Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,666 members, 7,816,722 topics. Date: Friday, 03 May 2024 at 03:55 PM

Ogun Awon Bàba Wa - Culture (6) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Awon Bàba Wa (326283 Views)

Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai / Asiri Ogun Awon Baba Wa (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply) (Go Down)

Re: Ogun Awon Bàba Wa by cashoggy(f): 12:11pm On Nov 08, 2016
.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by cashoggy(f): 12:12pm On Nov 08, 2016
08101646045atwp:
Edakun fun idahun ojogbon Ti obere nipa ogun yi
(Ovarian Cyst)
Aiparo'o!
E Mio gbo iru aisan Yi rio
Tabi Ki nma Mon itumon re
Edakun kini Yoruba Ti ale fun aisan Yi Ni ede tiwa ntiwa.
Akonisasise'o
Ajuwase o

ovarian Cyst ma nwu bii fere (balloon) si inu ovaries obirin nibi ti eyin ti maa n develop. Omi lo saaba ma nwa ninu e tabi ora. O ma nfa ipalara fun obirin ti o ba fi le burst tori e ni won se maa nso pe ki eni to ba ni lara se ise-abe.
(Modify) (Quote) (Report) (Share)

Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 7:48am On Nov 09, 2016
Moma wa imon Lori eyi, nitori alaye Yi koiti yemi daada sugbon awon ogun kan wa ti afi ma nyo nkan jade Ni ara, bee asiti fi yo orisirisi awon Arun bi mogun, majele, ati orisirisi ofa Ni ago'ara!

OGUN TI AFI NYO INIRA KURO NI AGO'ARA!
AO lo ja ewe olátìdíjò, Ni igba Ti ao ma pe Ni olátìdíjò Ni igba meta Ki atoja, ao Jo pelu padi stare kan, ao mafi omi lo nigba Ti ao mape gbolohun bai:- wipe olátìdíjò3* walo bami Ti nkan baibai ti nfa nkan baibai Ni ago'arami, lobami tiijade, eji'ogbe Ni mofi ise Yi ran'o
Eji'ogbe'oooo
Walo bami gbe nkan baibai jade pelu aniyan, ao fi omi lo.
Bi ase nlo tofi nje niyen'o
Ajuwase'o!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 8:05am On Nov 09, 2016
Baka'na!
Mo nfi asikoyi wifun gbogbo Ile Yi wipe Emi kii ran enikeni wipe Ki olore'sojumi Ni ibikibi'o, bimotile je wipe Omode nimi nitooto, sugbon emi kiigbe ara mi pamon Debi wipe Ki enikan wama soro nipami, bimowa leko maaso wipe ekoni mowa, bimowa Ni Abuja maje ki emon wipe Abuja nimowa,
Awon kan Ni ama npe Tele Lori eyin Ti Ewa Ni oke'okun, sugbon Mori wipe 419 tifewo Ni mose dawore duro!
Fun Idi eyi emi'o mo enikankan emi ati enikankan'o sida'ise papo, number mi'o sitiiyi pada, nitori na Ewa won siwaju'o
Bi ebasi nfe oogun Ti eofi muwon ogun riwon mun, oogun'e wa daada!
Emi kiisi tewe'o
Akonisasise
Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by beware16: 6:57am On Nov 11, 2016
Eku Ise Opplo O, Eledua Ama Fun Yin Se, Amin. Ejowo Sir, Kini Mole Se Fun Omobinrin Yii, Oti Bi Omokan Tele Botile Jepe Ise Abe Ni Won Se Fun, Sugbon Lati Igba Naa Loti Ni Idaduro, Lati Bi Odun Meje Bayi. Otomi Sona Eyin Awo. Isese Agbewa O.Ase
Re: Ogun Awon Bàba Wa by beware16: 10:09am On Nov 11, 2016
ayokomi1010:
oruka bi meta tabi Meje lama lo fun Ogun na

