraaro.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by BermudaTriangle(m): 4:36am On Apr 21, 2016
Ejowo sir, ogun AKOJEDI ati IDAKOLE to daju nko. Ese.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ladycomfort(f): 2:57pm On Apr 21, 2016
orunmila76:
Oogun Eyonu to daju

Eyin adiye sise kan, iyo die.aa da iyo yen sinu plate ,waa te Odu iwori meji si,waa fi eyin adiye naa lee Lori, waa gbe sinu orun di 12pm,waa lo gbe kuro ninu orun by 12pm,waa Bo ara e si ihoho ,waa gbadura,waa Bo eyin naa wa fi kan iyo naa,waa je eyin naa lodidi. Waa da iyo naa sinu omi fun wiwe.
. E jowo mofe bere nkan lowo yin lori ise yi. Bawo ni ma se te odu iwori meji is inu iyo naa. Ati wipe kini eniyan le se lati gba owo ti eniyan ba je(debt payment) nitori awon kan je mi ni owo won is fe san.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ladycomfort(f): 3:22pm On Apr 21, 2016
ayokomi1010:
OGUN EYONU TI A MALO LO SI ODE TAFI GBA IYIN NI BE
ao fi epo pupa te ejiogbe si atelewo alafia,ao tun fi omi na te pelu iyo isebe,ao wa pe ohun yi si ao wa la,ao fi owo iyoku sa ori,kama lo sode na ao gba iyin nibe, ohun re:amo roro loruko ti won pe iwo epo,amayegun loruko ti won pe iwo omi,amuludun loruko ti won pe iwo iyo,omi kiti laye o,ejiogbe kiti lawujo ifa,ki emi lagbaja omo lagbaja gba iyin nibi gbogbo loni o.
ejiogbe
! !
! !
! !
! !
ogun yi dara gan ni o asegbayin la o ma se o ni ojojumo aye wa ao ni te lase edunmare
. Baba e jowo e se alaye oro yi fun mi ( ao fi owo iyoku sa ori) e se pupo

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by ladycomfort(f): 3:26pm On Apr 21, 2016
ayokomi1010:
OGUN FUN OBINRIN TI OKO RE KORIRA
ao toju eyele kan ao pa eje re sinu Oyin ao ropo ki Obinrin mafi pa oju ara re ti won bafe Joni ajoseopo pelu oko re
. E jowo baba se adodun nooni eleyi ati wipe se a le lo ise yi fun eniti eniyan ba nfe ki won le ma toju eniyan daada. E se pupo

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by sanjayzaman(m): 2:03am On May 06, 2016
Baba e se pupo olohun atunbo ma ran yin lowo mofe ki e bami wo akose Jaye mi won bi mi ni 24 July 1988
Re: Ogun Awon Bàba Wa by sanjayzaman(m): 2:16am On May 06, 2016
Baba e seun pupo se omisinmisin Pele ni abi gogoro?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by mahmudhathunder(m): 11:21am On May 06, 2016
baba edakun mo need iferan ti eyan le fi fa iyawo eyan to koyan sile pada.eseun
Re: Ogun Awon Bàba Wa by alexdan1881: 11:33am On May 10, 2016
Oogun Eyonu to daju
Eyin adiye sise kan, iyo die.aa da iyo yen sinu plate ,waa te Odu iwori meji si,waa fi eyin adiye naa lee Lori, waa gbe sinu orun di 12pm,waa lo gbe kuro ninu orun by 12pm,waa Bo ara e si ihoho ,waa gbadura,waa Bo eyin naa wa fi kan iyo naa,waa je eyin naa lodidi. Waa da iyo naa sinu omi fun wiwe.


Ejor se 12pm si 12am Ni abi 12pm to 12pm
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:22pm On May 22, 2016
e Ku ile o Gbogbo ile,e Ku atijo la ki ara eni,motide bayi
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:57pm On May 22, 2016
Osole Imule Awon Agba:Odidi eye Owiwi kan,awo lili ti won bo toritori,ewe abamoda oojo,ewe owu akese,esuru pupa,odidi atare kan,ao ro sinu ado sere,ao pa akuko adie funfun kan,ao fi ejere ra ado na,ao le ihuhu adie na mo ado na lara,ojumeji kogbodo ri ado na mo o,ao ma loni 12am,aso funfun la o wo sorun o,ao wa fi ise yan fo eko tutu mu,aso funfun la o si ma wo ni ojo keji o.

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Nostradamus: 7:40pm On May 22, 2016
ayokomi1010:
Osole Imule Awon Agba:Odidi eye Owiwi kan,awo lili ti won bo toritori,ewe abamoda oojo,ewe owu akese,esuru pupa,odidi atare kan,ao ro sinu ado sere,ao pa akuko adie funfun kan,ao fi ejere ra ado na,ao le ihuhu adie na mo ado na lara,ojumeji kogbodo ri ado na mo o,ao ma loni 12am,aso funfun la o wo sorun o,ao wa fi ise yan fo eko tutu mu,aso funfun la o si ma wo ni ojo keji o.
ejoor sir,kini iwulo ise yi ati ba wo ni o se maa n sise?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ademotech: 5:30pm On May 23, 2016
alexdan1881:
Oogun Eyonu to daju
Eyin adiye sise kan, iyo die.aa da iyo yen sinu plate ,waa te Odu iwori meji si,waa fi eyin adiye naa lee Lori, waa gbe sinu orun di 12pm,waa lo gbe kuro ninu orun by 12pm,waa Bo ara e si ihoho ,waa gbadura,waa Bo eyin naa wa fi kan iyo naa,waa je eyin naa lodidi. Waa da iyo naa sinu omi fun wiwe.


Ejor se 12pm si 12am Ni abi 12pm to 12pm
ejor sir se lati 12pm so 12pm ni
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Tayo1one: 6:23pm On May 27, 2016
E Jo, ewe WO ni won npe ni EWE OGUNBO(ewe oko) ati pe nibo Lara ireke ni won npe ni Ade ori ireke. E Jo, inu mi ma dun gon.. ti nba ri idahun. a tun da ti n ba le ri aworan Ade ori ireke.

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply)

Meet The Most Beautiful People On Earth- The Fulanis / Post Pictures Of Traditional Weddings. / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 37
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.