Eku Ise,eledua Atiyin Lehin,ase. Ejowo Kini Ama Fi Adie Ye se Ti Abati Ko Oruka Kuro Ninu E Tan, Se Ale Je Abi Kaju Danu. Ati Pe Ti Aba Fa Ogun Yen Ni Emeta Toba Ku Sinu Omori Isaasun Yen Se Koni Si Nkankan Ati Pe Se Ka Fo Omori Ikoko Yeni Abi Asi Le Pada Lo.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by sayyid(m): 8:59am On Nov 12, 2016
08101646045atwp:
Moma wa imon Lori eyi, nitori alaye Yi koiti yemi daada sugbon awon ogun kan wa ti afi ma nyo nkan jade Ni ara, bee asiti fi yo orisirisi awon Arun bi mogun, majele, ati orisirisi ofa Ni ago'ara!

OGUN TI AFI NYO INIRA KURO NI AGO'ARA!
AO lo ja ewe olátìdíjò, Ni igba Ti ao ma pe Ni olátìdíjò Ni igba meta Ki atoja, ao Jo pelu padi stare kan, ao mafi omi lo nigba Ti ao mape gbolohun bai:- wipe olátìdíjò3* walo bami Ti nkan baibai ti nfa nkan baibai Ni ago'arami, lobami tiijade, eji'ogbe Ni mofi ise Yi ran'o
Eji'ogbe'oooo
Walo bami gbe nkan baibai jade pelu aniyan, ao fi omi lo.
Bi ase nlo tofi nje niyen'o
Ajuwase'o!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o

ese pupo baba ewe ama je oooo.ase
edakun kini oruko miran fun ewe olatidijo?
ajinde ara yio ma je oo

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 9:08pm On Nov 13, 2016
Amin ase!
Ewe olatidijo ni ama npe ni koropo sugbon ti abafee lo fun ifayi olatidijo ni aope ni igba meta!
Akonisasise'o
Ajuwase
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 9:20pm On Nov 18, 2016
ISEYI NI AFI NSAN GBESE ODAJU
Ewe ata epo obo ao lo kuna dada ao gun po mon ose dudu ao ma fi epo pupa para kato lore we oseyi asiri obo latima san owo yi pelu ase oloun

OGUN ISANGBESE¤ Ao waa iyo ati suger ao lo papo ao waa lo pelu Imi ojo ao po mo ose dudu.... Ao tee ose yen ni Ifa Ogunda ao maa se adua bi oba ti wuwa si, ao maa fi ose yen we lararo ati alale.
Ajuwase'o

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by beware16: 7:47am On Nov 24, 2016
ayokomi1010:
Osole Imule Awon Agba:Odidi eye Owiwi kan,awo lili ti won bo toritori,ewe abamoda oojo,ewe owu akese,esuru pupa,odidi atare kan,ao ro sinu ado sere,ao pa akuko adie funfun kan,ao fi ejere ra ado na,ao le ihuhu adie na mo ado na lara,ojumeji kogbodo ri ado na mo o,ao ma loni 12am,aso funfun la o wo sorun o,ao wa fi ise yan fo eko tutu mu,aso funfun la o si ma wo ni ojo keji o.

Eku Ise O Baba Eledua Amaa Fun Yin Se O,ase.
Ejowo Baba Efun Wa Ni Ogun Ifibe Obinrin Todaju Atipe Ti Ara Eniyan Ba Dede Nfala Lojojumo Ti O Nta Eniyen Bi Wipe Won Naa Eniyen, Ejowo Ki Lale Sesi. Ejowo Ebami Wa Solution Si, Isese Se Agbe Wa Oooo.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by beware16: 6:23pm On Nov 24, 2016
ayokomi1010:
beni ajegun Miran wa
Ejowo Sir, Efun Wa Ni Ajegun Miran. Baba Ayokomi
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:24am On Nov 26, 2016
ASEJE TI AFIRI OWO
Awo ilu toya loju agbo,ao ha Gbogbo aje ara tangiri kan,egungun eran ainiwo,ewe sawerepepe,ata ijosin 16,ao loop,ao fise Edo malu ti a ge si 16,je ao se ni epo iyo,ao fi aso kan su osuka kale ,lori re la o so obe yan ka,ao wo aso ti o dara si orun,ao daniyan owo nla ,ao je obe na.

ALEKO
irun oya,ao lo kunna,ao po mo ose ao mafi wo oko wa.

2.ao fi abere oporo kan tele igo,ao ju eso 4inches kan si,ao ko ewe ehinelebe si,ao ro oti si ,lehin ojo keta odi mimu.

(E jo mo lofun awon Eto kan lefirimi bi ojo meta sehin, Gbogbo Iwo ti o mope woli alfa baba alawo,onisegun,to pe oju owo ni e,add watsapp number yi Ki o le jafani ogun nla ati asiri ti o wuwo,08135072961/08075198871
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 2:30pm On Nov 30, 2016
Ka Malage eleyi fun todun Yi osile kan Simi fun fun eyi Ti otun gbona juyi lo.
Ajuwase'o

ASIRI BIBO #50,000..
elowa oga gbigbe kan tope,aoha aje ara tagiri,ewe tagiri mefa,ashishu die,ewe anu,ewe sawerepepe,ewe sinkinmini die,ewe aje,ao lopo,aofi epo din pelu eyin agric mefa.
Aosadua si,ao je. Aodaba #50,000 laarin ose meji.pelu ase olohun. Odaju
Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by HorlarhMheporzy(m): 7:15am On Dec 03, 2016
Ejo wo, se ao fi ori se obe awa yo ori na pada kuro ninu obe na ni tabi bawo esalaye dada nibi eyonu ti eniya ma fi feran yan
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 1:14pm On Dec 03, 2016
E kasan o Gbogbo eyin Ojogbon, mati ikanni yi pa o,tori mifi aye sile fun enikeni lati ma polowo nkan,tabi mafi number sori abalayi,emi Ayokomi 1010,ti o da ogun awon baba wa ati ASIRI awon woli lailai sile,si Ori Nairalad, number mi ni 08075198871/08135072961,fun lati bami soro tabi darapomo wathsapp mi,ikanni ti e bari ti o tunje Ogun Awon Babawa, ti Ki batise ayokomi 1010,tikisi se number yi lefi pe enina,kise emi o,fake ni o,Eniti o bawu Ki oun naje adari kolo Hope ikanni ti e,ko wa oruko fun .ayo ni o,ajo nikan nimo fun enia lati fisi Ori ikanni yi,ati ibere oun teba fe
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 4:24pm On Dec 13, 2016
OGUN OWO KIA KIA TI INAWO BA KU 4 DAYS TO DAJU SAKA

Biscuits die, ashisu die, ose dudu, Schnapps, ao lo Biscuits ati ashisu papo, ao fi schnapps gas kan po mo ose dudu die ti a le lo fun ojo merin, ao maa fi we....

Ofo e: Bi oku ba ku, a gbowo lowo ara, a gbowo lowo ebi, oku a gbowo lowo okunrin, a gbowo lowo obirin, ti ekun, ti eje loku fin gboowo lowo omo e, tori ipakupa ni igbo npa eni to mun igbo ko to na owo owo e tan, itikuti ni oti nti oloti ko to fi owo owo e tore, inawo ti mo fe se ni ojo bayi bayi, bii eni mun igbo, bii eni mun oti ni ki o maa lo ti gbogbo awon enyan to lowo gidi lowo gboongboon ki won maa wa ko owo owo won wa fun mi, ki wo maa wa da owo owo won sile fun mi, ki emi fi bo asiri ara mi oooo. Ase!!!...Tested ok.. o confirm baje... ai mo ye igba la ti lo fun ianwo... e test e wo, ki e fun wa labo...

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 10:27am On Dec 15, 2016
AKIYESI PATAKI! AKIYESI PATAKI!!
Moki gbogbo eyin Omo Iya wa Nile loko lona leyin oodi
Wipe AKI'IMUNRA ODUN'OO!!!
Mo se awon aki'esi Pataki kan Lori gbogbo eyin Omo iyawa Ti eje yioruba Ti Ewa Ni Ilu okeere tabi Ti eyi kuro Nile tipe...
Opo awon call Ti moma ngba ati awon atejise to nwole lofun mi Ni akie si lopolopo Lori won wipe opo ninu won atun maarahun, elomiran tie le wipe ohun Fe pe sugbon Ko si owo card tori wipe owo Kekere Koto bawa soro, elomi ama sise sugbon bukaata tipoju, nipa bai elomi kotie ran to Ile mon nitori opo igba Ti obati ranti awon enyan re bai ironu Ni Ni gbogbo ijo na, oroyi Ni Moro Ti mofi fi awon oogun kan sile seyin iyen fun awon Ti won bale jawe tabi Sa oogun!
Opo lositi lo oogun yala Ti ose fun arare tabi Ti won fi ranse sugbon pabo lotun njaasi
Nitori Idi eyi nimose tun gbe ilana eto nipa wiwo akosejaye sile
Sugbon bai motun Fe fi awon oogun sile fun eyin Ti enpe mi lati okeere tabi fun oniru'iru isoro
Emaabawa kalo
Ajuwase o

-2.
Ni bai ao fi epo obo Tele ape, ao Ko eeru alamon le Lori
AO Ko ewe ewuro oojo ati ewe eyeoba le ao bu omi totowe si ao gbe ka ori Ina Ni ago kan osan gerege, ao we Ni ago kan oru nitori Ti ide baja ona asi Ti ona basi arisiki owo awole
-3.
Bakan na ao lo kafura pelebe merin ati epo obo ao fi omi Idi igbin poo, ao maawe Ni igba kan Ni odun
N.B:- ao fi oseyi si ori kan-nkan meta, ao kunle ao we ikan, ao naro ao we ikan, ao joko ao we iketa, ao ju kan'nkan na nu, ao we be Ni ekan Ni ose akoko ose keji ati iketa, eyi Ti otun Ku odi odun miran, abawon kankan koleefo Mon eniyan
Ajuwase o

-4.
HMMM
eyin pepeiye mewa, eyin adie ibile mewa, a o Jo eyin mejeji sinu awo olomori funfun, ao bu iyo die si, ose lux funfun mewa, ao ha , ao ko sinu re. Ao jeki ore di ojo keji,. A o po po ninu awo yen nibe, ao ma fi we. .
N.B:- ( JOWO MASE FUN ENIA LO NINU OSE YIO ).
-5.
Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Ayomidegbenga1(m): 5:48pm On Dec 17, 2016
E jowo baba e fun mi ni ogun igboya todaju, l always find it difficult to face crowd
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 8:50pm On Dec 18, 2016
Ogun Awon Babawa pe Odun kan ti Olorun eledunmare Osa oke,ti owo emi omo yin,aburo yin,egbon yin,ore yin,baba yin,Ololufe yin,da ikanni yi sile, ni 04/12/2015,ni ojo ti o pe Odun kan gere,nibati soro yi,sugbon misini Nigeria ni date yi lofa,mofe Ki Gbogbo ololufe ikanni yi join mi lati se ajoyo yi,mosifeki a ri testimony awon ti o tiri afanije lati Ori ikanni yi Ogun awon babawa ti emi ayokomi1010,dasile,tori kuse nimu Ori onise wu o,kosi enikeni ti o le so pe mo pe oun ni idakoko ri ,tabi pe mo bere tabi toro owo lowo oun ri,emi fe Ki awon enia di olorire ni,Ki a de tu awon enia kuro ninu igbekun,tibari ijeri si wa Dada,mofe ta Gbogbo omo odudua lore oun nla,Mofe Ki fi ona ola ti Olorun fi ran awon babala wa,han awon enia,ni 2017 o tun gbodo se alaini owo mo.pemi ti o bafe Ki fi owo arami tojure sise fun e 08135072961/08075198871.oludasile ikanni Ogun Awon Babawa. ti e bari oruko mi,number mi Lori ikanni yi e sora o,bi won ba gba yin mini daun si o,Odun ayo lase o,moni idaniloju fun 2017 pe awon olugbinyanju a di olowo tori ati se iwadi odun yan a je ogun gan,sugbon mo bawon lo ninu ogun tabi ajo ti won bafi fi ijimere se ,ninu odun 2017, tori o lewu gan o, Ra ogede Ominni Ki o pemi oni oun ti wa se si Ki odun 2017,le de o,Ki o mani e Lara ni,08135072961/08075198871.4rm ayokomi1010 oludasile Ogun Awon Babawa

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by ademotech: 6:45pm On Jan 03, 2017
baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 11:21am On Jan 04, 2017
Bi otile je wipe:- nti okoju si enikan, eyin lokoju si fun elomiran!
Sugbon gege bi eti la alayi!
Eyi ntumon bai wipe:- tobaje wipe awon Ti oyi yin kayi baje aon Ti edamon eyin tumon si wipe bi iku Ile koba pani tode kii pani
Ti osi nsalaye bai wipe olowo kan laarin otosi otosi Ni gbogbo won, Ni odunyi aseyori wa ninu afoju sun yin yen daada!
Sugbon enilati se imule ati ebe awon agba Ti ma nje Ki omo'osowo Lai jere!
Nitori wipe Oni sowo Ti Ko se ase jere ifa ohere meki wipe eran awon Iya Ni nse!
Nitori na esun Mon awon agba daada.
Ekoni ri ija kule'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 12:11pm On Jan 04, 2017
OSOLE=Ti o ma n mun EYAN Mon AWON nlanla nileyi ati okere.(OMO-YAHOO LELO KOSI LABURU)
Eiye kannakanna tutu kan,ao fi biscuit okin si labiya otun, ao fi Odidi atare kan si labiya OSI,Ao wa ka iye re mejeji Mon Lara ki awon nkan wonyi maba bole.....ao wa ko eyin ororo meta tele ape tuntun, ao wa GBE eiye kannakanna yen le monle.....ao wa ko ewe ekuya tutu pelu sawerepepe tutu die bo monle....odi jijo.......ao lo kuna Dada,ao wa ma fi 1000naira tuntun kan ko ebu yen sinu oti ST-REMMY....Ao wa GBE si igun yara wa,ao fi 1000naira yen si legbe.
Ao wa sope:---------Owo timofi dao loko owo re ooo,kio lo ma bami WO olowo nlanla, olooro,okunrin, obinrin tiowa fun emi l omo l ni owo nlanla wasi odo mi.ADURA....
Ao ma mun diedie laro laro.
N/B******

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Morewealth79: 12:56pm On Jan 08, 2017

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todar
are loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Ejowo ewe wo lonje ewe ekuya
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 9:10pm On Jan 25, 2017
OSO ONITIKUTI
Omo aja eyikeyi ninu ako tabi abo, aofi ewe swerepepe tutu oojo teele inu agbada, aogbe omo aja na lelori, aofi odidi atare nla 7 si legbe, aoda opolopo ewe ola le aja na mole, aowa fi ewe aje onisefun sefun bomole ti aja na koni han sita, aojo ni dede ago mejila osan, aoto epo pupa yika aro na, ti aba njo oogun yi lowo, aoma mu oti ti aofi jotan, ti aba jotan, aolo kunna, aoda sinu ado sere kan, aoran aso osunwon, aogbeko fun ojo meje kiato mafi oti lo lararo, pelu OHUN; onitikuti walole ti olowo wa, olola wa, oba ilu, ijoye, borokini ilu yi wa kiwon wafi owo owo won tamilore, kiwon wafi sanu mi, kiwon wafi bomi lasiri Ki won wa fi tiwon gbe temi lawuge etc...

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 3:03pm On Feb 15, 2017
OSOLE GBEWA PAJAWIRI
Omo yahoo na lelo daada kosi ewu
Ori kanakana 3, alangba 3 atare aja 3, pelu pelu biscuit okin ati opolopo ewe ola ao jo papo ao ma fi omi alujannu lo ebu na.........

N.B:- owo Ni afi ma nlo ebu na'o
Iru owo ewo Ni ao maafi lo?

=****
Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Mallam1910(m): 3:59pm On Mar 01, 2017
ayokomi1010:
OGUN TAFI WE ISE OSI DANU
Ao toju odidi ori etu kan,iye agbe meta,iye aluko meta,ikode meta,iye lekeleke meta,iye akala meta,iye igun meta,iye awodi meta,ao Jo po pelu atare odidi kan,ao po Mo ose,ao kosinu igba olomori,ao te ifa osa meji si lori,ao ma fi we,ao bere si ri se,iba eyin agba o.
kini ori etu
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 9:59pm On Mar 12, 2017
OSOLE OWO TIMU OWO NLA TI ALE FI KOLE LARIN OSU META!
Sugbon nigbati Emi danwo, Mio kole'o
Sugbon hmmm!!!
Nkan Ti mofise komabaje'o!!!
:- EWE BARA MESAN TI OOJO, AOGUN MO ERU ALAMO IYEKIYE, AOPO LOSE, AOFI EJE EIYELE funfun PO OSE NA DADA, AOKO ose na SINU IGBA OLOMORI, AOGBE PAMO FUN 16DAYS. Aoma buwe lararo, pelu ogo Eledumare owo ti ama fi kole nlala yio wa larin osu meta pere. IKILO: enikeni kogbodo ri igba yi ki ojo na tope. Osole yi Koni daun daada na.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ibnmukhardam(m): 8:50am On Mar 13, 2017
Ejoor baba kinni onje ashisu?? Ogun ki ole mawole efun mi baba ejoor
Re: Ogun Awon Bàba Wa by frontpage79: 6:54pm On Mar 13, 2017
eku ise Baba,ewe ama je o,ejowo baba kini molese si okunrin kan ti o Rent ile lowo mi,kope ti o ko wole ni moto mo wipe amugbo ati odaran paraku ni,bii koja loni ki won ma fi olopa wa kiri ati wipe orisirisi awon oju ti koseri loma nwa wasi ile,moni ki o jade loba so di ija,EJOWO BABA KINI MOLE SE TI YIO FI KO JADE FUNRARE,EJOWO E SANU MI.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by honorablepedro: 7:41pm On Mar 13, 2017
ejo sir, ese alaye lekunrere funwa lori osole gbewa pajawiri, notiri motigbo pe ore mi kan timo timo, sugbon koso asiri e funmi.,,ewe amaje lase eledua,..
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ibnmukhardam(m): 10:19am On Mar 16, 2017
Baba ejor, kinni onke ashishu? Ati ise maran se ao singbere yen yika ikun wa ni ati pe se eyan pupo lelo?? Ewe amaje oooo iba agba
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 6:15pm On Mar 22, 2017
ibnmukhardam:
Ejoor baba kinni onje ashisu?? Ogun ki ole mawole efun mi baba ejoor

Ewe Ola Ni won tun npe ashisu!

KI OLE(THIEF)MA LE WOLE!
Ikamudu kan,Ado kekere kan,A o da Ado na lu lori,A o fado na sile ki Ikamudu wo inu Ado na lo fun arare,Eyo Atare kan,A o fi nkan di lenu.A o fowu dudu ati funfun we papo,A o fi Ado na ko senu ona.

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply)

Meet The Most Beautiful People On Earth- The Fulanis / Post Pictures Of Traditional Weddings. / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 129
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.